YO/Prabhupada 0180 - Bi egbogi iso di-mimo ni Hare Krishna Mantra yi



Lecture on SB 1.5.11 -- New Vrindaban, June 10, 1969

Prabhupāda: Vināpi pada-cāturyaṁ bhagavad-yaśaḥ-pradhānāṁ vacaḥ pavitram ity aha tad vāg pavitra iti. O si mo gan. Kilon pe? egbogi iso di- mimo. gbogbo agbaye loti k'aarun ibaje maya, sugbo egbe imoye Krsna yi, pelu mantra Hare Krsna gege bi egbogi iso di- mimo loseje. O daju. Tad-vāg-visargo janatāgha-viplavaḥ. Bhagavad-yaśaḥ-pradhānāṁ vacaḥ pavitram ity aha tad vāg iti, sa cāsau vāg-visargo vacaḥ prayogaḥ. Janānāṁ samuho janatā, tasya aghaṁ viplavati naśayati. A fi ku pa nitumo Viplava. Nitoripe egbogi iso di- mimo loje. fun apeere, ale sofun yin gege bi egbe imoye Krsna yi se je egbogi iso di- mimo, awon tonti gba egbe yi s'okan wan le fi ipaari si gbogbo ese ton ni, awon ofin merin, ton gbodo mase, imo ako ati abo, oti mimu, ere tẹtẹ, ati eran jije. Bawo ni gbogbo eleyi se je egbogi iso di- mimo.. Aeon nkan merin wanyi lon je ki ese wa posi. Gbogbo awon ese to ku ma jade die die. Ole jija, awon nkan to po ma tele awon nkan merin wanyi. taba fi ipaari si awon nkan merin wanyi, o dabi wipe a ti paana si awon ese wanyi. Egbudo mo be. bawo lesele toju r bayi? Pelu ilana egbogi iso di- mimo yi, orin Hare Krsna. Bibeko, pelu ogbon lasan kolese se.

Gege na egbogi iso di- mimo loje. Janatagha-viplavah. Afi ipaari si gbogbo awon ese teni na n'se. Sugbon taba rowie " Motini egbogi iso di- mimo tole ranmilowo, orin Hare Krsna. Nitorina mole ma se awon isekuse merin wanyi, lehin na mole ya si mimo pada." Gege bi awon ile-esin Kristiani, tonma lo jẹwọ Kosi nkan to buro. Pe eyan jẹwọ gege bi egbogi iso di- mimo lose je. sugbon kilode teyin se tun ese na se? Kini 'tumo eleyi? Elosi ile-esin, te jewo. Oda bayi. Nisin awon ese yin ti tan. O da bayi. Sugbon kilode tese fe tun awon ese yi se? Kini idaun si iru iwa bayi? Hm? Kini idaun ti awon okurin Kristiani ma funmi tin ba bere pe: " Eti se, ko buru, eti losi ile-esin lati jewo niwaju Jesu Kristi tabi awon onise re tabi Olorun. Wanti dariji ese te se. O da bayi. Sugbon kilode te tun ese na se?" Kini idaun?

Nara-narayana: Wantun jewo si.

Prabhupāda: Wantu jewo. Itumo iyen niwipe , oti d'eto owo niyen. anfaani to wa ko niyen. Seti ri awon ofin wa ti awon eyan o gbudo se... Nāmno balād yasya hi pāpa-buddhiḥ. Enikeni toba rowipe nitoripe moti ni egbogi iso di- mimo yi Mole se isekuse toba wunmi lehin na ma korin Hare Krsna, gbogbo ese mi a de tan, ese n'la niyen je.