YO/Prabhupada 0384 - The Purport to Gauranga Bolite Habe
Purport to Gauranga Bolite Habe -- Los Angeles, January 5, 1969
Narottama dāsa Ṭhākura lo korin yi. O sowipe, " Igba wo ni igba yen ma wa, pe mole korin oruko Oluwa Caitanya, igba wo ni ara mi a gbon bayi? Gaurāṅga bolite habe pulaka-śarīra.GBigbon ara nitumo Pulaka-śarīra. Tryan ba wa lori ipo mimo to ga, nigbami aami mejo lowa: bi ekun, keyan a sori bi were, ki ara wa magbon, keyan ma jo lai wo awon eyan imi... awon aami wanyi ma wa fun ara wan, ko kin se nkan teyan lese pelu eke. Gege na Narottama dāsa Ṭhākura sin duro de ijo na, kon sepe keyan ma farawe awonn ton tide ipo yi. Koye ka sebayi. O sowipe, " Igbawo ni ijo na ma de, toje pe tinba p'oruko Oluwa Caitanya, gbogob ara mi magbon?" Gaurāṅga bolite habe pulaka-śarīra. Ati hari hari bolite: " Ati wipe lesekese tinba p'oruko 'Hari Hari', tabi 'Hare Krsna," ekub ma jade latinu oju mi." Hari hari bolite nayane ba'be nīra. Omi nitumo Nīra. Beena Caitanya Mahaprabhu sowipe "Igbawo ni asiko na ma de?" Oyeka gbiynaju fun ojo na. Sugbon ti pelu ore-ofe Krsna, ale de ipo yi, awon aami wanyi ma de lesekese. sugbon Narottama dāsa Ṭhākura sowipe kolese se, lati de ipo yi lai ni igbala lowo awon nkan ile aye yi.
Nitorina lose sowipe, āra kabe nitāi-cander, koruṇā hoibe: "Igba wo ni ijo na ma de, nigbati ore-ofe Oluwa Nityananda ma funmi nibukun..." Viṣaya chāḍiyā. Āra kabe nitāi-cander koruṇā hoibe, saṁsāra-bāsanā mora kabe tuccha ha'be. Itumo Saṁsāra-bāsanā ni ife okan fun igbadun aye yi. Saṁsāra-bāsanā mora kabe tuccha ha'be: "Nigbati ife fun igbadun ile aye yi ma tan, ti koni se pataki." Tuccha. Itumo Tuccha ni nkan tio niyi kankan: " E so danu." Beena, ilosiwaju ninu eto mimo le daju teyan ba ni igbagbo, pe " Ile aye yi ati awon idunnu aye yi o ni iye kankan. Kole funmi ni idunnu kankan to daju." Igbagbo yi se pataki gan. Saṁsāra-bāsanā mora kabe tuccha ha'be. o si sowipe " nigbawo ni mole bo lowo awon ife okan fun igbadun ile aye yi, lehin na nimole ri Vrndavana gege boseje." Viṣaya chāḍiyā kabe śuddha ha'be mana: " Nigbat'okan mi ba yasi mimo, laisi idoti ile aye yi, nigbana nimole ri bi Vrndavana se ri." Ni oro imi, eyan o le losi Vrndavana pelu agidi lati olo gbe nibe, kosi ni idunnu mimo yi. Kolese se. Eyan gbudo paari gbogbo awon nkan t'okan re fe. Nigbana leyan le gbe ni Vrndavan kosi gbadun gbigbe re nibe. beena Narottama dāsa Ṭhākura sowipe Viṣaya chāḍiyā kabe, śuddha ha'be mana: Nigbat'okan mi bo lowo gbobo idoti igbadun aye yi tinba de ya si mimo, lehin na nimole ri Vrndavana boseje." Bibeko kolese se. lehin na o sowipe , itumo lilo si Vrndavana ni lati ni oye nipa awon akoko idaraya laarin Radha ati Krsna. Bawo lasele se? O sowipe, rūpa-raghunātha-pade hoibe ākuti. Rūpa, Rūpa Gosvāmī, lati Rūpa Gosvāmī titi de Raghunātha dāsa Gosvāmī, awon Gosvami mefa lo wa: Rūpa, Sanātana, Gopāla Bhaṭṭa, Raghunātha Bhaṭṭa, Jīva Gosvāmī, Raghunātha dāsa Gosvāmī. o sowipe, rūpa-raghunātha-pade: "Lati Rūpa Gosvāmī titi de Raghunātha dāsa Gosvāmī," pade, " niwaju ese wan. Nigbawo ni mole ni anfanni lati ni ifes fun ese wan..." Rūpa-raghunātha-pade, hoibe ākuti. Ākuti, anfanni, Iru anfanni wo leleyi? Itumo re niwipe agbudo ni oye nipa Radha-Krsna lati awon Gosvami. Eyan o gbudo gbiyanju lati no oye Radha-Krsna fun ara re. Koni ranlowo. awon Gosvami, wanti funwa ni ilana, gege bi Bhakti-rasāmṛta-sindhu, gege bayi, agbudo tele won, latile ni ilosiwaju. Lehin na nijokan, boya a le ni oye, nipa awon itan idaraya laarin Radha ati Krsna. Bibeko, a le rowipe omo-okurin tabi obirin lasan lonje, ton fi ife han ara won, lehin na koni ye wa. Lehin na awon prakrta-sahajiya ma jade latinu iru imoye bayi, awon ton jiya ni Vrndavana.
Gege bayi Narottama dāsa Ṭhākura ti funwa ni ilana, basele de ipo to gaju ninu asepo pelu Radha ati Krsna. Nkan t'alakoko niwipe agbudo ni ifarasi Śrī Caitanya Mahāprabhu. Eleyi m fona han wa. Nitoripe o wa lati le funwa l'oye nipa imoye Krsna, Nitorina agbudo teriba fun Śrī Caitanya Mahāprabhu. Taba si teriba fun Śrī Caitanya Mahāprabhu, inu Nityananda Prabhu asi dun, Ti inu re ba dun, awa ma nigbala lati awon ifekufe okan wa. Ti awon ifekufe yi ba tan, lehin na a le wonu Vrndavana. taba ti wonu Vrndavan, tabi ti l'anfanni lati sise fun awon Goswami mefa, lehin na a le de ipo tole funwa ni oye nipa awon itan idraya ti Radha ati Krsna.