YO/Prabhupada 0278 - Itumo Akeko ni eyan to fe keko
Lecture on BG 7.2 -- San Francisco, September 11, 1968
nisin eyan toni ibasepo pelu Krsna tode ti teriba fun, iru eyan bayi lole ni oye Imoye yi Ti eyan ooba teriba fun Olorun kosi bosele ni oye nipa Oludari ati agbara re ati bo se ni idari lori gbogbo nkan Tubhyāṁ prapannāya aśeṣataḥ samagreṇa upadekṣyāmi. nkan to wa niyen. ema ka ni awa apa-iwe to kehin Krsna sowipe nāhaṁ prakāśaḥ sarvasya (BG 7.25). gege bi eyan to ba wole si ile-eko ti eni na ba kọ lati teriba fun awon ofin ninu ile-iwe na bawo lose fe ni oye akeko to ba fun? Ni ibikibi ti eyan ba fe, ti eyan ba fe gba nkan, egbudo gba kon ni idari lori yin, gege bi awa sen ko awon eyan lati inu iwe Bhagavad-gita teba se aimatele awon ofin lati awon akeko wa Kosi besele gba imoye na gege na, Imoye toto nipa Oludari ati ilana bo sen se ise re eyan leni iru idari bayi toba teriba bi Arjuna si Krsna. Afi t'eyan ba di eda to teriba fun Olorun, kole sese Oye ke ranti pe, Arjuna si teriba fun Krsna Śiṣyas te 'haṁ śādhi māṁ prapannam (BG 2.7). Nitorina Krsna sen ba soro
Nitorina, awon ìtàkurọ̀sọ lati iwe mimo bayi koye ka se wan ni osere afi ti eni ton soro bani asepo pelu awon apejọ eniyan awon akeko ni itumo apejo tin mon so, awon ton ba gba imoye yi awon ni akeko Śiṣya. Śiṣya ni Oro na ni ede Sanskrit ẹka-ọrọ iṣe ni oro śās ni ede Sanskrit Idari ni itumo śās.. lati oro yi ni sastra ti wa Itumo Sastra ni awon iwe to le fun eyan ni idari. itumo imi ini ohun-ijagun ti ariyanjiyan oba sese, kosi bi awon eyan sefe l'ogbon.. gege bi ijoba L'alakoko wan fun yin ni awon ofin Teba ba se aimatele awon ofin na, teba sise aimatele awon iwe ton fun wa ni idari, igbese to ma tele ni sastra. Ohun ijagun ni Itumo Sastra Teba se aimatele awon ofin ijoba fun apeere ewa oko yi ni apa otun, teba ko lati tele wansi yo igi si yin egbudo ni eyan toni idari lori yin, sugbon teba je okunrin jeje ele gba idari yin lati sastra sugbon teba se ijogbon, Ohun-ijagun Durgadevi ma ko yin logbon Se ti ri iworan Durgadevi, pelu ida to l'apa meta, itumo wan ni awon isoro meta ninu ile-aye yi kosi be sele se aimatele awon ofin gege bi ijoba se ri, bena ni Ijoba Krsna se ri. Ko le sese Fun apere ejeka wo awon ofin nipa ilera Teba jeun ju, aisan ma wo ara yin Ema ni ikun gbigbi, dokita asi sufon yin kema jeun fun ijo meta Idari to wa niyen. Iseda. Iseda ti Olorun ti da niyen. Lesekese loma sise Awon eyan tio logbon kosi bon sele ri ofin Olorun, sugbon Olorun sini ofin Oorun ran lasiko to ye lojojumo, nkankanna pelu Osupa Ojo kini ni odun ma wa lasiko to ye.
Gege na idari wa. Sugbon awon asiwere ko si biwan sele ri. Gbogbo nkan loni idari. Gege na wan gbudo mo Olorun ati bi awon ile-aye yi sen sise agbudo mo awon nkan yi, kon sepe ka se nkan nitoripe otewalorun awon ton tele esin kan tabi keji nitoripe gbogbo eyan se, iwa awon eyan ton ti di afoju ni eto esin Sugbon ni aye isin awon eyan si ni ilosiwaju ni eto eko gege na Bhagavad gita asi fun yin ni gbogbo alaye teba fe lati mo Olorun, pelu ogbon, pelu ariyanjiyan ati imoye kon sepe ke ma tele bi awon afoju. Imoye Krsna o ri be Osi ni idi re ni awon imoye to daju Vijñānam. Jñānaṁ vijñāna sahitam. laisi vijñāna sahitam... ilana telefi ni oye imoye yi ni wipe egbudo teriba Nitorina itumo akeko ni eyan to ba fe gba eko ti eyan o ba fe k'eko kosi bosele ni ilosiwaju. Kolesese ti eyan ba fe ni imoye ni nkankan, ko ba je ise, tabi, imoye nkan Eyan na gbudo gba eto idari to wa ninu re Samagreṇa vakṣ ya svarūpaṁ sarvokaraṁ yatra dhiyaṁ tad ubhaya-viṣayakaṁ jñānaṁ vyaktum.