YO/Prabhupada 0283 - Ife ni eto ise wa



Lecture -- Seattle, September 30, 1968

Prabhupāda: Govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ bhajāmi.

Olufokansi: Govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ bhajāmi.

Prabhupāda: Eto ise wa ni lati mo basele s'aduro s'olorun pelu ife Govindam ādi-puruṣaṁ. Imoye Krsna niyen Awa si fe kp awon eyan bon sele niife krsna eto wa ni bi awon eyan sele nife ara wan. Eto ise wa niyen Gbogbo eyan lo fe ni ife elomi, sugbon gbogbo latini ibanuje nitori awon eyan tiole da ife na pada Koleye awon eyan Wansi ko wan, " l'alakoko egbudo ni'fe ara yin" wa tun sowipe, " lehin na egbudo ni'fe awon Baba ati iya teni" lehin na " eni'fe fun aburo yin tabi egbon lehin na " Eni'fe awujo yin, tabi Orilde-ede teti wa, kesi ni'fe gbogbo eyan ni aye yi" sugbon kosi besele ni itelorun lati gbogbo ife wanyi, afi teba de ipo tenife fun Krsna. Nigbana lema ni itelorun teba ju okuta sinu omi odo, lesekese lema ri awon ayika lori omi odo na awon ayika lori omi na asi tobi titi digba ton ba kan eti-odo afi ti ayika na ba ka eti-odo ama tobi si gege na agbudo fikun.. asile fikun niwonba meji teba fe beere lati " moni ife ilu mi, moni ife awujo eyan, etc sugbon teba losi Krsna, gbogo nkanlo wan'be Eleyi si da gan, nitoripe itumo Krsna ni eni toni ifarafun gbogbo awon eda Kini idi fun gbogbo nkan? Nitoripe orisun gbogbo nkan ni Krnsa je ninu ebi awon eyan, tabe feni'fe baba, aburo, awon iranse Ninu ile baba yin, iyawa baba yn to je iya fun yi Orisun gbogbo eto na ni baba. apeere to daju niyen Gege na teba ni'fe fun Krsna gbogo ile-aye yi a kunfun ife wa fun apeere teba ni'fe fun igi, ema ni'fe awon ewe to wa lori re, awan igi ara re na, gbogo nkan nipa igi na teba si da omi si ese igi na, nigbana ife te ni fun a seri teba ni'fe awon eyan lati orile ede yin, ema seto lati ri pe wan si ni k'eko teba si ni ilosiwaju ni eto owo, tabi ogbon, kilema se? esi son owo-ori si ijoba. kon sepe ema fi owo-ori na pamo. ema son owo-ori na si ijoba awn lon ma seto bi awon eka ile-akeko ma ri gba wan si fun eka toni ise lati gbeja ijoba, wansi fun eka ilera... Nitorina... Awon apeere lasan ni awonyi,, sugobn teba fe ni'fe gbogbo nkan egudo ni'fe Krsna. kosi besele ni ibanije nitoripe, ife asepari loje teba ni'fe to kun, kosi besele ni ibanuje. gege bi eyan to jeun kunu teba si ni jeun yo, ema sowipe " Moti yo, mio jeun mo"