YO/Prabhupada 0265 - Ati di iranse fun Hrsikesa ni itumo Bhakti, Olori iye-ara wa



Lecture on BG 2.10 -- London, August 16, 1973

Pradyumna: Itumo "Iwo to je iran Bhārata,, nigbayen krsna si rẹrin Laarin awon ologun meejeji, Krsna si soro si Arjuna toni ibanuje

Prabhupāda: hṛṣīkeśaḥ, prahasann iva. Krsna bere sini rerin, "kini gbogo iranu yi, Arjuna" Ni alakoko o sowipe , wa mi si "Senayor ubhayor madhye rathaṁ sthāpaya me acyuta (BG 1.21). Krsna jo wa kẹkẹ mi si aarin apa meji awon jagun jagun . Emu omi wa funmi Ni alakoko o sini igbona ọkan.. Sugbon nisin asiwere yi sowipe oun le ja mo " no yotsya" Se ti ri iranu. se ri pe māyā lagbara gan, Ore krsna ni Arjuna je To je pe o bere sini huwa bi awon asiwere, ti Arjuna le sebayi talo wa ku. Wa oko mis'aari awon apa meji, nigbayi O sini igbona-okan Nisin, O nipe oun ofe ja mo. Iranu Krsna si rerin pe, Ore mi .. ko fe ja mo Krsna si rerin. Erin Krsna na ni itumo, prahasann Tam uvāca hṛṣīkeśaḥ prahasann iva bhārata, senayor ubhayor viṣīdantam, ipọnju Ni alakoko owa pelu igbona-okan lati jagun, nisi ko fe jaa mo wan si pe Krsna ni Hṛṣīkeśa. O si le, Acyuta lo je, Okan re o le yipada itumo imi fun Hṛṣīkeśa. ninu iwe Nārada-Pañcarātra itumo bhakti je hṛṣīkeśa-sevanam. nitorina wan si da oruko Hrsikesa nibi Hṛṣīkeśa-sevanaṁ bhaktir ucyate. itumo Bhakti ni wipe agbudo di iranse fun Olori iye-ara wa, Hrsikesa Awon asiwere wa ton ni pe Onisekuse ni Krsna Bawo lose je Onisekuse to ba je pe Olori Iye-ara loje Se bi awon eyan bayi se ka Bhagavad-gita sodi Ti Krsna ba je brahmacari.. brahmacari to da ni Krsna je Nkan ti Bhismadeva so niyen Ninu ile-aye yi brahmacari ipo to gaju ni Bhismadeva je O se ileri fun baba Satyavati.. Se mo alo na,.. baba Bhismadeva si ni ife fun apeja obirin kan O si fe se Obirin na ni iyawo, sugbon baba re o si gba Kilode? Oba ni mo je. Mo si fe se omoyin ni iyawo. " Rara eyin ti ni omo okurin" Omokurin iyawo t'alakoko, iya Ganges, ni Bhismadeva je Iya Ganges ni iyawo Maharaj Santanu, Omo wan toku ni Bhismadeva je adehun laarin Santanu Maharaj ati Iya Ganges ni wipe " Mo ma di iyawo re to ba je kin fi gbogbo awon omo taba ni sinu Odo Ganges" Toba ko, masi fi e sile Santanu Maharaj si ba, O si se ni iyawo ni eyo kankan osi fi awon omo to bi sinu Odo Ganges Okurin na ba bere snin ronu " Iru iyawo wo nimi fe bayi? O kon ju gbogbo omo tabi sinu Odo igbati asiko Bhismadeva de, Santanu Maharaja so wipe " Mi o legba ko se bayi mo" Iya Ganges so wipe " Motin lo niyen" "Kosi isoro, ma lo, mi ofemo. Omode yi ni mo fe" nitorina ni kose ni iyawo. nisin ofe fe Satyavati Lehin Baba omo-obirin na si sowipe " mi o le fun yin ni omomi nitoripe, eyin ti ni omo-okurin to dagba. Omo na madi Oba. Omomi o le di iranse fun yin Ti awon omo re ba le di oba, Nigbana ni mo le fun yin ni omomi Rara kolesese Sugbon Bhismadeva si mowipe " baba mi ti ni ife fun omo-obirin yi" O si lo ba Okurin apeja Eyin ro pe mofe d'Oba, sugbon ele fun baba mi omo-obirin teni Awon omo lati omo-obirin yin ma d'Oba. O si sowipe "rara mi o le se. Kilode? Awon omo ti e le fe d'Oba Seri iru ogobn ile-aye yi Nigbana lo sowipe " Mi oni se igbeyawa. Otan. " O si gbe ile-aye bi brahmacari, Nitorina itumo Oruko re. nkan to le gan tio se yipada ni itumo Bhisma Brahmacari lo je lati je ki inu baba re dunsi, o si gbe ile-aye bi brahmacari