YO/Prabhupada 0275 - Ise ni itumo Dharma



Lecture on BG 2.7 -- London, August 7, 1973

Krsna ni Guru je. Arjuna ti funwa ni apeere imi Pṛcchāmi tvām. kini itumo tvām? Kṛṣṇa kilode to sen berelowo mi? Dharma-sammūḍha-cetāḥ (BG 2.7). "Mi o mo nkan ti ise mi je mo, dharma" Ise ni Itumo Dharma Dharmaṁ tu sākṣād bhagavat-praṇītam (SB 6.3.19). Sammūḍha-cetāḥ. gege na kiloye kin se? Yac chreyaḥ. Kini ise mi gan? Śreyaḥ. Śreyaḥ ati preyaḥ. Preyaḥ..nkan meji lon je. Nkan ti mo gba feran ni itumo Preya Opin to gbehin ni itumo śreya. Nkan meji lo je. Gege mi awon omode ton fe sere lojojumo iwa mode niyen. śreya niyen Sugbon ogbudo keko ton ba fe ki ojo iwaju re dara. preya ni eleyi je Itumo preya ati sreya niyen. Sugbon Arjuna o fe preya o ti bi Krsna ni ibeere sugbon kon se fun Sreya Toba jepe lesekese lon ronu pe " mi o leni idunnu tin ba pa awon ara-ile mi, nigbana sreya niyen ma je Sugbon nitoripe O bere sini ronu bi omode, Sreya Sugbon nigbato pada si ogbon ori re.. Ni otooro, kon se pe ko rori wo, nitoripe eyan to logbon ni Arjuna Yac chreyaḥ syāt. O bere fun sreya. kini Opin fun ile-aye mi ? Yac chreyaḥ syāt. Yac chreyaḥ syāt niścitaṁ (BG 2.7). idojuko ni itumo niścitaṁ. , laisi asise. Niscitam Kosi iwulo fun iwadi, nkan ti Bhagavata so niyen nipa itumo niścitaṁ. Ipinnu oro na niyen Nitoripe opolo wa o le mo itumo niścitaṁ. . idojuko ni itumo sreya Ti eyan o ba mo, Oye ko beere lowow Krsna tabi awon alabasepo re Yac chreya syāt niścitaṁ brūhi tan me.

" ejo e sofun mi" "kilode to fe kin soro si e" nibi wan sowipe : śiṣyas te 'ham (BG 2.7). "Moti gba pe guru leje simi. Moti di sisya yin" Oukooun teba so ni moma se, itumo Śiṣya niyen lati oro ton pe ni śas-dhātu ni sisya tiwa. Śas-dhātu. Śāstra. Śastra. Śāsana. Śiṣya. Orisun kanna lon tiwa. Sas-dhatu. iṣakoso itumo Śas-dhātu, gege na oni orisirisi ona ti eyan logba lati ni isakoso Eyan le ni isakoso lori wa taba je sisya fun guru na. sas-dhatu niyen tabi ki sastra ni idari lori wa...ohun igajun gege bi Oba seni ohun-ijagun, ti awon eyan ba ko lati tele awon ilana ijoba awon Olopa tabi awon ologun Sastra leleyi je, sastra na niyen je iwe ni itumo Sastra, iwe-mimo, gege bi Bhagavad-gita. gbogbo nkan lo wani be gege na sastra tabi guru gbud ni idari lori wa. Nitorin lon se so wipe " śiṣyas te 'ham (BG 2.7). lat'okan mi mo teriba fun e" ki l'ẹri pe oti di sisya mi? Śādhi māṁ tvāṁ prapannam. "Nisin moti teriba fun e." Prapannam.