YO/Prabhupada 0210 - Lori Oreofe Olorun ni Ilana Bhakti-marga wa



Lecture on SB 1.15.30 -- Los Angeles, December 8, 1973

To ba fe ki iwe mimo Bhagavad-gītā yee E, E gbudo gbiyanju lati ko gege bi won se ko yin Nkon ton pe ni eto parampara ni eyi. Gba wipe mo gbo nko lati Oluko mi, emi na asi ko yin gege bi Oluko mi se ko mi Ninu eto parampara eyan o le fojú inú wò nkan ti Oluko to ko mi so. ko le ye yin afi teba ti gbo lat'enu mi Eto paramapar ni yen ti eyan ba ni àìbìkítà fun Oluko re ko le ko nkan to wa ninu awon iwe mimo Gege bi egbe Caitanya Mahaprabhu, nkan ti Caitanya Mahaprabhu ba so ko le ye wa. Lati ni amo nkan to so, agbudo ni oye re lati awon Gosvamis Nitorina niipari gbogbo akori ninu iwe Caitanya-caritāmṛta, olukọwe na man so wi pe... rūpa-ragunātha-pade... kini yen?

śrī-rūpa-ragunātha-pade yāra āśa
caitanya-caritāmṛta kahe kṛṣṇa-dāsa

Ko so wipe " Nkan ti Caitanya Mahaprabhu ko ti ye mi" Rara. Asiwere ni yen. Nkan ti Caitanya Mahaprabhu so ko le ye E. Nitorina nigba gbogbo a so wi pe rūpa-ragunātha-pade sada yāra āśa caitanya-caritāmṛta kahe kṛṣṇa-dāsa. dipo a so wi pe " Emi Kṛṣṇa dāsa, Kavirāja mo teriba fun awon Gosvami. Ilana parampara le leyi Gege na Narottama dāsa Ṭhākura so wi pe, ei chay gosāi jār tār mui dās, "iranṣẹ nimo je fun enikeni to ba gba awon Gosvami mefa bi Oga re. Mi o le di iranṣẹ enikeni ti o ni igbagbo ninu iwaasu awon Gosvami. Nitorina awa man gbadura si Oluko ti wa rūpānuga-varāya te, rūpānuga-varāya te, A ni igbagbo ninu Oluko nitoripe oun na ni igbagbo ninu Rūpa Gosvāmī Awa o gbudo ro pe a ti ju Rūpa Gosvāmī lo.. rara Tāṅdera caraṇa-sebi-bhakta-sane vās. Ilana parampara le leyi.

Nkan na ni awan tun so. Lati enu Krsna (Oluwa) ni arjun ti gbo. Nigbami awon man so wipe asiwere ni iyen je. won man beere pe Arjuna gbo lati enu Krsna.. sugbon awon o ri Krsna ni aye isin. Nitori iyen won so wi pe kilode ton ma gba? kon se oro wiwalaarin, nitoripe eyin o si ni ero otitọ ayeraye Oro Krsna (Oluwa) ninu Bhagavad-gītā ko yato si Krsna. Nigbati eyan ban gbo Bhagavad-gītā ate enu Krsna loti ngbo. Nitoripe ko si iyato Oruko Krsna, irisi Krsna, ami idayatọ Krsna, iwaasu Krsna, ohunkohun ti krsna ba ni to yato si Krsna Krsna (Oluwa) ni gbogbo wan je. Ogbudo ye wa bayi. Ko si iyato si wan ati Krsna NItorina Irisi Krsna ko yato si Krsna. ere aworan ko lo je.ere aworan okuta didan ko lo je. Krsna lo je O ti yo si iwaju yin sugbon eyin o ni oju lati fi ri Krsna. Nitoripe eyin ri okuta and igi, gege na o ti yo sinu awon ere Ewo ro bo ya pe okuta ati Igi lo je. Sugbon Krsna lo je. Beena awon iwaasu Krsna oyato si Krsna na. Ti nkan ti Krsna ba so wa ninu Gita ko si iyato si krsna.

Gege bi brahmana lati ilu kan ni guusu ni Orile-ede India aláìmöwé lo je nitorina ko si le ka Bhagavad-gītā Sugbon Oluke re si wi fun pe ko ka eri meji-din-logun ninu Bhagavad gita ni ojojumo Okan re si daamu. " aláìmöwé ni mo je, bawo n mo se le ka bhagava daj. Inu ile-adura Ranganatha lo wa O si mu Bhagavad gita sugbon ko si le ka dada Awon ore re to mo fi se yeye " Brahmana wa igba wo lo beri si ma kaBhagavad gita" ? Ko daun nitoripe oun na mo pe awon are re fin se yeye. aláìmöwé ni mi Mi o mo iew ka Nigbati Caitanya Mahaprabhu de, oun na beere lowo Brahmana "se emo iwe ka?" aláìmöwé ni mi, mi o mo iwe ka, Sugbon Oluko temisofun mi pe kin ka . kini mo le se? Eyan to ni igbagbo gan ninu oro Oluko re leeleyi je. Ko si bo se fe se, sugbon Oluko re ti soffun pe O gbu do ka Bhagavad Gita ni Ojo jumo Kini itumu yi? Nkan ti awan pe ni vyavasāyātmikā buddhiḥ. agbara mi le ma ka, sugbon kon se aanfani to le Sugbon ti mo ba gbiyanju ati se bi Ouko mi se wi agbara ati se ma wa.

Aṣiri oro ni yen Yasya deve parā bhaktir yathā deve tathā gurau (ŚU 6.23). Ti eyan ba ni igbagbo to gbora ninu Olowa ati Oluko yathā deve tathā gurau, nigbana ni gbogbo asiri awon iwe mimo ma yo si yin kon se oro iwe kiko, tabi ogbon. Eyan gbodo ni ìgbàgbọ ninu Oulwa ati Oluko re Nitorina iwe mimo Caitanya-caritāmṛta so wi pe guru-kṛṣṇa-kṛpāya pāya bhakti-latā-bīja (CC Madhya 19.151). kon se oro iwe kiko, oro igbagbo ni Caitanya Mahāprabhu so wipe guru-kṛṣṇa-kṛpāya, agbudo ni Ore-ofe Oluko at Ore-ofe Oluwa Oro Ore-ofe lo je, kon se iew kiko, tabi owo. Esin bhakti-mārga gbarale Ore-ofe Oluwa Agbudo sa tele ore-ofe yi Athāpi te deva padāmbuja-dvaya-prasāda-leśānugṛhīta eva hi, jānāti tattvam... (SB 10.14.29). Prasāda-leśa, ìdá ni itumo leśa. Eyan to ti gba ìdá ore-ofe Oluwa , oun nikan loleye. na cānya eko 'pi ciraṁ vicinvan. awon iyoku won le ma jiyan sugbon ko le ye won won gbudo ka iwe mimo Bhagavad-gītā nitorina awa fe fun yin ni Bhagavad-gītā gege bi Arjun se ko lati Krsna (Oluwa) Ko soro pe awan fo kakiri lati Oluko si imi. Rara. Awa o le se be iṣowo ko ni yen. Eto parampara ni.