YO/Prabhupada 0383 - The Purport to Gaura Pahu



Purport to Gaura Pahu -- Los Angeles, January 10, 1969

Gaura pahū nā bhajiyā goinu, prema-rathana-dhana helāya hārāiṅu. Orin imi lati Narottama dasa Thakura leleyi. O sowipe " Moti wa iku mi fun ara mi nitoripe mi o s'adura si Olorun Caitanya." Gaura pahū nā bhajiyā goinu. Olorun Caitanya nitumo Gaura pahu Na bhajiya, " Lai s'adura." Goinu, " Moti se iku lalejo." adhane yatane kari dhanu tainu. " Kilode ti mose pe iku? Nitoripe mon se nkan iranu mode ti fi ipinnu aye yi segbe." Awon nkan iranu nitumo Adhana. awon nkan gidi ni dhana. Niotooro gbogbo wa lan ti ilosiwaju wa ninu eto mimo segbe kan, asin s'eto igbadun aye yi, nitorina lose le lati lo ara ede yi, fi gunke lori ipo mimo. Ara eda yi si je nkan ton fun awon emi ninu aye yi latile l'aaye fun eto mimo. beena awon eyan tio ba foju si ilosiwaju ninu eto mimo, eyan na fe se iku lalejo. itumo iku mimo yi niwipe ati gbagbe ara wa, pe emi laje. Iku mimo leleyi. Ninu ara awon eranko, wanti gbagbe tan. kosi besele ran wan leti pe wa yato si ara wan, pe ara yi ko lonje. ninu ara eda eyan nikan lowa, eyan le mo wipe, ara re koloje, emi loje. teyan ba korin Hare Krsna, ole ni oye nipa oro yi, teyan ba si s'adura si Olorun Caitanya, to tele awon ofin re eyan le korin Hare Krsna, lehin na asi wa sori ipo imoye yi. Sugbon Narottama dasa Thakura sin soro fun wa pe awan fi eto yi segbe kan. nitorina awa pe iku mimo yi.

Lehin na o sowipe prema-rathana-dhana helāya hārāiṅu. Itumo ile aye mimo niwipe agbudo ni ife gidi. Gbogbo eyan lon soro nipa ife. Awon aami idayato to po wa ton so " ife, ife." Sugbon kosi ife kankan. Aimokan leleyi. Ifekufe loje. Ife fun oti mimu, ife fun imo ako ati abo, ife fun nkan bayi bayi... nkan to n sele niyen. Kosi besele salaaye nipa ife lais fi Krsna, tabi Olorun si. Nitoripe idi ton se da wa niyen. Lati nife Krsna. Nkan ta fe niyen. Ife mimo leleyi. prema-rathana. Mole ni ipo mimo yi, sugbon moti ti segbe kan. Nitorina mon pe iku mimo yi. awon nkan wanyi n'sele nitori awon iwa mi toti koja. Gbogbo wa tani ara eda yi, nitori awon isekuse tati se tele. Nigbami awon iwa rire. Sugbon teyan ba ni ara yi, kosejo nkan to da. Awon iwa rire o ni fun wa l'ara eda yi. Iwa rire niyen. Bibeko, o ye koye wa pe Brahma gan, toje Olori gbogbo awon eda ninu agbaye yi, sini odun aye to po gan, iwa kuwa niyen je, nitoripe oun gan si ni ara eda. nitorin awon iwa iranu tati se, awa sin lole die die. Ninu Bhagavata wanti salaaye pe awon eyan o mo, pe pelu gbogbo igbadun tonse yi, wansi ni ara imi. ara eda wa n'idi fun isoro aye yi Nitoripe mo ni ara eda yi nitorina ni ori fifo se wa, inu riro. Ati awon nkan bayi bayi lo. sugbon lesekese tawa ba kuro ninu ara eda yi, koni sejo isoro aye yi. Idunnu nikan lowa. Brahma-bhūtaḥ prasannātmā (BG 18.54). Idunnu nitumo Prasannātmā, lesekese teyan ba ni aye mimo. nitori awon iwa mi, moti lo anfani yi ni ilokulo Apana kara mada seva..

