YO/Prabhupada 0242 - O le gan lati pada si awujo t'alakoko



Lecture on BG 2.3 -- London, August 4, 1973

Prabhupāda: laana aka ninu iwe pe nigbati Vaivasvatu Manu lo ki Kardama Muni Ejoo Sa kini itumo irin-ajo ti eyin se yi?

Eelesin: ayẹwo.

Prabhupāda: ayẹwo.. beeni. ayẹwo. Irin-ajo yin wa fun ayẹwo varnasrama.. Afe mo boya awon brahmana se ise wan, tabi awon ksatriya na se ise wan Irin-ajo Oba ni eyi je. Oba o gbudo se ise irin-ajo fun idaraya, ko gbudo na owo ijoboa ni inakuna Niigbami Oba le ni idibọn lati jade, gege na O le mo boya awon eyan tele ofin varnasrama-dharma baayi o le mo boya awon eyan tele ofin na, tabi wan kon se isekuse bi awon asiwere Iyen o le se se. Ni isin ni ijoba yin, wan se iṣabẹwo lati mo awon ti o ni ise sugbon opolopo awon nkan wa ti wan ni lati se iṣabẹwo fun Ie ijpba ni wi pe wan gbudo ri gbogbo nkan Varnāśramācaravatā, agbudo se gbogbo nkan gege bi brahmana Kon se wi pe ka di brahmana ní ayédèrú..agbudo di brahmana to daju Ise ijoba ni yen je ni isin gbogbo nkan ti daru. awon nkan o ni yi mo Nitorina Caitanya Mahāprabhu so wi pe.. kalau.

harer nāma harer nāma
harer nāmaiva kevalam
kalau nāsty eva nāsty eva nāsty eva
gatir anyathā
(CC Adi 17.21)

O ma soro gan lati le yi pada si ilaju t'alakoko Gege na fun eyan to je Vaisnava, tri-daśa-pūr ākāśa-puṣpāyate durdāntendriya-kāla-sarpa-paṭalī Idari lori iye-ara, durdanta ni yen. itumo durdhanta ni nkan t'agbara pupo O si soro gan lati ni idari lori iye-ara Nitorina ani awon ilana yoga bi eyan sele ni idari lori iye-ara Sugbon fun eyan to je elesin... Gege bi ahon wa, agbudo fi korin Hare Krsna ka si je ounje to ti ni ibukun Krsna Gege bayi lo ye ka se FUn eyan to je bhakta ko si isoro pelu iye-ara re Nitoripe eyan to je bhakta mo bi wan e fi iye-ara se ise fun Oluwa Hṛṣīkeṇa hṛṣīkeśa-sevanam (CC Madhya 19.170). Bhakti lele yi. Itumo Hṛṣīka ni iye-ara Ti eyan ba fi iye-ara fi sin Oluwa, Hṛṣīkeśa ko si ni iwulo fun yoga lesekese ni wan ma wole sinu ise Oluwa. wan o ni ise mi. Ise to gaju ni eleyi je Nitorina Krsna so wi pe.

yoginām api sarveṣāṁ
mad-gatenāntarātmanā
śraddhāvān bhajate yo māṁ
sa me yuktatamo mataḥ
(BG 6.47)

"Enikeni to sin ronu mi ni igbagbogbo olori laarin awon yogi lo je" Nitorina ti awa na ba si korin Hare krsna ilana to ye ka gba ni yen "Kilode ti aya re sen ja"? O si wa labe idabobo temi, mo si fe ko ja. Kilode to sen ko? Mo ti s'aalaye.

Ese pupo.