YO/Prabhupada 0372 - The Purport to Anadi Karama Phale



Anadi Karama Phale and Purport - Los Angeles

Anādi karama-phale. Anādi karama-phale pori' bhavārṇava-jale taribāre nā dekhi upāya. orin Bhaktivinoda Ṭhākura leleyi, ton soro nipa awon eda aye yi. Wan so nibi, Bhaktivinoda Ṭhākura sowipe, on salaaye nipa ara re biwipe eda lasan loje, pelu awon ise ti mose leyin, moti bosinu odo ile aye yi, mio si ri ona kankan lati jade ninu odo yi. O dabi odo majele, e viṣaya-halāhale, divā-niśi hiyā jvale. gege, teyan ba je awon ounje toti baje, asi jo wan lokan, gege na awan gbiyanju lati gbadun ara wa, niotooro, iriri toyato lon mu jade, on jo wa l'okan. E viṣaya-halāhale, divā-niśi hiyā jvale, ina ton jo wa yi, sin jo wa lo ni gbogbo igba. Mana kabhu sukha nāhi pāya, nitorina okan mi o ni itelorun rara. Āśā-pāśa-śata-śata kleśa dey abirata, Nigbogbo igba nimon s'eto to po gan, bi mo sefe ni idunnu, sugbon gbogbo wan lon funmi ni isoro, fun wakati merin-le logun.

Pravṛtti-ūrmira tāhe khelā, gege bi awon igbi odo, ton lon lati ibi kan sikeji, ipo mi niyen. Kāma-krodha-ādi caya, bāṭapāre dey bhaya, pelu na, awon ole ati odaran to po gan wa. nipataki wan to mefa, ifẹkufẹ, ibinnu, ilara, aimokan, ni ona to po gan, wan si wa, mo sin beru gbogbo wan. Abasāna hoilo āsi' belā, bayi ile aye mi ma ni ilosiwaju, tabi motin wa si ipaari. Jñāna-karma ṭhaga dui, more pratāriyā loi, ipo mi leleyi, awon ise meji lo wa, awon eto ori-riro ati awon ise pelu ijere, wan tanmi je. Jñāna-karma ṭhaga, enito feran lati yan awon eyan je nitumo ṭhaga. jñāna-karma ṭhaga dui, more pratāriyā loi lon je, wan fi ona tioda fi han mi, abaśeṣe fele sindhu-jale, lehin igba ton ba yanmije tan, wan mu mi wa sori eti-odo, wan si ti mi sinu odeo. E heno samaye bandhu, tumi kṛṣṇa kṛpā-sindhu, lehin gbogbo nkan wanyi, Krsna mi, Eyin ni ore kan soso timoni, tumi kṛṣṇa kṛpā-sindhu. Kṛpā kori' tolo more bale, nisin mio lagbara kankan lati jade ninu odo okunkun yi, ibeere mi niwipe, mosi fe gbadura si yin, pe pelu agbara yin, e le mu mi duro. Patita-kiṅkare dhari' pāda-padma-dhūli kori', Iranse yin nimo je. Bakanna tabi ikeji, moti subu ninu odo yi, ele mu mi jade, kesi fi mi segbe yin. Deho bhaktivinoda āśraya, Bhaktivinoda Ṭhākura ti sowipe "E fi mi segbe yin." Āmi tava nitya-dāsa, nisin mole di iranse yin. Bhuliyā māyāra pāś, bakanna tabi ikeji moti gbagbe yin, moti bosinu iho maya. Baddha ho'ye āchi doyāmoy, Olorun mi, moti bosinu isoro yi. E daakun e ranmi lowo.