YO/Prabhupada 0361 - They Are My Gurus. I Am Not Their Guru



Lecture on BG 7.3 -- Bombay, March 29, 1971

tawa ba gba ise apinfunni yi, lehin na ni orin kiko, kiko orin Krsna si rorun gan, taba gba gege bi awa se fun awon omo okurin wan yi ni ilana orin kikio yi, wansi ti gba ton ba de sise diedie, toye kan se, wan mani oye Krsna. Teyin ba wo dada ema ri awon to ni ilosiwaju gan ton jo, ele ri fun ara yin, aduro oye ton ni nipa Krsna. Eto to rorun gan, awa o da enikankan duro: Ewo o kin se Hindu. Ma korin Hare Krsan." rara. Yei kṛṣṇa-tattva-vettā sei guru haya (CC Madhya 8.128). kosi nkan to baje toba tie je Hindu tabi Musulman tabi Kristiani, teyi tabi tooun Eyan gbudo ko Sayeni Krsna yi, Bhagavad-gita boseje. Lehin na asi di Oluko mimo. awon omo oukrin at'obirin yi ton sese fe rawon, mofe ran wan losi Australia. Okurin na lati Australia loti wa, obirin na wa lati Sweden nisin wanti fe ara wan. Wan lo sise ni ile-ijosin wa ni Sydney. Lehin ijo meji si meta wan ma lo. wan toju ile-ijosin wa, wan si sewaasu. Egbe imlye Krsna wa yi tin fe si, pelu iranlowo wan. Emi nikan nimo wa sugbon wan ranmilowo. Awon ni guru mi. Emi koni guru wan ( Atewo) nitoripe wan ranmilowo lati sise Guru Maharaja mi Gege na nkan to da gan niwipe eyan losi Australia, Enikan losi Fiji Island, elomi nlo si Hong Kong, elomi nl si Czechoslovakia. asi fe wa basele losi Russia na. Aye die si wa lati wonu China na, asin gbiyanju. Ati ran awon omo-okurin meji losi Pakistan - Ikan ni Dacca ati ikan ni Karachi (atewo)

Awon omo- okurin wanyi lati America, wan ranmilowo. O si dun mi pe awon omo-ilu India osi fe wa ranmilowo, wan wa na sugbon wan o five po. Oye kan wa, awon ton kere, e parapo ninu egbe wa, kesi ti imoye Krsna yi si gbogbo agbaye. Ise India niyen. Caitanya Mahāprabhu sowipe,

bhārata-bhūmite haila manuṣya-janma yāra
janma sārthaka kari' kara para-upakāra
(CC Adi 9.41)

Ise para-upakara loje, ise iranlowo lati pin imoye Krsna fun gbogbo agbaye, ni ise to se pataki ju lasiko tawayi. Asi jeki gbogbo wa jo wapo lori eto, onisel, awujo, asa, esin, gbogbo nkan. Krsna. Krsna lowa laarin gbogbo eleyi. Otooro to wa niyen. On lonsiwaju. taba si gbiyanju si, asi losiwaju si.