YO/Prabhupada 0274 - Awa na pelu ninu Brahma-sampradaya



Lecture on BG 2.7 -- London, August 7, 1973

gege na egudo sumon Olorun, Krsna tabi awon alabasepo re gbogbo awon asiwere to ku Ti eyan bani asepo pelu eni tio kin se alabasepo pelu Krsna, awon asiwere lon ba rin niyen bawo ni eleni oye?: Egbudo loba awon alabasepo Krsna tabi Krsna Tad vijñānārthaṁ sa gurum eva abhigacchet (MU 1.2.12). tani guru je? Samit-pāṇiḥ śrotriyaṁ brahma-niṣṭham Guru ni oye krsna ni iba to pogan. Brahma-niṣṭham. Itumo Śrotriyam ni eyan toti gbo, eyan toti gba imoye lati awon Olori pelu lat'ona śrotriyaṁ paṭha, Evaṁ paramparā-prāptam imaṁ rājarṣayoḥ viduḥ (BG 4.2). gege na agbudo ko ogbon gege bi Arjuna ta ba ni Idamu taba si gbagbe nkan ti ise waje, nigbana lama ni idamu gege na ise wa ni wipe agbudo sumon Krsna gege bi Arjuna teba beere: " Iboni Krsna wa? Krsn osi nibi sugbon awon alabasepo re wa". Egbudo sumon. Nkan ti Veda so niyen Tad-vijñānārthaṁ sa gurum eva abhigacchet (MU 1.2.12). Eyan gbudo gba guru. Sugon Krsna ni guru je Tene brahma hṛdā ya ādi-kavaye muhyanti yat sūrayaḥ (SB 1.1.1). Janmādyasya yataḥ anvayāt itarataś ca artheṣu abhijñaḥ svarāt. Egbudo sunmọ. Guru niyen Taba ronu wo, ka mu Brahma.. Nitoripe oun ni eda alakoko ninu ile-aye yi, asi le gba bi guru gege bi awa ni asepo pelu Brahma-sampradāya. sampradāyas merin lowa, Brahma-sampradāya, Śrī-sampradāya, Rudra-sampradāya ati Kumāra-samapradāya. mahājanas ni gbogbo wan je. Mahājano yena gataḥ sa panthāḥ (CC Madhya 17.186). Agbudo tele ilana awon mahajana.

Mahajana ni Brahma je, nitorina ema ri iwe Veda lowo Brahma Oun lo si fun wa ni ilana t'alakoko lati awon Veda sugbon nibo loti gba imoye Veda na? Nitorina ni Imoye Veda se je apauruṣeya. Kon se nkan awon eda. Nkan Olorun lo je Dharmaṁ tu sākṣād bhagavat-praṇītam (SB 6.3.19). gege na bawo ni Krsna se fun Brahman? Tene brahma hṛdā. Itumo brahma ni imoye Veda. Śabda-brahma. Tene. Lati hṛdā loti gba imoye Veda Teṣāṁ satata-yuktānāṁ bhajatāṁ pritī-pūrvakam (BG 10.10). Sugbon nigbati Olorun da Brahma ko si mo nkan to ma se, " Kini ise ti moni lati se? Gbogbo nkan si dudu" Osi ṣaṣaro, lehin na Krsna si fun ni imoye " Ise re ni ko se bayi" Tene brahma hṛdā ya ādi-kavaye. Ādi-kavaye (SB 1.1.1). ādi-kavaye ni Brahmā je gege na Krsna ni guru je. Krsna si ti salaaye ninu iwe Bhagavad-gītā awon asiwere wanyi kosi bon sele gba Krsna bi guru Wan si loba awon asiwere, tabi awon elese bi guru. Bawo ni eyan bayi le je guru?