YO/Prabhupada 0352 - This Literature will Revolutionize the Whole World



Lecture on SB 1.8.20 -- Mayapura, September 30, 1974

Tad-vāg-visargo janatāgha-viplavaḥ. Awon oriki ton ni nibikan tabi ibi ton yin Olorun logo Tad-vāg-visa..., janatāgha-viplavaḥ. Iru ijuwe akosile yi le da iyipada ninu agbaye. Iyipada. Viplavah. Iyipada nitumo Viplavah. Iru viplava wo? gege bi eyi to wa ninu iyipada na, apa oniselu kan ni isegun lori ikeji Oye wa pe iyipada t'oniselu nitumo iyipada yi. awon ironu oniselu kan a si paare ikeji. Nkan ton pe ni iyipada niyen. Gege na iypada ni oro na ni ede geesi, viplava loje ni ede Sanskrit. tad-vāg-visargo janatāgha-viplavaḥ. tawa ba mu awon ijuwe -akosile wanyi jade gege basen se. Alakowe ko ni wa. awa osi ni amuye kankanlati ko awon ijuwe-akosile. orisirisi alebu lowa.. ounkoun toba je. Sugbon asi da iyi pada sile. otooro niyen. Bibeko kilode ti awon alakowe nla sen gba? wan mo pe iwe yi ma ni iyipada ninu agbaye yi. nitoripe ninu awujo awon geesi kosi irun ejo bayi. Kilode towa je nkan iyipada? nitoripe wan gbiyanju lati fun Olorun logo, Kosejo pe eni na fe di olukowe.

Nkan ta gba niyen. Tad-vāg-visargo janatāgha-viplavo yasmin prati-ślokam abaddha... Śloka (SB 1.5.11). Lati ko awon sloka ni Sanskrit, eni na gbud je alakowe giga. awon ofin po gan, kosepe keyan kon ko nkan to ba wun, ade di oriki. Rara. awon ofun teyan gbudo tele po. Lehin na eyan le ko. Gege bi eyin na sen ri, awon mita wa.

tathā paramahaṁsānāṁ
munīnām amalātmanām
bhakti-yoga-vidhānārthaṁ
kathaṁ paśyema hi striyaḥ
(SB 1.8.20)

mita to wa niyen. Gbogbo sloka ni meter. nigban kole tele mita talakoko, sugbon nitoripe wan yin Olorun logo... Nāmāny anantasya. Eledumare ni Ananta je. Awon oruko re wan be. Nitorina Guru Maharaja mi gba/ Oruko Olorun si wanbe bi " Krsna", " Narayan" śṛṇvanti gāyanti gṛṇanti sādhavaḥ. awon eyan mimo nitunmo Sādhavaḥ iru awon ijuwe akosile wanyi, wan o ba de tie ko wan ni ede tio da, ele gba e gbo, nitoripr wan yin Olorun logo.

Ilan to wa niyen. bakana tabi keji ale ni ifarasi Krsna. Mayy āsakta-manāḥ pārtha. Ise soso ta ni leleyi. Kosi nkankan to baje orisirisi sanksrit wa ti awon eyan o le pe dada. Gege bi awa na sen se. Awa o fibe mo. Awon tonn mo ede Sanskrit yi po gan, veda-mantra Awa ofi bee mo. sugbon awan gbiyanju. Sugbon oruko Krsna wa nbe. Nitorina o to fun wa. Oto fun wa