YO/Prabhupada 0373 - The Purport to Bhajahu Re Mana
Purport to Bhajahu Re Mana -- The Cooperation of Our Mind
Bhajahū re mana śrī-nanda-nandana-abhaya caraṇāravinda re. orin Govinda dāsa leleyi, akewi Govinda dāsa. On ma okan ara re soro, nitoripe, lehin gbogbo nkan, agbudo sise pelu okan wa. ti okan wa o ba ni ifokan bale, ti okan wa ban mu wa losinu awon nkan toyato, a soro gan lati le gbokan le ise nkan. Nkan to wa niyen Nitorina itumo ilana yoga ni wipe afe ni idari lori okan wa. Ona to daju lati ni idari lori okan leleyi. Nitoripe lai ni idari lori okan wa, lai ni idari lori okan wa, koseni tole ni ilosiwaju ninu eto emi. ilana Vaisnava ni wipe agbudo fi okan wa ninu ise fun Oluwa, bayi kole lo kuro ninu ise ifarasi Olorun. Ilana wa niyen. Nkan tose se niyen. tawa ba gbokan le Krsna, arcanam- śravaṇaṁ kīrtanaṁ viṣṇoḥ, smaraṇaṁ pāda-sevanam (SB 7.5.23). Pāda-sevanam, lesekese loma ni idari lori okan re. awon yogi sin gbiyanu lati ni idari lori okan wa, sugbon wan o le se. Ni opolopo igba ni awon yogi giga wanyi ti wo lule. gege na ounkooun toba je eke teyan base, kosi besele se dada. Nitorina ni ilana lati ni idari lori okan a si fun yin okan yin ni ise to da ju, lehin na okan wa o leni ifarasi awon agabra kekere mo. Sayensi tabi asiri leyin ilosiwaju wa niyen. gege na Govinda dāsa fe fi okan re sori Krsna, ton pe ni abhaya-carana. "Laisi iberu" nitumo Abhaya. Bi awa na sen fo'wo wa si ile-owo to daju, nitoripe a rowipe kole si ipadanu. Nkan ton pe ni abhaya niyen, "laisi iberu," ese nitumo carana.
Givinda dasa sin ba okan re wi, hū re mana " Okan mi," hu re; on ba okan re wi. Bhaja hū re mana. Bhaja. Ton sise ifarasi Oluwa nitumo Bhaja." Bhaja hū re mana śrī-nanda-nandana, " ninu ise Krsna, omo Nanda." Krsna to po gan wa, sugbon yi lawa fe soro nipa to wa bi omo Nanda Maharaja ati bi omo Vasudeva. Nitorina on sowipe... basele da awon eyan m, pelu oruko re, oruko baba re, bayi idanimo to daju loje. Gege na, toba sowipe śrī nanda-nandana; bhajahū re mana śrī-nanda-nandana abhaya-caraṇāravinda re, " A le ni idabobo labe re." Awon sloka nipa eto yi po gan ninu Bhāgavatam: Samāśritā ye pada-pallava-plavam mahat-padaṁ puṇya-yaśo murāreḥ. Mahat-padam, "Gbogbo agbaye yi wa labe ese Krsna," Ti gbogbo agbaye yi ba le sinmi, tinba je eda to kere gan, tinba si ni idaboo labe Krsna, tio niberu, bayi o dami loju pe aabo mi daju. Bhajahū re mana śrī-nanda-nandana, abhaya caraṇā-ravinda re, durlabha mānava-janama sat-saṅge, taroho e bhava-sindhu re. Durlabha, " lati l'ara eda eyan yi nkan to le gan loje.." Durlabha mānava-janama. Lati le f'okan wa sori Krsna, O se pataki pe ka gbe pelu awon elesin. Durlabha mānava-janama sat-saṅge. " awujo awon elesin" nitumo Sat-saṅge tawa o ba gbe pelu awon elesin, Tawa ba fe f'okan wa le Krsna fun ara re wa, kolese se, kolese se. O ma kuna. Nitorina lose sowiep sat-saṅge, " ninu awujo awon elesin." Taroho e bhava-sindhu re, "ipinnu aye yi ni wipe agbudo so koja odo aye yi." Gege na tawa ba gbokan wa le Krsna ninu awujo awon elesein, a le soda odo ile-aye yi, igbese aye yi. Lehin na , kini ise ti mon se nisin? Nisin ise ti monse ni: śīta ātapa bāta bariṣaṇa, e dina jāminī jāgi re. Ise mi ninu aye yi niwipe mi oni idamu nipa otutu, tabi oru gbigbona, Mio ni idamu nipa sisun lale; mon sise lat'aro d'aale." Śīta ātapa bāta bariṣaṇa, e dina jāminī jāgi re. Kini id fun? Kṛpaṇa, bhipale sevinu kṛpaṇa durajana, "fun ise kṛpaṇa dura-jana." fun awon ara'ta nitumo Kṛpaṇa. Awon awujo aye yi, awon ore, ife, gbogbo