YO/Prabhupada 0259 - Iyipada si ipo ife fun Krishna



Lecture -- Seattle, September 27, 1968

Se enikan wa ninu apejo yi tole sowipe, iranse ko loun je? Ogbudo je be, nitoripe ipo re niyen Sugbon ilera towa ni wipe bi awa ti di iranse fun iye-ara wa kosi ona-abayo si oro na Nitoripe mo fe gbadun mo ti mu ọti amupara nitori ọti amupara na mo rope "Oga nimi je" lesekese ti ipa ọti na ba ton, apada si ipo iranse Ipo gbogbo wa niyen Sugbon kilode ti gbogbo eyan tiraka? Wan fe kin di iranse, sugbon mi ofe se. Kini ona-abayo? Imoye krsna ni ona-abayo ti eyan ba di iranse Krsna, lehin na èròńgbà lati di Oga pelu èròńgbà lati ni ominira, gbogbo e loma bosi Gege bi aworan Arjuna ati Krsna Olorun ni krsna, eda eyan ni Arjuna Sugbon o si nife Krsna bi Ore nitori irepo na, Krsna si di iwakọ fun, iranse Arjuna. Gege na ti gbogbo wa ba yipada si ife fun Krsna gbogbo ètò wa lati d'oga ma ni aseyori Nisin ko le sese, sugbon taba gba lati did iranse fun krsna die die na krsna a di iranse fun wa Oro asesemo lo je sugbon ti awa ba fe bolowo ise ile-aye, ise iye-ara agbudo bere sini s'ise fun Krsna Nkan ti awa n'pe ni Imoye Krsna niyen

kāmādīnāṁ kati na katidhā pālitā durnideśās
teṣāṁ mayi na karuṇā jātā na trapā nopaśāntiḥ
sāmpratam aham labdha-buddhis
tvām āyātaḥ niyuṅkṣvātma-dāsye.

Adura elesin kon si Krnsa leleyi " Ni gbogbo aye mi, mo s'ise fun iye-ara mi" Kāmādīnām. iye-ara ni itumo Kāmā. ifẹkufẹ " Oni awon nkan tio ye kin se sugbon nitori ifẹkufẹ ti mo ni, mo si se gbogbo wan" Nkan to ma sele niyen ti eyan ba di eru eyan na ma se awon nkan ti ofe se. O gbudo se Nibi elesin na tin jewo " moti se nkan nitori ifẹkufẹ.. awon nkan ti oye kin se.. sugbon mo se" Oda, eti di iranse iye-ara yin. sugbon isoro to wa ni teṣāṁ karuṇā na jātā na trapā nopaśāntiḥ. Mo ti s'ise gan, sugbon mi oni itelorun Wan oni itelorun. isoro ti mo ni yen iye-ara mi oni itelorun, emi na o ni, iye-ara mi o si ni fun mi ifehinti fun ise ti mo se fun wan to ba je pe mo ri be.. " Mo ti s'ise fun aduru odun yi, nisin iye-ara mi ti ni itelorun" Rara. Wan o ni itelorun. wan si p'ase wan p'ase ".. Ma si so nibi, opolopo ninu awon akeko mi, wan so fun mi pe iya arugbo wan nile sin wa oko imi lati fe Eworan. Wanti ni awon omo to dagba bayi Elo si sowipe iya agba re na fe fe Oko. Kilode? wanti koja odun àádọ́ta, tabi marundilogorin, sugbon iye-ara wan si le Osin p'ase fun wa " Beeni, ogbudo se bayi"