YO/Prabhupada 0342 - We are All Individual Persons, and Krishna is Also Individual Person

From Vanipedia
Jump to: navigation, search
Go-previous.png Previous Page - Video 0341
Next Page - Video 0343 Go-next.png

We are All Individual Persons, and Krishna is Also Individual Person
- Prabhupada 0342


Lecture on CC Adi-lila 7.7 -- Mayapur, March 9, 1974

Eyan ototo ni gbogbo awon eda ile aye yi je, eyan ni ni Krsna je. Imoye leleyi. Nityo nityānāṁ cetanaś cetanānām eko yo bahūnāṁ vidadhāti kāmān (Kaṭha Upaniṣad 2.2.13). Krsna tabi Olorun, nita lo je, tabi ayeraye. Nitya na laje, ayeraye. Na hanyate hanyamāne śarīre (BG 2.20). Awa o le ku. Ibere imoye emi leleyi je, pe " Ara mi ko ni mo je, emi nimi, ahaṁ brahmāsmi,sugbon eyan toyato nimi>" Nityo nityānām. Eyan ni Krsna je, eyan na nimo je. Nigbati Kṛṣṇa sowipe sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja (BG 18.66), kon sepe mama di ikan pelu re tabi ma wonu ara Krsna. Moma wa bi mose wa, Krsna na asi wa bo sewa, sugbon moma se gege bose so. Nitorina ninu Bhagavad-gita Krsna sofun Arjuna wipe " Moti salaaye gbogbo nkna fun e. Kilo ro nisin? Kon sepe Krsna fi agidi ba Arjuna soro. Yathecchasi tathā kuru: (BG 18.63) " Nisin nkan to ba wun e ni ko se." Eyan to yato niyen.

Imoye to gaju niyen, imoye Mayavadi yi, pe agbudo wonu are re lo, itumo re niwipe agbudo wonu awon ilana Krsna. Maya lati gbe ara fun, nitoripe awan se orisirisi nkan. Nitorina awon nkan tiyin ati titemi ma daabo. sugbon tab gba pe Krsna ni Olori awa meji, awa o le ja mo. nkankanna niyen je, kon sepe a ma so idanimo wa nu. awon Veda ti so, Krsna na ti jerisi pe, gbogbo wa yato. A yato sira wa. Svayaṁ bhagavān ekale īśvara. yato to wa niwipe oun ni Olori to gaju, īśvara. Olori nitumo Isvara.Olori na lawa na je, sugbon awa keresi, gege na ekale isvara loje, Olori kan. Īśvaraḥ paramaḥ kṛṣṇa, ninu Brahma-saṁhitā. Ekale īśvara. Īśvara o le po Isvara koniyen. Imoye Mayavadi pe Olorun ni gbogbo wa, ko sogbon ninu e. Iranu niyen, Krsna sowipe, Na māṁ prapadyante mūḍhāḥ (BG 7.15). Eyan tio ba teriba si isvara to gaju, Olorun, ele mo wipe mudha loje, asiwere," nitoripe kon sepe gbogbo wa ledi isvara. Kolese se. Koni si itunmo fun Isvara. OLori nitunmo Isvara Kasowipe ninu egbe wa yi. ti gbogbo eyan ba di olori tabi acarya, bawo lesefe toju e? rara. Olori kan gbudo wa. Ilana to wa ninu aye wa niyen. Eyin tele awon oniselu wanyi. Awa o le sowipe "ninu apa oniselu yi nimo wa, afi to ban tele olori kan. Bose ri niyen.

Gege na awon Veda sowipe nityo nityānāṁ cetanaś cetanānām (Kaṭha Upaniṣad 2.2.13). olori kan gbudo wa, Olori to ni amuye kanna, nitya. nita nimi, nitya na ni Krsna je; eda na nimi. Nityo nityānāṁ cetanaś cetanānām. Kini iyato laarin emi ati Krsna? Iyato to wa niwipe nitya meji tabi cetana meji lowa. wan juwe ikan bi eyokan, sugbon ikeji bi nkan to po. Nityo nityānām. nkan to po ni nityanam yi, sugbon ikan soso ni nitya yi. nitya ni Olorun je, ikan soso, sugbon wan ni idari lori. Awa si po. Iyato to wa niyen. Bawo lose nidari lori awon to po yi? Nitoripe eko yo bahūnāṁ vidadhāti kāmān. Nitoripe oun lon fun wa ni gbogbon nkan koseemaani aye yi, nitorina lose je isvara, Krsna loje, Olorun loje. Eni to fun wa ni awon kosemaani, isvara loje, Krsna loje, Olorun loje. Ole yewa pe Krsna lon toju wa, ati kilode to je pe agbudo teriba fun? Otooro niyen.