YO/Prabhupada 0241 - Gege bi awon ejo ni iye-ara se ri
Lecture on BG 2.3 -- London, August 4, 1973
Ninu iwe Veda itumo imi fun Orun ni Tri-daśa-pūr itumo Tri-daśa-pūr ni wi pe awon Orisa metalelogbon lona àádọ́ta ọkẹ́; ẹgbẹ̀ẹgbẹ̀rún lo wa gbogbo wan lo si ni isọgbe-oorun ototo Nkan tan pe ni tri-daśa-pūr ni yen Meta ni Itumo Tri, mewa ni dasa, eyin je ogbon tabi metalelogbon tri-daśa-pūr ākāśa-puṣpāyate. itumo Ākāśa-puṣpa ni nkan ilero.. fun apeere ododo ni ofurufu Inu ogba ni ododo wa sugbon ti eyan ba ronu pe o wa ni ofurufu.. ilero ni yen gege na fun awon elesin igbala si Oru da bi ododo ni ofurufu Tri-daśa-pūr ākāśa-puṣpāyate. Kaivalyaṁ narakāyate. Jñānī ati karmī. Ati durdāntendriya-kāla-sarpa-paṭalī protkhāta-daṁstrāyate. Ati Yogi. itumo Yogi ni yoga indriya-samyama, idari lori iye-ara Ise yogi ni yen. Iye-ara wa si le gan gege bi awon Vaisanava, ni alakoko agbudo ni idari lori ahon wa Awon yogi na gbiyanju lati ni idari lori awon iye-ara, ahon ni kan ko, o si ni iye ara mewa kilode ti wan fe ni idari lori iye-ara wan? Nitoripe iye-ara da bi awon ejo. Ibikibi ti ejo ba sumo, iku ma wa ni be lati ipalara na iku ma jade fun apeere : asepo laarin Okurin ati Obirin lesekese tan ba bere asepo wan, isoro to po ma wa Laye isin, gbogbo nkan ti rorun Laye igbayen, ko rorun bayi, nipataki ni Orile-ede India Nitorina wan fo ju so awon omo Obirin gan, nitoripe ton ba je ki awon obirin ni asepo pelu awon okurin ton se asepo, Omo obirin na ma loyun Ko seni to ma fe mo. Asa veda ni yen. O si le gan. anfanni re ni lati pa da si ile-Olorun Jije, mimu, ati idaraya. Ipinile ile-aye eda ko ni yen lati pa da si Orun ni Ofin gbogbo nkan. Viṣṇur aradhyate:
- varṇāśramācāravatā
- puruṣeṇa paraḥ pumān
- viṣṇur āradhyate panthā
- nānyat tat-toṣa-kāraṇam
- (CC Madhya 8.58)
Varṇāśrama, awon brāhmaṇa, kṣatriya, vaiśya, gbogbo wan lon ma tele ofin wonyi Brahmana gbudo huwa bi brahmana.. gege na ksatria Krsna na so wi pe " Ksatriya lo je, kilode ton sen so isokuso? Naitat tvayy upapadyate (BG 2.3). fun idi meeji ma se bayi gege bi ksatriya, gege bi Ore mi to je ma se bayi ilera teni ni yen. ksatriya gbudo jagun. brahman o le jagun satyaḥ śamo damaḥ, ni brahmana, ise re ni bi ase di olooto, ko si ya si mimo bi ase ni idari lori iye-ara re, ati lori okan re ba se gbe aye to rorun, ba se ni oye iwe Veda ba se fisinu aye re,ba se ni igbagbo to le Ise brahmana ni gbogbo eyi je. gege na ksatriya- jija ogun ni ise re Vaiśya-kṛṣi-go-rakṣya-vāṇījyam (BG 18.44). agbudo tele gbogbo ilana wonyi.