YO/Prabhupada 0204 - Moni oreofe ti Guru. Vani leleyi



Morning Walk -- July 21, 1975, San Francisco

Prabhupāda: Egbudo ni asepo pelu mejeeji Guru-kṛṣṇa-kṛpāya pāya bhakti-latā-bīja (CC Madhya 19.151). E gbudo mu kṛpā guru ati ti Krsna papo. gege na ema ri abajade ninu re.

Jayādvaita: Awa si ni itara lati gba guru-kṛpā (oreofe t'oluko).

Prabhupāda: Tani?

Jayadwaita: Gbogbo wa.

Prabhupāda: Beeni. Yasya prasādād bhagavat-prasādaḥ Te ba ti ri oreofe guru (oluko), lesekese le ma ni ti Oluwa na.

Nārāyaṇa: Śrīla Prabhupāda se aleri Oreofe guru ti awa ban se nkokan to ba telorun?

Prabhupāda: bibẹkọ bawo lo le ri gba?

Nārāyaṇa: E dakun, ko yee mi.

Nārāyaṇa: bawo wa ni awon eyan ti o le ri eyin tabi ba eyin soro, bawo ni won se le ri ore-ofe yi gba..

Prabhupāda: Ibi ti vāṇī ati vapuḥ ti wa ni ye. Ti eba le ri mi, e mu sokan awon knon ti mo ba so fun gbogbo yin.

Nārāyaṇa: Sugbon, Srila Prabhupad bawo ni wa se mo pe nkon ton se a mu inu eyin dun?

Prabhupāda: Ti eba se gege bi Guru (Oluko) se wi, iyen ni kan to ati mo wipe inu guru ma dun. sugbon ti te ba se nkon ti mo ba wi, bawo ni inu mi a dun?

Sudāmā: Eti so fu tele pe Ore-ofe yin si wa fun gbogbo eyan to ba fe. Sugbon awa gbudo gbiyanju lati gba

Prabhupāda: Beeni

Jayādvaita: taba de ni igbagbo ni awon nkon ti oluko ba wi, lesekese na ni ama se nkan to le mu inu re dun.

Prabhupāda: Beeni Oluko mi ku ni odun 1936, mo da egbe wa yi ni odun 1965. Nigbana? Mo ni Ore-ofe t'Oluko mi vāṇī ni eyi je. Bee na ti Guru (Oluko) o si mo ninu aye yi te ba se gege bo se wi, eyin na ma ri iranlowọ.

Sudāmā: Beena ko si ibeere pe awa o ni asepo mo pelu Guru (Oluko) taba le se nkan to ba wi.

Prabhupāda: Rara Cakhu-dān dilo jei.. Kini eyi tókàn Sudāmā: Cakhu-dān dilo jei, janme janme prabhu sei.

Prabhupāda: Janme janme prabhu sei. Beena nibo ni iyasọtọ? Eni to je ki oju yin la, oun gan ni baba yin titi lai lai.

Paramahaṁsa: Se ni igbami aisilaye Oluko yin man dun yin?

Prabhupāda: Kon se ibeere to ye ke beere.