YO/Prabhupada 0186 - Gege bi wura se je wura



Lecture on BG 7.1 -- Fiji, May 24, 1975

Boya awa ni ilu Fiji tabi Ilu geesi, tabi ibikibi, nitoripe Krsna ni oludari gbogbo nkan, n'ibikibi..., Sarva-loka-maheśvaram (BG 5.29). Gege na apa die ninu sarva-loka ni Fiji je. Gege na toba je Oludari gbogbo awon loka, oun na ni oniwun Fiji. Kosi 'yemeji kankan. Gege na awon olugbe FIji, teba gba imoye Krsna yi s'okan, ipo to gaju aye yi niyen. Pipe ile aye yi niyen. Ema yipada lori awon ilana Krsna. bhagavān uvāca, Bhagavān n'soro fun ara re. E mu anfaani yi ni pataki. Ona abayo fun gbogbo awon isoro aye yi wa ninu Bhagavad-gita. Eyikeyi ti isoro na baje, ona- abayo wa fun, teba le gba ona abayo na.

Nisin awon eyan o l'ounje mo. Ona abayo wa ninu Bhagavad-gita. Kṛṣṇa sowipe, annād bhavanti bhūtāni: (BG 3.14) "Bhutani, gbogbo awon eda, eranko at'eyan, wan le jo gbe po, laisi inira, sugbon wan gbudo ni ounje to po fun wan." Nisin atako wo leni si oro yi? Ona abayo to wa niyen. Krsna sowipe, annād bhavanti bhūtāni. Konse nkan tawa o le se, nkan to sese leleyi. Egbudo ni ounje to po lati boo awon eyan at'eranko wanyi, lehin na gbogbo nkan ma lo jeje lesekese. Nitoripe awon eyan ma fa'jogbon t'ebi ba pa wan. Nitorina egbudo fun l'ounje na. Ilan Krsna leleyi. Se nkan to le lati se lelelyi, ko le sese? rara. Egbin ounje to po, ke pin . Ile to po repete wa, sugbon awa o fe gbin ounje. Awan eyan da ero sile ati awon taya oko. Nisin ton ounje ba ton wan je awon taya wanyi. Sugbon Krsna sowipe " Egbin anna." Lehin na koni sejo aini. Annād bhavanti bhūtāni parjanyād anna-sambhavaḥ. Sugbon ele s'eto anna teba ni ojo to po. Parjanyād anna-sambhavaḥ. Ati yajñād bhavati parjanyaḥ (BG 3.14). teba si se awon yajna, lehin na ojo ma ro dada. Bose je niyen. Sugbon koseni to nife fun yajna mo, koseni to nife fun ounje mo, Sugbon teyin ba da aini wanyi fun ara yin, ejo Olorun koniyen, ejo yin niyen je.

Gege na ele bere ounkoun teba fe - eto awujo, iselu, imoye, esin, ounkoin teba fe - ona abayo fun wa nibe. Gege bi Orile-ede India se ni isori nipa eto ipo. awon eyan pupo feran eto ipo yi, sugbon awon to po na, o si fe. Sugbon Krsna ti fun wa ni ona abayo na. Gege na kosejo awon tonfe tabi awon ti o fe. Agbudo da ipo yi lat'ori amuye awon eyan na. Cātur-varṇyaṁ mayā sṛṣṭaṁ guṇa-karma (BG 4.13). Kosowipe, " Lati ibimo." wanti jerisi na ninu Śrīmad-Bhāgavatam, yasya yal lakṣaṇaṁ proktaṁ puṁso varṇābhivyañjakam yad anyatrāpi dṛśyeta tat tenaiva vinirdiśet

yasya yal lakṣaṇaṁ proktaṁ
puṁso varṇābhivyañjakam
yad anyatrāpi dṛśyeta
tat tenaiva vinirdiśet
(SB 7.11.35)

Ilana to daju lati Narada Muni.

Gege na aw tini gbogbo nkan to da ninu awon iwe mimo Veda, taba tele.. Egbe imoye Krsna yi sin gbiyanju lati fun awon l'eko lori awon ilan wanyi. Awa o da nkankan sile. Ise wa ko niyen. Nitoripe amo wipe aláìpé laje. Taba da nkan sile nkan na o le daju. Gbogbo lani alebu merin ninu aye wa: aman se asise, itanra-eni sin damu wa, aman tan awan eyan je ati awon iye ara o daju to. Gege na bawo lasefe ni oye to daju lat'eni toni gbogbo awon alebu wanyi? Nitorina agbudo gba imoye lati eni to gaju , tio ni gbogbo awon alebu wanyi, mukta-purusa. Imoye to daju leleyi.

Gege na ibeere wa niwipe ke gba imoye lati Bhagavad-gita, kesi huwa bose ye. Nkan teje o wulo. Bhagavan wa fun gbogbo wa. Olorun ni Olorun je. gege bi wura se je wura. Ti awon Hindu ba ni wura lowo, koni di wura Hindu. tabi ti awon Kristiani ba di wura sowo, koni di wura Kristiani, wura ni wura je. Gege na ikan soso ni dharma je. Esin kan soso lowa. Awa o le ni esin HIndu, esin Musulman, esin Kristiani. Ko daju. Gege bi " Wura Hindu," " Wura Musulman." Kolese se. Wura ni wura je. Gege bi esin na. Awon ofin OLorun nitumo esin. Esin niyen. Dharmaṁ tu sākṣād bhagavat-praṇītaṁ na vai vidur devatah manuṣyāḥ (SB 6.3.19), geg bayi - Olorun lo da awon ofin dharma sile." Olorun kan soso lowa, nitorian, dharma tab'esin kan soso loyeko wa. Awa o le ni meji.