YO/Prabhupada 0339 - God is the Predominator - We are Predominated
Lecture on SB 5.5.2 -- Hyderabad, April 11, 1975
fun asiko tawa ba wa ninu ile-aye yi, iyato ma wa: omo-ilu India nimi, omo-ilu America ni e, Omo ilu Geesi loje," Bayi bayi loje, orisirisi nkan bayi. nitorina teba fe wa sori ipo imokan emi, sarvopādhi-vinirmuktam ni ilana tema tele. Sarvopādhi-vinirmuktaṁ tat-paratvena nirmalam (CC Madhya 19.170). Ibere to wa niyen. Itumo iyen niwipe agbudo bere lati ipo brahma-bhūta. Brahma-bhūta... (SB 4.30.20). Nkankana Ninu Nārada Pañcarātra, sarvopādhi-vinirmuktam,ati brahma-bhūtaḥ prasannātmā (BG 18.54), Bhagavad-gītā, nkankana Ibibkibi teba ri iwe Veda, nkankana loje. Gege na Olori loje. Kosi idamu kankan. ninu aye tawayi, tin ba ko iwe kan, teyin na ko iwe tiyin, mio ni gba nkan teyin so, eyinna o ni gba nkan timonn so. Bi ile aye se ri niyen. Sugbon ninuj ipo mimo, imokan nipa emi wa. Kosejo alebu, kosi itaraeni, kosi iye ara tio djau, kossein tan tanya je. ipo emi niyen. gege na Bhagavad-gītā sowipe, brahma-bhūtaḥ prasannātmā na śocati na kāṅkṣati (BG 18.54). nkankana lowa ninu Nārada Pañcarātra:
- sarvopādhi-vinirmuktaṁ
- tat-paratvena nirmalam
- hṛṣīkeṇa hṛṣīkeśa-
- sevanaṁ bhaktir ucyate
- (CC Madhya 19.170)
Ipo toye ka wa sori re niyen, hṛṣīkeṇa...
iye-ara nitumo Hṛṣīka, awon iye ara tayeyi ati awon mimo. Kini iye ara mimo? Iye ara mimo o kin se iye-ara lasan. Rara. Iye-ara to yasi mimo. Ninu iye ara to mo moronu wipe, " Ara omo-ilu India nimo ni, nitoripe mo gbudo sise fun India," " Ara omo-ilu America nimo ji, mo gbudo sise fun America." upadhi niyen. Sugbon itumo iye ara mimo niwipe sarvopādhi-vinirmuktam - " Mio kin se mo ilu India, emio kin se omo-ilu America, mio kin se brahmana, mio kin sudra. Kini mowa je? Gege bi Caitanya Mahāprabhu se so Kṛṣṇa na ti sobe, sarva-dharmān parityajya mām ekam... (BG 18.66). ipo emi leleyi, pe " mio kin se ara dharma yi tabi dharma toun. Moti teriba fun Krsna." sarvopādhi-vinirmuktam (CC Madhya 19.170). Teyan ba le wa sori ipo pe " Emi nimi. Ahaṁ brahmāsmi. Moni asepo pelu Olorun...." Mamaivāṁśo jīva-bhūtaḥ (BG 15.7). Kṛṣṇa sowipe gbogbo awon eda yi, wan ni asepo pelu mi." Manaḥ ṣaṣṭhānīndriyāṇi prakṛti-sthāni karṣati: (BG 15.7) "Wan sise lati le wa laaye, wansi wa ninu idimu okan ati ara wan. Bo se ri niyen.
Imoye Krsna wa sin ko awon eyan pe: " Ara yn kole je, okan yin ko leje, ogbon yin ko leje, emi leje " Krsna ti jerisi mamaivāṁśa. Ti Krsna ba je emi to gaju, emi na leyin na. sugbon iyato to wa niwipe, oun lo gaju, awa keresi. Nityo nityānāṁ cetanaś cetanānām eko yo bahūnāṁ vidadhāti... (Kaṭha Upaniṣad 2.2.13). Nkan to awon iwe Veda so niyen. Eda lo je gege b awa na, sugbon oun ni eda to gaju, aw si keresi. Iyato to wa niyen. Eko yo bahūnāṁ vidadhāti kāmān. Ipo wa niyen. Imoye ara eni niyen. toba ti ye yin pe Krsna ni Olorun to gaju, oukoun teba so, Oun ni ei to gaju, awa si keresi, oun ni Oludari gbogbo nkan, awa lon toju. Oun ni Oga wa, awa ni iranse re," imoye talakoko niyen. Nkan ton pe ni brahma-bhuta niyen. sugbon teba ni ilosiwaju ninu ipo brahma-bhuta,lehin ibimo to po ale ni oye nipa nkan ti Krsna je. Bahūnāṁ janmanām ante (BG 7.19). ninu Bhagavad-gītā, Kṛṣṇa sowipe bahūnāṁ janmanām ante jñānavān māṁ prapadyate. teyan ba logbon, jñānavān, ise to ma se ni vāsudevaḥ sarvam iti sa mahātmā sudurlabhaḥ (BG 7.19). lehin lole mo pe Vasudeva, omo Vasudeva, Krsna ni gbogbo nkan. Pipe imoye Krsna niyen.