YO/Prabhupada 0268 - Kosenikeni tole ni imoye Krishna laidi iranse Krishna
Lecture on BG 2.10 -- London, August 16, 1973
O le gan koseni to le ni oye Krsna lai di elesin to daju nitoripe Kṛṣṇa so wipe, bhaktyā mām abhijānāti yāvān yas cāsmi tattvataḥ (BG 18.55). Tattvataḥ, ni oto. Oto oro ni itumo Tattvataḥ. Eyan to ba fe ni oye Krsna gbudo bere sini se ise toni ifarun Oluwa, bhakti Hṛṣīkeṇa hṛṣīkeśa-sevanaṁ bhaktir ucyate (CC Madhya 19.170). Ti eya ba tidi iranse Hrsikesa, Olori Iye-ara wa Te ba fi iye-ara yin se ise fun hrsikena na nigbana lema di Olori iye-ara yin. Nitoripe eti fi iye-ara yin sinu ise Oluwa, gege na kole ni asiko fun awon nkan imi. Eti tipamo Sa vai manaḥ kṛṣṇa-padāravindayoḥ (SB 9.4.18). Ilana ise ifarun Oluwa niyen teba fe di Olori iye-ara yin, gosvami, svami egbudo fi iye-are yin sinu ise Hrsikesa Ona soso towa niyen. Bibeko ko le sese lesekese teba gbowosile ninu ise Oluwa, lesekesemaya ma wa. " Ejo wa" Ilana to daju lleyi Kṛṣṇa bhuliyā jīva bhoga vāñchā kare, pāsate māyā tāre jāpaṭiyā dhare. teba gbagbe krsna fun iseju kan pere, lesekese ni maya ma wa "Oremi jo wa sibi" Nitorina agbudo ni ifura Awa oye ka gbagbe Krsna fun iseju kan nitorina lase se eto orin kiko Hare Kṛṣṇa, Hare Kṛṣṇa, Kṛṣṇa Kṛṣṇa, Hare Hare, Hare Rāma, Hare Rāma, Rāma... Eranti Krsna nigbogbo igba, Nigbana maya o le fowo kan yin Mām eva ye prapadyante māyām etān taranti. Maya o le fowo kan yin. gege bi Haridasa Thakura O si wa ninu ise Hrsikesa maya si wa pelu gbogbo agbara re sugbon nkan to wa se ko ri se, Haridasa Thakura si ni aseyori.