YO/Prabhupada 0368 - You are Foolishly Thinking that you are Not Eternal



Morning Walk -- January 3, 1976, Nellore

Prabhupāda: Awujo nipa imoye ati esin leleyi, mo robe. Huh? Idanimo. Tabi egbe Ramakrishna. Acyutānanda: Rara, Ologun Igbala. Prabhupada: Ologun Igbala, oh. Harikeśa: Ni otooro awa nikan soso ni ologun igbala to wa. (Isinmi) Acyutānanda: ... Olori fun olori. Awa ti gba oludari re, sugbon lati nkan toti ri ni iriri re tin wa, nkan to jepe.. Prabhupada: Awa o le gba iru olori bayi, ton gba iriri lati awon elomi. Awa ma gba oolori toje.. Keśavalāl Trivedi: to ni'iriri. Prabhupada: Lesekese. Parāsya bhaktir vividhaiva śruyate svabhāvikī jñāna-bala-kriyā ca. Svabhāva, ... Teba bimi besele sen nkan, tin ba sowipe, "Beeni, se bayi," svabhaviki. Moti ni oye bimosele se dada. Nkan ton sele niyen. Mayādhyakṣeṇa prakṛtiḥ sūyate sa-carācaram (BG 9.10). Krsna n'salaaye fun wa pe " E se bayi." Gege na e ma riwipe , gbogbo nkan lo dada. Lati eso dongoyaro ni igi na mati jade. Krsna ti seto gbogbo nkan dada - bījo 'haṁ sarva-bhūtānām (BG 7.10), nkan toma jade niyen, igi mangoro o ni jade. Awon kemika ton wa ninu re ti wa bayi, eyin gan o le mo nkan to wa ninu re, eso kekere, baṭa vṛkṣa. Igi banyan loma jade, kon se igi imi. Imoye niyen je. O ti fi gbogbo nkan yi ninu eso kekere. Nitorina ni Krsna se sowipe, bījo 'haṁ sarva-bhūtānām. Kosi asise kankan ninu e. E mu ke gbin. E ma ri ibajade towa ninu re. Acyutānanda: Ilana to wa lehin idi ton jeki awon irugbin hu, wanti salaaye ninu Īśopaniṣad pe, so 'ham asmi: " Emi l'ofin yi." Īśopaniṣad ti salaaye ninu sloka to gaju, so 'ham asmi: " Emi niyen." Prabhupada: Itumo Asmi niwipe " Agbara mi niyen Agbara mi niyen" Acyutananda: Rara, o sowipe.. Prabhupada: Tin ba sowipe " ISKCON nimi," kilo buru? Nitoripe emi ni mo daale; nitorina tin ba sowipe, " Itumo ISKCON ni emi. Emi ni ISKCON." Kilo buru? Bose ri niyen. Pelu agbara Krsna ni gbogbo nkan jade. Nitorina lonse sowipe, " Emi leleyi, emi leleyi, emi leleyi." Vibhūti-bhinnam. Nitoripe gbogbo nkan.... Janmādy asya yataḥ (SB 1.1.1). Lati Krsna ni gbogbo nkan tin wa. Acyutananda: rara, Isopanisad sowipe eyin ni ofin yi. Isopanisad sowipe ofin to wa lehin ina orun, pe " Emi l'ofin yi. Prabhupada: Beeni, awon elesin ma gba.. awa na gbabe. Acyutananda: Eda ton jeki Orun ra, emi l'eda yi. " Prabhupada: Ko yemi. Acyutananda: So'ham asmi. merindin-logun.. Harikesa: " gege bi orun se je, leemi." Prabhupada: Beeni, so'ham asmi - nitoripe nkankan nimoje . Acyutananda: Rara, sugbon o sowipe " Emi leleyi, " nkankana nimoje." Prabhupada: rara. Ton ba sobe, a gbabe, nitoripe amuye kanna lani. Keśavalāl Trivedi: amuye, iyato to po. Prabhupada: Beeni. Prabhupada: tin ba sowipe, " Omo-ilu India nimi," kilo buru, tin ba sowipe " omo-ilu India nimi? Acyutananda: Nkan toyato niyen. Prabhupada: Beeni. Nkan to