nkan bayi, ara'ta ni wan je. Kosi bonsele funmi ni ilosiwaju ninu eto mimi aye mi. sugbon awa sini'se pelu awujo, ore, ife, orile-ede, bayi bayi lo. awon nkan tan se po gan, sugbon biphale niyen. Itumo Biphale niwipe " Laisi iriri." Iriri to wa niwipe mofe da irori kan sile, lati fun awon orile-ede, awujo, ebi wanyi ni'daabo, lehin na ti asiko iku baade, masi gba ara to dabi ironu mi. Awon eyan sin se orisiris awon nkan tio da lati le ma sise awujo, ore, ati ife. Ibajede to wa n'be niwipe on da ironu sile tio da bi teyan mo, iriri to wa niwipe ni aye atun wa fun, asi ni ara tojo iru ironu toni. Nitorina kṛpaṇa durajana. "Alaahun" itumo Kṛpaṇa. Kosi bonsele funmi l'ogbon kankan nipa awon nkan timofe ninu aye yi, sugbon awa si wa nninu ise durajan yi, " ara'ta." Biphale sevinu kṛpaṇa durajana, capala sukha-laba lāgi' re, lehin na a le ni idunnu die. Bibeko, bawo ni Okurin sele sise tole lat'aro daale. Imo ako ati abo ni idunnu to wa n'be, capala, "baibai." Vidyapati ti korin, tatala saikate vari bindu-sama, " Idunnu yi daabi omi ninu ile gbigbe." Kos'omi ni ile-gbigbe, sugbon teba wan omi lori ile na, te sowipe " Nisin m'omi na," kini iwulo iru omi bayi? Gege na awa sin wa idunnu t'ayeraye, kini awon awujo, ore ati ife fe fun wa? Nitorina awa kan lo asiko wa nilokulo pe awa fewa idunnu lati ile-aye yi, an toju awujo, ore ati bayi bayi lo, ilokulo. Biphale. Itunmo Biphale " laisi iriri to da fun." Biphale sevinu kṛpaṇa durajana, capala sukha-laba lāgi' re. " Ko buru, ma gbadun fun ara mi. mosi wa l'ododo, mosi le pawo, mi o si niyi kankan fun ebi mi." Niotooro nkan ton sele lasiko tawayi leleyi. Koseni to femo nipa ebi sugbon wan s'eto ara wan, wan gbadun idodo aye wan, ati bayi bayi lo. Govinda Dāsa, akewi yi sin ba okan re wi, " Okan mi, mo mowipe nisin osi wa l'ododo, ati pe mosi le gbadun." Nitorina, lonse sowipe e dhana yaubana putra parijana, ithe ki āche paratīti re, "akojo gbogbo owo yi; ati aye idodo yi: igbadun." E dhana yaubana putra parijana, pelu awujo, ore ati ife, se idunnu kankan wa, tabi idunnu mimo? Ithe ki āche paratīti re. "O da bi omi lori ododo." Kamala-dala-jala, jīvana ṭalamala. "Fun igba die l'omi yi ma wa fun, o le jabo sile nigba die." Niotooro gbogbo idodo wa yi ati awon ise lati fi pa owo, lasiko die o le tan. gege na ema gbokan le iru awon igbagbo bayi. Eleyi o da nitoripe o le tan ni eyikeyi asiko. awon eyan yi fe ko ile giga, tabi kon ni owo repete ni'le owo, tabi kon ni oko lati wa kaakiri, ati orisirisi nkan ton fe gbadun, sugbon wan ti gbagbe pe l'eyikeyi asiko o le paari. L'eyikeyi asiko. O da bi kamala-dala-jala, " omi lori ewe." Kole duro, l'eyikeyi asiko o le ro sile. Apeere to da leleyi. Nitorina lo sen fun wa ni imoran, śravaṇa kīrtana, on salaaye fun okan wa wipe, " mase bayi, mase bayi," awon nkan tio da to po. Ibeere to wa niwipe, Okan re a beere lowo Govinda Dasa, " Kilo fe kin se nisin? Oti sowipe gbogbo nkan ile aye yi o da, kilo wa fe kin se? O sowipe, " Beeni, nkan timo fe ko se leleyi: śravaṇa kīrtana smaraṇa vandana, pāda-sevana dāsya re, pūjana sakhī-jana ātma-nivedana, govinda dāsa-abhilāṣa re." "Okan mi, nkan timo fe niwipe, ko ranmilowo lati gbo nipa abhaya-caraṇāravinda, Kṛṣṇa, śravaṇa. kin baa le korin nipa ogo re, śravaṇa kīrtana. jekin ranti, jekin le sise fun, jeki le d'ore pelu re. Jekin le fun ni gbogbo nkan timo ni. Awon ibeere mi niyen. toba ranmilowo, mole se." Orin to da gan leleyi, to le kowa leeko, nipa igbese aye eda, enikeni toba tele awon ofin wanyi, inu re asi dun.