YO/Prabhupada 0328 - This KC Movement is All-embracing
University Lecture -- Calcutta, January 29, 1973
gege na imoye Krsna yi wa fun gbogbo eyan O le fi ipari si gbogbo isoro ayeyi- oniselu, awujo, oro-aje, esin, gbogbo nkan. Ibere mi niwipe mon sise pelu awon akeko mi lati America ati Europu, awon omo-ilu India nko? Mo rowipe ninu akojopo wa yi, awon alakowe, po gan. E parapo pelu egbe wa yi, gege bi ase Śrī Caitanya Mahāprabhu,
- bhārata-bhūmite manuṣya janma haila yāra
- janma sārthaka kari' karo paropakāra
- (CC Adi 9.41)
Asiko toye ka sise iranlowo fun gbogbo agbaye. Idamu wa ni gbogbo agbaye. Seyin mo ni awon ilu-geesi, awon egbe hippie. Seyin mo awon hippie? Alakowe na ni wan, lati awon ebi ton lowo na, sugbon awon eyan yi o feran nkan ti baba wa fe. Wanti fi sile. Gege na asiko to daraju lati se iwaasu ni gbogbo agbaye leleyi. Eyin pariwo nitoripe, Pakistan ti gba ile die lowo yin, sugbon teba pin egbe imoye Krsna yi, gbogbo agbaye ma di Hindustan. Agbara yi wa, mole jerisi. Awon eyan fe iru nkan bayi. Tin ba joko ni India mo kon lo asiko mi ni ilokulo. Ni awon orile ede ni'ta, awon eyan si mu egeb yi ni pataki, wansi lo dada.
Gege na mosi wa sinu ile-eko giga yi, nitoripe mo fe ni awon imi ninu yin di brahmana gidi. ile-iwe Sanskrit fun awon brahmana lo wa fun. Paṭhan pāṭhan yajana yājana dāna pratigraha. Pandita ni oruko brahmana. kilode? Nitoripe brahman gbuod keeko. Ode ko ni brahmana je. eka ile-iwe yi, ti ede Sanskrti fun awon brahmana loje. mosi fe ki imi ninu yin wa sinu egbe mi, ke lo si awon ilu -geesi, ke sewaasu egbe Caitanya Mahaprabhu. Pṛthivīte āche yata nagarādi grāma. Nkan pataki to ye ka se leleyi. A ti da awo ile-adura to po sugbon agbudo da awon imi na, awon ile adura Radha-Krsna, ile adura Caitanya Mahaprabhu, ni gbogbo abule, ati ilu laye yi. Lati gbogbo awon ile-adura wa , awan ran awon eyan ninu oko. wan losinu awon abule ni Europe ati America wansi gba iwaasu wan. ni ilu- geesi gan, wan loo lati abule kan sikeji Awon eyan si feran iwaasu wan gan. Egbe yi da gan. Awon alufaa Kristiani, o ya wan lenu gan. O ya wan lenu gan Ikan ninu awon alufaa ni Boston, o si ko ninu iwe iroyin pe awon omo- okurin wanyi lati ebi Krsitiani ati jew lonti wa Ki egbe yi to de, wan o fe wa si awon ile-adura kristiani gan. Nisin wan nife Olorun gan. O ti gbagbe. Awon alufaa Kristian gan wa pelu wa. Awon ton logbon gan mo pe " Swamiji fuh awon eyan ni nkan to daju." Baba wan ati baba agba wan wan teriba funmi. wan sowipe, "Swamiji, ore-ofe nla ni funwa pe e wa si ilu wa." gege na emini kan nimom sise, wansi nife egbe yi. Oye ki awon alakowe lati ile-iwe giga wa se iwaasu egbe yi. Ise awon Brahmana niyen, iwaasu. Brahmā jānāti. Eyan gbudo mo Brahman, kosi pin imoye yi, brahma-jnana. ise brahmana niyen.