YO/Prabhupada 0209 - Basele pada lo sile, si Odo metalokan
Lecture on SB 6.1.16 -- Denver, June 29, 1975
Ile aye eniyan wa fun yi ya si mimo Gbogbo eyan sin se ise lati le rin nkan je Ko se ni to le ri nkan je laišišẹ. Ko ṣee ṣe. won gbudo se ise gan. Ilu Denver si dara gan, sugbon kon se lesekese lo di bayi Awon eyan si ise lati je ko si dara bayi Iyen fi hon wa pe ti awa ba si feran idunnnu oye ka si ise. ko soro Sugbon Krsna (Oluwa) so wi pe yānti deva-vratā devān (BG 9.25). Awon eyan wa ton si ise gan lati di Olowo ninu aya ta wa yo tabi elomi wa ti ko ni ayo ninu aye, nitoripe O logbon, won de fe ni ifonkanbale inu aye atun wa Ni aye atunwa won si le lo si isọgbe-oorun gege na yānti deva-vratā devān pitṛn yānti pitṛ-vratāḥ (BG 9.25) gege bi teba se ise yin, gege na le ma ri abajade Sugbon ni ila kehin ninun iwe mimo na Krsna (Oluwa) so wi pe, mad-yājino'pi yānti mām: " ti won ba si se ise fun mi, tabi ke si yin mi logo, lẹhinna ema wa si ile mi ni Orun. Ki wa ni iyato eyan to wa ninu aye yi ati eyan to wa ni Orun? Iyato to wan be ni ābrahma-bhuvanāl lokāḥ punar āvartino 'rjuna (BG 8.16). Gege na ti eyan ba lo si isogbe-orun to ga ju ninu aye ta wa Brahmaloka, sibẹsibẹ ibimo, iku, aarun ati atijo ojo-ori si wa ni be, tabi na eyan gbudo pa da si nu aye yi gege bi awon eyan ton lo si osupa pada wa, won lo won si pa da wa. Iru alo ati abo bayi o da. Yad gatvā na nivartante (BG 15.6). Agbudo gbiyanju at lo si Orun to je pe awa o ni pa da sinu aye yi. Orun ti awan salaye yi asin pe ni Krsnaloka.
Krsna(Oluwa) so wi pe, kaka te ma se ise to ba ma fun yin ni isoro, e se ise fun mi Te ba si yin mi logo, ke si se ise na fun mi, o daju pe ema pa da si mi. Mad-yājino 'pi yānti mām. Ki wa ni anfaani gbogbo eleyi? Mām upetya kaunteya duḥkhālayam aśāśvatam nāpnuvanti: (BG 8.15) Enikeni to ba wi si ile mi ni Orun, ko ni pada sinu aye yi Gege na egbe wa sin ko awon eyan bi won se le pa da si Ile wa l'Orun Eyi ma je ki inu wan dun gan Se eyin ro pe inu awon eyan to wa ninu egbe wa o dun? Eyin na le ri fun ara yin pe inu wa dun. asi jo ko ni ibi pelu ounje to dara ati Orin kiko. Ko si ibanuje laarin wa. Sugbon ilana awon esin mi si po gan, orisirisi ilana ton fa ibanuje fun won Sugbon laarin wa ko soro ibanuje iwe mimo Bhagavad-gītā so wi pe: susukham kartum avyayam (BG 9.2). Susukham. Ti eyan ba se ise Oluwa pelu ifarafun, idunnu re a si po. Itumo mi fun susukam ni idunnu ati itẹlọrun itumo kartum ni wi pe agbudo se ise Oluwa pelu idunnu. Itumo Avyayam ni wi pe ohunkohun te ba se dúkìá yin titilai lo je gba wipe alakowe pataki le je Ede ti pari ile-iwe giga Vyayam ni iru nkan bayi je nitoripe ni ijokan o ma tan Lesekese te ba ti ku, gbogbo iwe kiko te gba ni ile-iwe giga no ma ton pelu yin gege na te ba tun pada ni aye atunwa esi tun le pada lo gba awon ipò wonyi, boya M.A tabi Ph.D Sugbon ipò t'alakoko ti tan.
Iyen fi hon wa pe ohunkohun ta gba ni ninu aye yi ijo kan o ma pari Itumo Vyayam ni inawo. ti eyan ba lowo, to ba de ti na, lehin igba mi o ma ton (Vyayam) sugbon itumo Avyayam ni wi pe ko si be se le na to, ko le tan. Gege na ise ifarafun ti Oluwa je susukhaṁ kartum avyayam. boba je pe aṣeyọri kekeri ni eyan ri gba, iru aṣeyọri bayi o le tan. Iwe mimo Bhagavad-gītā so wi pe, śucīnāṁ śrīmatāṁ gehe yoga-bhraṣṭo sanjāyate (BG 6.41). Awon eyan ti won o le pari bhakti-yoga ninu aye yi, won ma tẹsiwaju ni aye atun wa Won ma lo si orun lati gbadun lehina na wan si pada si aye ta wa yi Śucīnāṁ śrīmatāṁ gehe: won ma bi won si awon obi to ni ife Oluwa gege bi awon brāhmaṇa-Vaiṣṇava,, tabi kon ni awon ẹbi to lowo. Awon ti won ni Obi to lowo.. Eyin te je American oye ke lowo Nitoripe ni aye igbehin te wa, eti se ise Oluwa gan gege na pelu Ore-ofe Oluwa ni aye isin eti ni ibimo si Orile-ede to dara KO si oro pe eyan kan je talaka Egbudo gba so kan egbe Krsna (Oluwa) wa Eyi si ni aanfani to da. ko si eyan konkon ninu yin to je talaka ko soro pe eyin ronu, "nibo mo ti fe ri ounje," gege bi awon Orile-ede to je pe talaka ni won Eti s'orire gan, ema si se ni isekuse Egba Oluwa sinu aye yin, ke si di oniwaasu Oluwa egbe wa ti si awon ile-adura to po E si gbiyanju ati ko sayensi ti Oluwa gege na aye yin a dara ìbéèrè wa ni eyi.
Ese pupo