yato ko. Acyutananda: Sugbon taba fe gba nkan ti sruti so, o siwipe ofin kanna leje. Prabhupada: Nitorina egbudo ko lati guru. sugbon teba gbabe, ode le je niyen. Nitorina leyin se ni lati gba guru. Ilana ti sruti ti fun wa niyen. Tad-vijñānārthaṁ sa gurum evābhigacchet (MU 1.2.12). Egbudo keko awon sruti. Egbudo losodo guru. Acyutananda: Rara,sugbon leyin iyen leleyi. Ofin to daju ninu Upanisad, sruti, awon oludari, niwipe nkankanna leje pelu ofin yi. Prabhupada: Beeni, Nkankan nimi pelu ofin yi. Nityo nityānām. Acyutananda: Kosi nkan tole peju nkan towa layeraye. Prabhupada: Gbogbo nkan wa fun ayeraye. Acyutananda: Idamu wa niyen. Nityo nityanānāṁ. Eyin o le sowipe awon nkan to wa fun ayeraye ma peju nkan imi to wa fun ayeraye. Prabhupada: Rara, rara. Nkan tin mon so ko niyen. Alail'opin ni gbogbo wa. Acyutananda: Bawo nikan se wa je t'ayeraye ju ikejo lo... Prabhupada: gege bi Olorun se je alailopin, gege na leyin se je. nitoripe eyin tini ara eda, eyi rowipe eyin ma lopin. Bibeko, gege bi Olorun se je alailopin, beena leyin seje. Acyutananda: Kilode ta sen se iyasoto laarin awon meejeji tobajepe awon mejeeji o lopin? Prabhupada: Gege bi orun se yato si ina re, sugbon ina at'oru si wan'be. Sugbon eyin o le sowipe nitoripe ina orun wa, orun na wa. Eyin o le sobe. Mat-sthāni sarva-bhūtāni nāhaṁ teṣv avasthitaḥ (BG 9.4). Wanti salaaey. Keśavalāl Trivedi: Swamiji, moro wipe, eti salaaye ode yemi, pe isa nimi, sugbon sarvesa ko nimi. Atman nimi sugbon Paramatman ko nimi." amsa nimi sugbon Paramamsa ko nimi." Prabhupada: Beeni. Wanti salaaye bayi nimbo mi... Īśvaraḥ paramaḥ kṛṣṇaḥ (Bs. 5.1). Īśvaraḥ na nimi. Moti salaaye aimoye igba. Sugbon iyen o wipe paramesvara nimi. Krsna ni Pramesvara. Ile wo leleyi? Keśavalāl Trivedi: Ahaṁ brahmāsmi, oro yi o ye titi d'ojo ti mo gbo nigbati swamiji salaaye, ni ojo kini Rajeswara ni Mandapur. O si daju. Bibeko awon Mayavadi..., " O daa Śaṅkarācārya na sowipe, ahaṁ brahmāsmi. Kilode teyin se sowipe rara?" Nitoripe opolopo awon eyan ti bimi leere, mio de le daaun. Sugbon bese salaaye nipa mukti, beeni, ninu ojogbon yin, ati isa, sarvesa, gbogbo awon nkan wanyi - tmā, Paramātmā, aṁśa, Paramāṁśa - moti riwipe eyan le saalaye. nitoripe awon eyan to po man beere, bi awon ni "Lions Club, wan beere ibi ton le ko nipa awon oro yi. mi o le daaun. sugbon nisin mole salaaye fun wan. Prabhupada: Nkan ti mo salaaye so daa? Keśavalāl Trivedi: Beeni, nkan ti mo ro niyen. mode rowipe o si daaun si ibeere Acyutananda Swami no. Nkan ti mo ro niyen. Acyutananda: Rara, Mo kan dake. Keśavalāl Trivedi: rara, rara.. otan... Acyutananda: Iyen wipe Durga lagbara ju Visnu lo, nitoripe oun lo ji Visnu ninu yoga-nidra lati le pa Madhu ati Kaitabha. Iyen wipe o ni idari lori Visnu. Prabhuapada: Beeni Tin ba bere lowo iranse mi " Ji mi ti ago mesan ba lu, se iyen wipe.... (erin)