YO/Prabhupada 0190 - E din gbogbo igbadun ara yi ku



Lecture on SB 7.6.11-13 -- New Vrindaban, June 27, 1976

Taba tele awon ofin bhakti-marga, koni wulo mo pe awan gbiyanju lati jade kuro ninu idimu ile-aye yi. Ijarawon yi ma tele lesekese. Vāsudeve bhagavati bhakti-yogaḥ prayojitaḥ janayati āśu vairāgyam (SB 1.2.7). ijarawan nitumo Vairāgyam. oruko imi fun bhakti-yoga ni Vairāgyam. Vairāgya. Sārvabhauma Bhaṭṭācārya ti ko awon ese-iwe nipa vairagya.

vairāgya-vidyā-nija-bhakti-yoga-
śikṣārtham ekaḥ puruṣaḥ purāṇaḥ
śrī-kṛṣṇa-caitanya-śarīra-dhari
kṛpāmbudhir yas tam ahaṁ prapadye
(CC Madhya 6.254)

Nibi Krsna fun ara re ni Śrī Kṛṣṇa Caitanya Mahāprabhu Oti wa ko wa ni vairagya-vidya. O le die na. O le fun awon eyan lasan lati ni oye nipa vairagya-vidya yi. Ise wan ni bonsele jeki igbadun ara wan posi, sugbon itumo egbe imoye Krsna yi ni lati din gbogbo igbadun ara yi ku. Nitorina lonsen pe ni vairagya-vidya. Asi le bosori ipo Vairagya-vidya yi, gege bi wan se salaye, vāsudeve bhagavati bhakti-yogaḥ prayojitaḥ janayati āśu vairāgyam (SB 1.2.7), laipe yi, laipe yi. Janayati āśu vairāgyaṁ jñānaṁ ca. Nkan meji lani ninu ile aye eda yi. Ikan ni jñānam, jñānaṁ-vijñānam āstikyaṁ brahma-karma sva-bhāva-jam. Itumo jnanam yi niwipe, ibere jnana niwipe " Ara mi konimo je. Emi nimi." Jnana niyen. Lesekese tryan ba wa lori ipo jnanam, o rorun gan. Gbogbo awon eyan sise nitori ara wan. Sugbon teyan ba ni oye na, awa sori ipo jnanam, lehin na aye wipe " Ara mi ko nimi. Kilode timo sen sise tole gan fun ara yi?" Jñānaṁ ca yad ahaitukam (SB 1.2.7). Lesekese na.. Nkan meji loyeka se. Caitanya Mahaprabhuti salaaye nibi to po repete, p[elu ile aye re na osi fu jnanam ati vairagyam fi han wa. Ni aoa kan jnanam, ninu awon eko re si Rupa Gosvami, awon eko re si Sanatana Gosvami, awon nkan to sofun Sārvabhauma Bhaṭṭācārya, Prakāśānanda Sarasvatī, awon ejo pelu Rāmānanda Rāya. Ati salaaye gbogbo awon nkan wanyi ninu iwe eko Oluwa Caitanta. Jnanam leleyi. pelu ile aye re tofi s'apeere funwa, osi gba sannyasa, awon eko re nipa vairagya. Jnana ati vairagya, awon nkan meji yi lafe.

Kon sepe ka kon dede bosori ipo jnanam ati vairagyam, sugbon taba se ikeko, o lese se. Konse nkan tio sese. Nkan tafe niyen:

vāsudeve bhagavati
bhakti-yogaḥ prayojitaḥ
janayaty āśu vairāgyaṁ
jñānaṁ ca yad ahaitukam
(SB 1.2.7)

Nkan tafe niyen. Gege na egbe imoye Krsna wa yi wa lati de sori ipo jnanam ati vairagyam. Taba feran ile-aye yi ju bawo lase le ni'fe na? Prahlada Maharaj ti salaaye. Iyawo wa, awon omo, ile wa, awon eranko ati awon iranse, awon aga, awon aso, ati bayi bayi lo Awon eyan sise gan, lataro d'aale, fun awon nkan wanyi. se kosi ile to da, tabi awon eranko, tabi awon nkan to da tale ri? Fun kini? Lati le gbadun si. taba fe gbadun si, kosi basele jade kuro ninu idimu ile aye yi. Gege na agbudo se ikeko eto ijarawon.