YO/Prabhupada 0223 - Agbudo ni ile-eko lati le fun gbogbo agbaye l'eko



Room Conversation with Ratan Singh Rajda M.P. "Nationalism and Cheating" -- April 15, 1977, Bombay

Prabhupāda: ki l'atako?

Mr. Rajda: ko le si oro atako.

Prabhupāda: gbogbo eyan lo gba Iwe mimo Bhagavad-gītā. Bi mo se gbo na pe nigbati awon Olopa wa mu Morarji O so fun wan pe " e duro e je kin ka iwe mimo Bhagavad-gītā mi tan" Mo ri bayi ninu iwe irohin.

Mr. Rajda: Beeni, O so be.

Prabhupāda: Elesin iwe mimo Bhagavad-gītā lo je, ati awon eyan to po na Gege na kilode to ye ka fun gbogbo aye ni iwaasu yi?

Mr. Rajda: Lojojumo, o ma ji ni ago meta-abo laaro asi gba aadura, asi ka iwe mimo Bhagavad-gītā gbogbo eleyi ma gba wakati meta, lehin l'aago mesan asi lo si we. A de pade...

Prabhupāda: Awon Omo Orile-ede geesi yi na, wan man ji ni ago meta abo, wan si se eto iwe mimo Bhagavad-gītā titi di ago mesan aabo Wan o ni ise imi Se ti ri be na. L'ojojumo ni wan se bayi, gbogobo wan Lati ago meta abo titi di ago mesan aabo, ise iwe mimo Bhagavad-gītā lon se.

Mr. Rajda: Iyanu ni eyi je.

Prabhupāda: Awa de ni awon iwe to po ta ba fe soro lori ila kan tathā dehāntara-prāptiḥ (BG 2.13), ninu iwe mimo na, o le gba ju ijo kan lo.

Mr. Rajda: Emi na ri be

Prabhupāda: niisin ti eyi ba je ooto, tathā dehāntara-prāptiḥ and na hanyate hanyamāne śarīre (BG 2.20), kilode tan fin se gbogbo eleyi? Iwe mimo Bhagavad-gītā. Na jāyate na mriyate vā kadācin na hanyate hanyamāne śarīre (BG 2.20). Nigbana ti iku ba pa ara mi, ma si lo.... awon elesin wa wan si lo lati ile si ile, wan ta awon iwe wa gege na awan se eto egbe wa o si ijoba kan kan to ranmi lowo, tabi eyan Esi si wa ni ile-ifowopamọ America, aduro ajeji paṣipaarọ ti mon mu wa pelu ilera mi ti o da mon sin se ise fun wakati merin ni ale. wan sin ranmi lowo Se ri pe awan lan se ise wa fun ara wa. Se ko ye ke wa si odoo wa? To ba je pe akeko to se pataki iwe mimo Bhagavad-gītā ni eyin je, se ko ye ke wa, ka sowopo? And harāv abhaktasya kuto mahad-guṇā manorathenāsati dhāvato... (SB 5.18.12). ko si be sele ya awujo awon eyan si Olóòótọ pelu ọna-iṣofin nikan. Ko le se se rara E gbagbe e. Ko se se Harāv abhaktasya kuto.... Yasyāsti bhaktir bhagavaty akiñcanā sarvaiḥ... Ti eyin, tabi eyan ba di iranse Oluwa nigbayen ni gbogbo amuye to dara ma wa harāv abhaktasya kuto mahad sugbon ti eyan na o ban se iranse Oluwa Isekuse la ma sele, pelu gbogbo Ijoba giga ton ni Ni iwe-irohin teeni, mo si ka pe "arakurin yi, ati iyen, wan si ti le wan lo" Kilode? Harāv abhaktasya kuto Kini iwulo pe eyan di olori ti eyan na o ban se elesin Oluwa (ede Hindi) Eyan to l'ogbon ni eyin je, nitorina mo sin gbiyanju ati fun yin ni èrò to daa te ba de ti awan èrò ti mo ti fun yin si waju.. asiri ko lo je. Gbogbo wa ni lati gbiyanju. Agbudo da ile-akeko to ma s'eto ba sele fun agbaye ni eko to da E ma ronu eye awon eyan to wa. ko ba je kekere. Eyen o se pataki. Sugbon egudo so koko oro.