YO/Prabhupada 0202 - Talole ni ife ju oniwaasu lo
Morning Walk -- May 17, 1975, Perth
Amogha: Eye Ogongo le ti ori bo ninu iyepe.
Prabhupada: Bee ni.
Paramahamsa: nitori ilọsiwaju ti awa ni, lo je ki awon eyan farapo egbe Hare Krsna
Prabhupad: Won ti ni ilosiwaju to da. Bhava-mahā-dāvāgni-nirvāpaṇam. Nibena gbogbo isoro aye yi asi nipari. Won ti ni ilosiwaju Ceto-darpaṇa-mārjanaṁ bhava-mahā-dāvāgni-nirvāpaṇam (CC Antya 20.12). ti won ba nkorin Hare Krsna gbogbo ibanuje to wa lokan won a jade, a so okan di mimo, gbobo isoro aye a si pari. gbogbo ijaya aye pari.
Paramahaṁsa: O si jo wipe inu won dun, sugbon... O si dabi wipe awon elesin Krsna(Oluwa) ni idunnu to po, sugbon won kin se ise to le. nigbagbogbo ni won korin, won si ma jo wa de toro owo. Sugbon won se ise to le. Gbogbo ise ti awan se wulo
Prabhupāda: se jijo naa kon se ise? tabi iwe kikọ kon se ise? ti iwe kikọ o ban se ise, kini ise wa je? hm? tabi ka ma fo bi aaya? see bi ni? se iyen wa je ise?
Amogha: Sugbon awa nse iran lọwọ fun awon eyan gege bi won se ma ninu ile iwosan tabi fun awon ọmuti ọkunrin...
Prabhupad: rara, kilode.. bawo ni won se iran lowo? se iwo ro wipe ti eyan ba lo si ile iwosan ko le ku ni? bawo ni wo se iran lowo? E ro pe eyin se iran lowo.
Amogha: Sugbon eyan na a si wa laaye.
Prabhupada: isokuso imi tu niye. igba melo le ma gbe ninu aye yi? Ti asiko Iku ba de, eyan o le wa laaye ju iseju kan. Ti eyan ba ma ku, aye re ti pari ni yen. Se abẹrẹ, tabi oogun le fun eyan ni iseju kan ju ti asiko iku ba de? se oogun wa to le pari iku?
Amogha: bakanna, O da be wipe oogun naa wa.
Prabhupad: Rara...
Amogha: Niigbami, tiwon ba fun eyan ni oogun won le wa laaye ju bon se ye kon wa
Paramahaṁsa: won de ni wipe ti won ba le se ase yori ninu itọju okan asopo lati eyan kan si imi, eleyi ma je ki awon eyan wa laaye...
Prabhupāda: Won le so wipe, awon... nitoripe awa ri wọn be awon oponu. Kini iwulo oro won? Agbudo ri won be awon oponu, otan. (enikan kpariwo leyin; Prabhupad kigbe mo won) (Erin) Oponu imi ni ye. Oun gbadun aye. Aye yi kun fun awon oponu. Awa o gbodo gbe okan le aye tawa yi, agbudo gbokan kuro ninu aye yi. Taaba le gbokan kuro laaye yi, awa o le pada s'ile wa ni Orun. Ti okan enikeki ba ni ifamọra fun aye ta wa yi - " o dara - sugbon eyan na ko fi aye si le. Bee ni. Krsna le gan.
Paramahamsa: Sugbon Jesu so wipe: "ni ife arakunrin gege bi wo se ni ife ara re" bee na taba ni ife arakurin...
Prabhupada: awa ti ni ife yi. Awa fe fun won ni imo ohun ti Krsna (Oluwa). ife gidi le leyi. awa ma fun won ni ayérayé, ati alaafia. afi taba ni ife won, kilode taa fin gba aduru iponju yi mora. Alufaa ton wàásù gbudo ni ife awon eyan. bibẹkọ kilode ton soro? O le se fun ara re ni ile re. Kilode to fe gba aduru iponju yi mora? Mo ti le Ogorin ,Ti o ban se ti ife ki lo ma je kin wa si bi? ta lo tun ni ife to ju ti alufaa? O tun ni ife fun awon eranko. Nitorina lo se waasu. " ema si je eran mo". Se won ni ife awon eranko, awon oponu won yi? nwọn njẹun, won de ni ife fun orile ede ton ti wa, otan. Kosenikeni to ni ife. Igbadun nikan lon fe. Ti eyan ba ni ife, eyan na ni imo ohun Krsna (Oluwa). Otan. Awon Oponu. Igbadun tara won lon wa, sugbon won fi aami si ita pe " mo ni ife gbogbo eyan". Ise ton se ni ye Awon aṣiwere de ni igbagbo ninu won. " Oh, Ara kurin yi je eyan to ni okan to dara" Ko ni ife elo mi. Ara re nikan lo ni ife fun Otan. Won ti di iranṣẹ ti'ye ara. Otan