YO/Prabhupada 0212 - Niotooro, aye atunwa nbe



Garden Conversation -- June 10, 1976, Los Angeles

Prabhupāda: eko igbalode, eto ibimo, iku, aarun tabi eyan daarugbo, awon eto wonyi o le ye wan Ko le ye won. Kilode te ro pe won ma gba? Gba be, fun won ko si ona mi. Sugbon ti ona ba wa lati fi ipari si awon isoro aye wonyi, kilode ti won sele gba? Hm? kini iye eko ojo eni? won o le se iyato si nkan to da tabi nkan ti o da. Ko seni to feran iku. sugbon iku wa. Koseni to fe d'arugbo, sugbon gbo gbo wa la ma d'arugbo. Kilode ti won se afaani lati fi iyasoto si awan isoro nla wonyi, sugbon won de ni igberega bi pe alakowe ni won Iru eko-kiko wo ni eyi je? Ti won ba le se iyato fun awon nkan ti o da tabi to da, ki wa ni esi eko-kiko bayi? Itumo Eko-kiko ni wi pe agbudo ni ogbon lati fi se iyasato si nkan to da ati aṣiṣe Sugbon wan o le se. ton ba de mo pe Iku o da kilode to je pe won o le fi ipaaari si Iku Ibo ni Ilosiwaju wa? Wan de ni igberaga ilosiwaju sayensi ton se. Ibo ni ilosiwaju ninu gbogbo eleyi? Eyin o le fi Ipaari si Iku. Eyin o se le fi Ipaari si di d'aagba E le ṣelọpọ awon oogun, sugbon se le fi ipaari si iku? E gba awon oogun wonyi, ko ni si aaarun mo laye. Kini sayensi na to le fi ipaari si Iku? Hm?

Nalinīkaṇṭha: Won ni pe awon se ise lori re.

Prabhupāda: Asiwere imi niye.

Gopavṛndapāla:Gege bi awa se ni wi pe iwonba die die ni egbe Krsna (Oluwa), awon oni sayensi na man so nkan kanna

Prabhupāda: Iwonba kekere, sugbon se won ro pe won le fi ipaari s'Iku O jo wa loju pe awa ma pa da si Orun si Krsna (Oluwa) gege na ibo ni igboya won wa pe won le fi ipaari so iku, aarun, ..

Dr. Wolfe: Tituntun ton gbe jade ni wi pe awon gbiyanju lati fi ipaari si iku,Won ti gba wipe aye atunwa nbe.

Prabhupāda: O wa.

Dr. Wolfe: E fi sayensi fi s'alaye

Prabhupāda: E je ki won se, kon s'alaye pelu sayensi pe aye tunwa n'be Asi le so wi pe, emi omo mi ti ku, O ti lo. Mo ni ara to yato Sugbon lehin iku, aye wa. ilowo ni eyi je gege na Krsna so wi pe, tathā dehāntara-prāptiḥ (BG 2.13). gege bo se so wi pe, na hanyate hanyamāne śarīre (BG 2.20) gbólóhùn ìfúnláṣẹ t'Oluwa ni eyi je. sugbon o daju pe awa o si ku, atun ma pada ni aye atun wa ko s'atako ninu oro yi. Gege na Otoo oro ni aye atunwa. nkan ti awan pe ni iku, ipaari aye ninu are ta wa yi lo je gege na ti awa ba si so wi pe ko s'iku mo, agbudo wa bi asele je ko bo si Ogbon ni iyen je Iwe mimo Bhagavad-gītā so wi pe, ti eyan ba n'igbagbo ninu nkan ti Krsna ba so beena la ma ni yán lati pa d a si Ile-Oluwa, Ko soro iku mo.