YO/Prabhupada 0269 - Kosi besele ni oye Bhagavad-gita lati awon itumo iranu
Lecture on BG 2.10 -- London, August 16, 1973
Gege na egbudo gbiyanju lati mo Krsna bi Hrsikesa Krsna si bere sini rerin pe " Oremi lo je sugbon otini ijaya" Ni alakoko osini igbona okan lati ja, senayor ubhayor madhye nisin visidantam, sugbon nisin ayare n'ja Ode ni gbogbo wa je na ode ko ni arjuna je, Wan ti juwe re pelu oruko Gudakesa Bawo lose fe je ode? sugbon o sin sebi Ode ti ba sebi Ode, bawo lase fe ni iwe Bhagavad-gita lat'enu Sri Krsna? lehin na nitoripe o je elesin oun na sin huwa gege bi ode lati fun Krsna ni ona ati fi soro Oluko to daju pelu Akeko to daju, Arjuna Agbudo kogbon lodo wan.. Arjuna ti di aṣoju awon eda ninu ile-aye yi Krsna to je Hrsikesa sin saalaye fun, pelu imọran to daju taba ka iwe Bhagavad-gita pelu okan pe afe ni oye, gege bi Arjuna Akeko to daju taba si gba awon imọran Krsna, Oluko to daju nigbana ni ale ni oye Bhagavad-gita ti eyan ba fe lo ogbon ori, tabi ko fun iwe na ni awon itumo iranu, tabi ko si ro pe alakowe lo je, eyan na o le ni oye Bhagavad-gita Ko lesese. Ogbudo teriba Nitorina wan si so wipe ninu Bhagavad-gita tad viddhi praṇipātena paripraśnena sevayā (BG 4.34). Gege bi Arjuna se teriba awa na gbudo teriba Śiṣyas te 'haṁ śādhi māṁ prapannam: (BG 2.7) " moti teriba fun e, moti di akeko si E " Pe eyan di akeko itumo re ni wipe oti teriba asi gba imoran Oluko re l'atinuwa Arjuna ti gba be Sugbon O dabi wipe o so wipe " Krsna Mi O le jagun" Ti Oluko re basi saalaye fun, O ma jagun Kon se fun ara re lon Jagun fun itelorun Oga re asi jagun, Opin Bhagavad-gita niyen gege na nigbati Krsna ripe Arjuna tini ibanuje, visidantam pe ko si fe se ise re Nitorina ni ese-iwe to kan, O si so wipe: aśocyān anvaśocas tvaṁ prajña-vādāṁś ca bhāṣase: (BG 2.11) "Arjuna, Ore mi lo je" Ma rori mo, maya l'agbara gan mo si ti ripe ibanuje ti ba e, ore mi lode je gbo nkan timo fe so O si so wipe asocyan: " kilode ton se ni ibanuje lori nkan ti oye" Itumo śocya ni oro ibanuje, itumo asocya niwipe eyan ogbudo so awon oro ibanuje aśocyān anvaśocas tvaṁ prajña-vādāṁś ca bhāṣase. " sugbon O sin soro bi eyan to l'ogbon" nitoripe O ti soro. oto or ni awon nkan to so Arjuna soro nipa varṇa-saṅkara, Ti awon obirin ma bere sini se isekuse, gbogbo olugbe loma di varna-sankara. oto oro niyen Ounkooun ti Arjuna sofun Krsna nitoripe ko fe jagun, Oto oro lon je Sugbon ti eyan ba foju mimo wo, O le je Oto tabi iro sugon lati ipo awon nkan to ya si mimo, to fibe niyi aśocyān anvaśocas tvam. nitoripe oro ibanuje ton so, nitori awon nkan aye yi lon se imoye krsna si ti dalebi awon nkan aye yi Aśocyān anvaśocas tvam: (BG 2.11) Nitori ara re lon se soro ibanuje Nitoripe gbogbo awon eyan ton se ise fun ara wan, eranko daju wan lo.