YO/Prabhupada 0284 - Ati teriba ni iwa adayeba ti moni
Lecture -- Seattle, September 30, 1968
Imoye Krsna yi si rorun gan. Caitanya Mahāprabhu losi daale Imoye toti pe gan sini lati iwe mimo veda, sugbon lat'oju itan imoye Krsna yi beere nigbati Krsna wa sinu aye yi ni aye egbrun marun atijo lehin Caitanya si wa ni aye ogorun marun atijo, osi wa se itesiwaju imoye Krsna iṣẹ apinfunni Caitanya ni ārādhyo bhagavān vrajeśa-tanayaḥ. te ba fe ife ninu aye yin, ...tabi teba fe gba ipo to kehin Iro niyen. Gbogbo eyan lofe ominira, sugbon koseni to ni ominira na gbogbo wa la wa labe elomi, koseni tole sowipe "mio si labe elomi" senikankan wa to je pe enina o si labe elomi? Rara. Gbogbo wa la wa labe elomi, laise agidi pelu agidi ko, Obirin a si sofun Okurin mo fe teriba fun yin.. gege na Okurina asi sofun Obirin mo fe teriba fun e kilode? Iwa mi niyen Mofe teriba fun e nitoripe bon seda mi niyen., sugbon mio mo idi to seribe eyan le ma teriba fun enikan sugbon asi teriba fun elomi gege bi osise. O le ma bawa sise sugbon to ri ibomi ton le sonwo dada fun, asi lo sibe Iyen owipe oti ni ominira, Caitanya si ko wa pe agbudo teriba fun enikan ka si s'adura si Kilode te fe s'adura s'enikan? afi tenina ba je eyan to lagbara ju eyin kilode te fe s'adura si? Mosi teriba fun Oga mi nitoripe mo rowipe ogajumi lo a sonwo osu funmi, dollar ogurn mefa l'osu nitrina mo gbudo teriba fun, mo gbudo se nkan to ma telorun.
Caitanya Mahāprabhu sowipe agbudo teriba fun Krsna Ārādhyo bhagavān vrajeśa-tanayaḥ. teba fe s'adure si enikan, es'adura si Krsna tad-dhāmaṁ vṛndāvanam teba fe s'adura si enikan oye ke s'adura si Krsna, tabi ilu Vrndavana Nitoripe gbogbo wa ni'fe ilu kan Eto orile-ede niyen enikan le sowipe moni'fe Orile-ede America, elomi asowipe moni'fe Orile-ede China Elomi leeni ife fun Orile-ede Russia, gege na gbogbo eyan lo feran ilu kan tabi keji Bhauma ijya-dhīḥ. Bhauma ijya-dhīḥ. dondon ni wipe awon ma nife fun Orile-ede kan boya lati ibi ton bi si Caitanya Mahāprabhu si sowipe, teba fe nife enikeni, oye ke nife Krsna teba fe n'ife ilu kan, oye ke n'ife Vrndavana Ārādhyo bhagavān vrajeśa-tanayas tad-dhāma vṛndāvanam. t'enikan ba si beere " bawo ni mosele n'ife Krsna? Mio le ri Krsna. Bawo ni mo sele n'ife fun Caitanya Mahāprabhu so wipe, ramyā kācid upāsanā vrajavadhū-vargeṇa yā kalpitā. teba fe mo besele nife fun Krsna e tele awon gopi egiyanju lati se bi awon gopi Ife awon Gopi lo gaju ninu aye yi Ramyā kācid upāsanā. Orisirisi ife lowa ninu aye yi T'alakoko ni "Olorun si funwa ni nkan tama je" Ibere niyen, wansi ko wa basele nife Olorun "Elo si ile-adura ke si gbadura si Oluwa fun gbogbo nkan teba fe" Ibere niyen. sugbon Ife gidi koniyen. aami Ife to daraju lema ri pelu
Awon gopi Iru ife wo lon ni fun Krsna? Wan n'ife Krsna olúsö-àgùntàn okurin ni Krsna je, oun pelu awon ore re wansi jade lojojumo pelu awon maalu Bose ri niyen. Nitoripe, nigbayen awon eyan ni itelorun pelu ile ton ni ati maalu, otan. ọna abayọ fun gbogbo isoro nipa ọrọ aje Kode si ile-ise nigbana. Koseni ton sise fun elomi Wan si ri ounje lati ile, wan si ni wara lati awon maalu. Isoro ounje ti tan