YO/Prabhupada 0267 - Vyasadeva ti sallaye eni ti Krishna je



Lecture on BG 2.10 -- London, August 16, 1973

Gege bi Krsna bhakti se je niyen. idari tope lori iye-ara wa Gege bi Krsna se ni idari tope lori iye-ara re, gege na awon ton je elesin krsna wan ti ni idari lori iye-ara wan Gege bi Yamunacarya O si gbadura yad-avadhi mama cittaḥ kṛṣṇa-padāravinde, nava-nava-dhāmany udyataṁ rantum āsīt: lati igba timo ti ni igbala Oluwa, moti ni alaafia tio ni opin yad-avadhi mama cittaḥ kṛṣṇa-padāravinde, kṛṣṇa-padāravinde, the lotus feet of Kṛṣṇa. lati igbati Okan mi, citta, tini ifarafun Krsna tad-avadhi bata nārī-saṅgame, lati igbana ti mo ba ronu asepo pelu obirin bhavati mukha-vikāraḥ, ma kan tutọ Krsna-bhakti niyen. Gege bi Krsna-bhakti se je niyen Bhakti-pareśānubhava-viraktir anyatra syāt. ẹya-ara to dara ju ninu ile-aye yi ni asepo laarin okurin ati obirin ipilẹ ile-aye yi niyen gbogbo awon eyan ton si ise lat'aro d'ale, nitori igbadu asepo laarin Okurin ati obirin lon se Yan maithunādi-gṛha... wan si gba ewu to po wan sin se ise gan kin igbadun ninu aye wan? Igbadun asepo t'okurin ati obirin Yan maitunādi-gṛhamedhi-sukhaṁ hi tuccham. wan si se nkan ti o dafun igbadun ara wan Ile-aye niyen Krsna o ri be awon asiwere wanyi wan si se awon aworan toni Krsna pelu awon gopi. Enikan si sofun mi ni..... talo wa gan? Wan so wipe awon oni kun aworan ti Krsna tin pa Putana tabi ibi ti Krsna tin pa Kamsa Awon aworan wanyi Awon oluyaworan laini oye eniti Krsna je wa kon mu iwe awa de bere ti kun Krsna Eni ti o le mo eyan ti Krsna je Vyasadeva de ti se ijuwe krsna ninu apa mesa iwe re, latifi ni oye Krsna Ni apa mewa iwe na, osi bere pelu ibimo krsna Sugbon awon asiwere wanyi wa kon fo lo si rasalila Ni alakoko egbudo ni oye krsna gege ti eyan ba fe di ore eyan pataki, ni alakoko ema gbiyanju lati mo dada lehin na ke to bere sini gbiyanju lati mo nipa awon nkan to se igboya ni aye re sugon awon eyan wanyi wa kon fo lo si rasa lila nitorina wa so wipe onisekuse ni krsna je awon ton je onisekuse lesekese ton gba Krsna sinu aye wan, wan yipada lati gbogbo iranu ton se, bawo wani Krsna se je onisekuse. Iranu ton so niyen awon ton korin oruko krsna gbogbo wan lon si di eyan gidi sugbon wan so wipe onisekuse ni krsna je. Nkan ti oniranu alamọdaju okirun kan so niyen.