Kilon sele? Sat-saṅga chāḍi khainu asatyera vilāsa. " Moti fi akojopo awon elesin sile, sugbon mo tini asepo pelu awon oniranu okurin." Asatyera. Asat ati sat. Emi nitumo Sat. oun elo nitumo asat. beena itumo asepo pelu awon nkan aye yi niwipe eyan ma wonu ile aye yi si. Beena eyan gbudo ni aasepo pelu awon elesin. Satāṁ prasaṅgād mama vīrya-saṁvido. Eyan ko nipa Olorun ninu akojo awon elesin re. Nitorina lawa sen ti egbe imoye Krsna yi siwaju. Eyin na ma riwipe awon eyan toba ni asepo pelu wa fun ose die, oju wan ma la, wansi beere fun itebomi lati le ni ilosiwanu si. Asepo yi se pataki gan. Awon ton si awon ile-adura yi, oye kan je awon eyan ton daju, nitoripe lori iwa wan ni gbogbo nkan wa. Ti awon eyan o ba ni oto lenu, kole sise. Awon eyan lewa ni asepo pelu wa, sugbon t'awa o ba ni oto lenu, kole sise. Sugbon awon eyan pipe ni awon elesin je, enikeni toba ni asepo pelu awon elesin loma yipada. Asiri to wa niyen. Sat-saṅga chāḍi asatyera vilāsa. sugbon lesekese ti awon eyanyi ba fi akojopo awon elesin sile, maya ma dimu. Lesekese t'awa ba fi akojopo yi sile, maya masowipe " Beeni, wa bami." Koseni tole wa fun ara re, lai ni asepo pelu awon elomi. Kolese se. Ogbudo ni asepo pelu maya tabi Krsna. Beena gbogbo eyan ni lati ni asepo pelu awon elesin, pelu Krsna.

Itumo Krsna... T'awa ban soro nipa Krsna, pelu awon elesin niyen. Nitoripe Krsna o le wa fun ara re. Krsna wa pelu Radharani. Radharani wa pelu awon gopi. Krsna si wa pelu awon oluso maalu. Alainigba gbo ko ni wa. Awa o le ri Krsna nikan. Beena, itumo Krsna niwipe Krsna wa pelu awon elesin re. Beena itumo imoye Krsna niwipe agbudo ni asepo pelu awon elesin Krsna. Viṣaya viṣama viṣa satata khāinu. o sowipe " moti mu mejele lati igbadun." Viṣaya viṣama viṣa. igbadun nitumo Visaya. Jije, sisun, imo ako ati abo, ati igbeja. Nkan ton pe ni visaya niyen. Alebu nitumo visama. Majele nitumo visa. Teyan ba kan se awon nkan merin wanyi, gege bi awon eranko. O dabi eni ton mu majele. Otan. Viṣaya viṣama satata khāinu. "Mo mope majel leleyi, sugbon mosin mu, mosin mu majele yi nigbogbo igba." Gaura-kīrtana-rase magana nā painu. "Mio sile wonu egbe sankirtana ti Olorun Caitanya ti daale." Oh, otooro niyen. Awon ryan ton nife nkan aye yi, tabi ton mu majele igbadun, kosi bonsele ni ifarasi egbe sankirtana yi.

Ni ioaari Narottama dasa Thakura si sukun. Sugbon on sojuawon eda. Teyan ba wa sori ipo ibanuje yi, osi da gan. Lesekese lo ma ya si mimo. Iyasi mimo nitumo ibanuje yi. beena o sowipe, keno vā āchaya prāṇa kichu bali... kilode ti mose wa laaye yi? Mio ni asepo pelu awon elesein, mio ni asepo pelu egbe sankirtana yi. Nio mo nkan ti Krsna je. Mio ni oye nipa Caitanya. Kilode ti mo se wa laaye? Ekun to wa niyen. Kini idunnu mi? Kini ipo idunnu mi? Kinidi fun ile aye yi?" Narottama dāsa kena nā gela. "Kilode ti mio se ku nigbato pe? Oye kin ti ku . Kin itumo aye mi?" Beena ekun Narottama dāsa Ṭhākura niyen. Gbogbo wa gbudo ronu bayi pe " Ti awa o bale wonu akojopo awon elesin, t'awa o bal ni oye nipa imoye egbe Krsna yi, t'awa o ba le ni oye nipa Olorun Caitanya ati awon elesin re, o si da ju pe kin ku. Ko s'ona mi."