YO/Prabhupada 0260 - Iye-ara wa losin tiwa lati se isekuse
Lecture -- Seattle, September 27, 1968
E gbiyanju lati ni oye nipa agbara iye-ara wa Kon se pe awonn okurin ti di iranse iye-ara wan awon eyan ton ti ko ja marundilogorin, tabi ti wan oni pe ku, awon gan ti di iranse iye-ara na iye-ara wa ko le ni itelorun gege na mo ti di iranse moti di iranse iye-ara mi, pelu aduru ise tin mo sef un mi o le ni itelorun tabi ki iye-ara mi ni itelorun. isoro wa isoro to wa ni yen Nitorina Krsna so wipe
- sarva-dharmān parityajya
- mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja
- ahaṁ tvāṁ sarva-pāpebhyo
- mokṣayiṣyāmi mā śucaḥ
- (BG 18.66)
O ti se ise fun iye-ara re, fun opolopo aye tati gbe isasoto aye to koja Ẹgbẹgbẹrun mẹjọ awon eye ati eranko na si wa labe Iṣakoso iye-ara Awon eda eyan, awon aneli, gbogbo eyan to wa ninu aye yi wa labe iye-ara wan sugbon Krsna so wipe, " E gbudo teriba fun mi" E gbiyanju lati sise funmi. Lehin na ma si toju yin." otan. Ahaṁ tvāṁ sarva-pāpebhyo mokṣayiṣyāmi mā śucaḥ. nitoripe pelu ase iye-ara wa, ẹṣẹ wa ama po si itorina awa lori ipo orisirisi ni eto ara wa Ema rope gbogbo wa lori ipoo kanna gege bi eya ba si ise gegena lo ma ni ara awon ara orisirisi ta ni lati ise ati igbadun ototo lon ti wa Igbadun na wa ninu aye elede Sugbon kilode ti oun ni ara elede? nitoripe fun awon elede ko si iyato laarin, mama wan tabi, aburo-obirin gbogbo eyan lo mo bi awon aja ati elede se je niyen ni ile-aye awon eda na, awon kan wa ti mo iyato laarin, mama ati aburo-obirin.. Iye-ara wa si l'agbara gan. idi isoro wa ni yen, egbudo ni oye na. isoro apa meta ton se wa, awa de fe ona abayo kuro nitori ase iye-ara wa nitorina krsna si wa, Madana-mohana ni oruko re teba gbiyanju lati fun krsna ni ife yin, eyin na ma ri esi to wa lesekese lema mo wi pe. Sevonmukhe hi jihvādau (Brs. 1.2.234). Eto pe " Mo fe di Oga gbogbo nkan ti mo ba ri" " emi ni Olori gbogbo nkan " agbudo fi iwa yi sile Iranse ni gbogbo wa je Nisin iranse iye-ara wa laje Agbudo di iranse fun Krsna nikan Sevonmukhe hi jihvādau svayam eva sphuraty adaḥ. lesekese teba yipada si krsna die die, teba si ise fun krsna pelu otitọ, krsna a si farahan lehin na ema gbadun asepo na laarin krsna ati ara yin ele ni ife fun bi Ore, tabi Oga, tabi Ololufe... be sefe si Esi gbiyanju lati ni ife fun ke wo boya ema ni itelorun Imoye Krsna niyen. E gbiyanju lati ni oye na.