YO/Prabhupada 0203 - Ema da egbe Hare Krishna yi duro



Lecture and Initiation -- Chicago, July 10, 1975

Prabhupāda: Yajña, ẹbọ ... Yajña-dāna-tapaḥ-kriyā. Ile aye eda eniyan wa fun sise yajña, ka se ìdìmúlẹ̀ ati ìṣèbáramusí Nkon meta. Itumo aye ni yen. Awa o gbodo gbe aye yi be aja tabi Ologbo. àìyégé ni ye je. Iru ìlàjú ba yi àìyégé lo je si aye eda eniyan. ìlàjú aja lo je. Aye eda eniyan wa fun nkon meta: yajña-dāna-tapaḥ-kriyā. Eyan gbudo mo bon se gbe ebô, ati ba se le se ìdìmúlẹ̀ . ati ba se le ko ìṣèbáramusí. Eyi je ile aye eda eniyan. bẹ na yajña-dāna-tapasya, ni aye atijo awon eyan man se nkon meta won yi bi agbara won se to. Gege bi aye atijo Satya-yuga, Valmiki Muni se ṣèbáramusí ati ise ṣaṣaro fun odun ẹgbẹrun lọna ọgọta Ni aye igbayen awon eyan wa laaye fun odun Ọkẹ marun. Sugbon ni isin eleyi ose se mo. Ni aye atijo awon eyan le se ṣaṣaro sugbon ni isin ko le se se mo. Nitorina ni iwe mimo śāstra so wipe yajñaiḥ saṅkīrtana-prāyaiḥ: agbudo se yajña, saṅkīrtana Lati sise saṅkīrtana-yajña, a le ri èsì kana gba. Gege be Vālmīki Muni se ri èsì lati inu ise sasaro to se fun odun ẹgbẹrun lọna ọgọta Eyan le ri esi kon na to ba le se sankirtan-yajna fun igba kekere. Inú rere ôre le je.

Inumi dun pe ni Orile- ede àjòjì, paapana ni Orile- ede America Eyin Okurin ati Obirin ni ibi eti se oriire gan nitoripe eti mu so kan ise saṅkīrtana-yajña Awon eyan si ni imoore. Inu mi si dun gan Gege na yajña yi ti awan se, e fi oju si yajna yi ke si fi oju si ijosin Oluwa. E si tesiwaju pelu ajoo wa yi titi di igba ti gbogbo eyan ninu Orile-ede yin ma ni igbagbo ninu esin wa.

ijọ: Jaya!

Prabhupāda: Won ma gba nitoripe asọtẹlẹ ti Caitanya Mahaprabhu le je.

pṛthivīte āche yata nagarādi-grāma
sarvatra pracāra haibe mora nāma

Aṣèbéèré Caitanya Mahaprabhu ni wipe gbogbo eyan ni gbogbo abule, gbogbo Orile-ede, ati gbogbo ilu ni aye yi, gbudo gba so kan egbe Sankirtan, ton ba ti gba gbogbo wan ma ni Oluwa Caitanya Mahaprabhu loo kan. " Oluwa mi, E ti fun wa ni nkan ti o si ni yi. Eyi ni asọtẹlẹ ti awan so. agbudo gbiyanju lati je ko bosi. Gege na ko de ni ṣoro. E ti se ìṣàgbékalẹ̀ àwòrán Oluwa be na e bere irin ajo yi lati abule kan si ikeji, lati ilu kan si ikeji, lati Orile-ede kan si ikeji. Ni isin e ti ni iriri to ye, bẹ na lo ye ke wa ilosiwaju egbe wa. bi mo ti so tele pe Orile-ede yin, Ilu America s'orire gan. Nkon to ku to ye kon gba ni ise sankirtan... ton ba se aye won a se aṣeyọri Ni ana oni awon nkon to po ti mo so, boya eti ri ninu iwe irohin Mo so wipe ise ta ni lati se, ise mimo lo je. Gege na asiko ta wa yi, awon nkon o lo bon se ye. Ema si je ki ibanuje ile-aye yi ba aye mimo ta ni je. E fi oju si bukata aye ta wa subon ema gbagbe iwaasu mimo yi ati ise t'Oluwa bibeko, ipadanu lo ma je. Bibeko eniyan kon ma se ise ohunkohun , eyi je śrama eva hi kevalam (SB 1.2.8) Gege bi Irin-ajo te gbe lo si oṣupa, ínádànù Owo ati àsìkò le je E ti na owo ni inakuna, ki le de re mu ninu e? Iyepe lasan, Otan. E ma si se bi Aṣiwère. E ro inu wo. To ba ye pe E na aduro Owo te lo yen, lati fin pin Esin ati iwaasu Oluwa (Krsna) ni gbogbo ibikibi ni Orile- ede yin, anfaani na ati abajade to ma fun yin ma po ju bayi lo. lọnakọna, awa o le so ju bayi lo nitoripe owo yin len na. ejo yin ni ye Sugbon awa fe be awon alaṣẹ ati awon Okurin to logbon pe kon fara we egbe Sankirtan wa. nipataki Orile -ede America, ka to lo si Orile-ede Europe, Asia. Orile-ode yin je ikan ninu awon Ilu ni aye yi to lowo gan Gbogbo yin l'ọgbọn. Ko de si nkon te fe ti e ooni. E gba si inu okan yin egbe Hare Krsna wa pelu Isuru ati ogbon. O rọrun. E de ni iriri to ye ke ni E ma si da duro. E te si Iwaju Orile-ede yin a dara, gbogbo aye na asi dara.

Ese gan.

Ijo: jaya!