YO/Prabhupada 0367 - Vrndavana Means that Krishna Is the Center



Lecture on BG 7.1 -- Bombay, December 20, 1975

Krsna fun ara re n'ko wa ni Bhagavad-gita k'awa baa le ni oye nipa re, gege na agbudo mu eto yi ni pataki, bibeko awa ma lo ara eda ta ni yi ni ilokulo. Fun awaon aja ati ologbo ko ni Krsna wa fun ni oro Bhagavad-gita. fun awon eyan to se pataki ju lo wa fun, imaṁ rājarṣayo viduḥ. fun awon rājarṣi, awon olowo, awon ton l'ola, sugbon ton niwa mimo. Teletele rājarṣi ni awon oba je. Rāja ati ṛṣi wa papo. gege na Bhagavad-gita o kin se fun awon oniranu. Fun awon eyan to se pataki ju ninu awujo wa lowa fun: yad yad ācarati śreṣṭhas tat tad evetaro janaḥ (BG 3.21). Awon eyan ton p'ara wan ni Olori awujo, wan gbudo ko nipa Bhagavad-gita, bi wan sele di olori to daju, lehin na ni awujo wa ma niyi. t'awa ba tele ilana Bhagavd-gita ati Krsna, lehin na gbogbo isoro wa ma tan. Kon se nkan awon elesin nikan tabi nkan afori ro. Baayi ko loje. Sayensi loje - sayensi awujo, sayensi oniselu, sayensi asa. Gbogbo nkan lo wa nbe.

ibeere wa ni ki gbogbo yin di guru. Ase Caitanya Mahaprabhu niyen. O fe ki gbogbo ryan di guru. Bawo O ti salaaye:

yāre dekha tāre kaha 'kṛṣṇa'-upadeśa
āmāra ājñāya guru hañā tāra' ei deśa
(CC Madhya 7.128)

guru niyen. Kasowipe eyin pelu ninu ebi kan. awon eda to po, awon omo-okurin yin, awon omo-obirin, aya oo-eni tabi awon omode, eti di guru fun wan niyen. Gege bayi e le joko ni irole ke soro nipa Bhagavad-gita, yāre dekha tāre kaha kṛṣṇa-upadeśa (CC Madhya 7.128). Eyin o gbudo da nkankan si le. Ilana ti wa n'be; teba tun awon oro yi so kon gbo - eyin ti di guru niyen. Kole rara. Iwaasu wa niyen. kon sepe awa nikan lafe di guru, sugbon awa fe se'waasu to jepe, gbogbo, awon olori-ile, tabi awon okurin lasan, le di guru nibi ton wa. Enikeni lese. Eni to tie je eyan lasan, oun na ni awon ebi re, ati awon ore, tobatie jepe alaimowe loje, o le gbo ilana Krsna, a de se'waasu gege bose gbo. Nkan ta fe niyen. Awa de fe ki gbogbo awon okurin jeje, awon Olori, wa ko eto yi. O rorun gan: man-manā bhava mad-bhakto mad-yājī māṁ namaskuru (BG 18.65), Toba de pin ase Krsna yi, O ti p'ase pe, mām evaiṣyasi, E ma pada simi." Yad gatvā na nivartante tad dhāma paramaṁ mama (BG 15.6). Tyaktvā dehaṁ punar janma naiti mām eti kaunteya (BG 4.9). Nkan to rorun gan.

Ibeere sos tani niwipe, ki awon Olori awujo wa yi kon gba eto Bhagavad-gita yi nipataki, kon keko, konsi ko awon eyan Egbe imoye Krsna wa niyen. ko le rara; nkan to roun gan niyen. enikeni le se. sugbon eri to wa niwipe, lesekese ti awon eyan ba ni oye nipa Krsna, janma karma ca me divyaṁ yo jānāti tattvataḥ (BG 4.9), enikeni toba nipa Krsna, eri to wa ni wipe tyaktvā dehaṁ punar janma naiti... lehin igba toba f'ara yi sile koni gba ara imi laye yi. A gbada si ijoba orun lati gbadun pelu Krsna ni awujo re. Vrndavan niyen. Gopījana-vallabha. Kṛṣṇa... Kṛṣṇa, Itumo Vṛndāvana niwipe Krsna lowa laarin gbogbo nkan. oun l'eni ti gbogbo eyan feran. Awon gopi, awon Oluso maalu, awon omo maalu, awon igi, awon eso, awon idodo, baba, iya - gbogbo eyan loni ifara si Krsna. Vrndavana niyen. Ajora re leleyi, Vrndavana niyen, sugbon Vrndavana gidi si wa. Eleyi na daju. Ni eto emi kosi'yato.

sugbon ko bale ye wa, Vrndavana tala koko wa,

cintāmaṇi-prakara-sadmasu kalpa-vṛkṣa-
lakṣāvṛteṣu surabhīr abhipālayantam
lakṣmī-sahasra-śata-sambhrama-sevyamānaṁ
govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ bhajāmi
(Bs. 5.29)
veṇuṁ kvaṇantam aravinda-dalāyatākṣaṁ
barhāvataṁsam asitāmbuda-sundarāṅgam
kandarpa-koṭi-kamanīya-viśeṣa-śobhaṁ
govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ bhajāmi
(Bs. 5.30)

Ijuwe Goloka Vṛndāvana leleyi.