YO/Prabhupada 0277 - Itumo imoye Krishna ni wipe agbudo ni gbogbo imoye towa



Lecture on BG 7.2 -- San Francisco, September 11, 1968

Prabhupāda:

jñānaṁ te 'haṁ sa-vijñānam
idaṁ vakṣyāmy aśeṣataḥ
yaj jñātvā neha bhūyo 'nyaj
jñātavyam avaśiṣyate
(BG 7.2)

Awa si fe mo nkan ti imoye je. Itumo Imoye ni oye bi ile-aye yi sen sise kini idi gbogbo ise yi, kil'agbara. gege bi awon oni Sayensi, wan si fe wa idi gbogbo agbara to wa. gege bi ile-aye yi sen fo lori Ofurufu. Iru nkan totobi bai pelu gbogbo ori-oke, ati awon okun, awon ile-giga, awon ilu, awon Orile-ede gbogbo ile-aye yi sin fo ni ofurufu bi owu gege na ti eyan ba mo bi ile-aye yi sen fo, imoye niyen je.

Gege na itumo imoye Krsna ni wi pe agbudo ni oye orisirisi imoye to wa Kon se pe awon elesin Krsna feran imoye titawa nikan Awasini Imoye, sayansi, eko nipa esin, Iwa, gbogbo nkan lawani- Gbogbo nkan toye ka mo gege bi awon eda Krsna si sowipe " Mo fe soro nipa Imoye fun gbogbo yin" Imoye Krsna niyen Eyan toba ni imoye Krsna yi, ko gbodo je ki enikankan ton oun je ti eyan ba si beere lowo ko salaaye bi awon isogbe-orun yi sen fo, bi ara eda sen yipo, ati iwonba eda meelo lo wa ninu aye yi, ati bawo lon se ni idale Imoye Sayensi ni gbogbo eleyi je, fisiksi, ẹkọ nipa ohun ọgbin, kemistri, ìtòràwọ̀ ati gbogbo nkan Nitorina Krsna si so wipe, ti eyan bani Oye imoye Krsna kosi nkan toku lati mo. Itumo yen ni wipe, eyan na timo gbogbo nkan to ni lati mo gbogbo eyan lon wa Imoye, sugbon taba ni imoye Krsna taba mo Krsna, atini imoye gbogbo nkan toku.

tac-chakti viṣaya vivikta-svarūpa viṣayakaṁ jñānam. Ema ni ni imoye nipa ipo yin niniu aye y ile-aye yi, ijoba Orun, Olorun, asepo wa pelu Olorun, Akoko, Ofurufu, gbogbo nkan Oni nkan topo tawa gbudo mo, sugbon nkan to se pataki ju ni Olorun, awon eda, akoko, ise, ati agbara ile-aye yi Awon nkan merin wanyi agbudo mo wan Kosi besele sowipe "kos'Olorun" Oludari ni Olorun je, kosi be sele sowipe koseni toni idari lori yin Oludari gbudo wa. Ninu ilu na, koseni tole sowipe ko s'Olori. Olori gbudo wa Nigbogbo titi, gbogbo ile, idari gbudo wa, Idari lati Ijoba fun apeere toba je wipe ibi itaja nibi, ijba ma ni idari nibi na Eyan gbudo ko ibi itaja na gege bi ijoba sewi, eyan osile gbe ni be Toba jewipe ile-gbigbe ni "Egbudo seto ina bai". Idari ma wa Teba si wa oko loju titi, " egbudo wa ni apa Otun". Idari wa teba ri ami to wipe " e da duro", egbudo da duro.

Gege na, nigbogbo igba ni eyan wa labe idari elomi sugbon Oludari ni Krsna je Sugbon Olori kna si ni eyan toje Olri fun oun na teba si fe mo eni to je Olori fun gbogbo wan, ema ri Krsna Sarva-kāraṇa-kāraṇam (Bs. 5.1). Brahma-saṁhitā si sowipe, īśvaraḥ paramaḥ, Oludari ni Kṛṣṇa je. Īśvaraḥ paramaḥ kṛṣṇaḥ (Bs. 5.1).Oludari ni itumo Īśvaraḥ eyan gbudo mo eni ti Oludari yi je ati bi Oludari na sen sise (omode sunkun) Idamu niyen. jñānaṁ vijñānaṁ te sahitam. Kon sepe ka kon mo eni ti Oludari na je, sugbon agbudo mo bo sen sise agbudo mo aduro agbara toni, ati bo se je pe oun ni Oloudari jñānaṁ vijñānaṁ te nate tubhyāṁ prapannāya aśeṣataḥ.