YO/Prabhupada 0392 - The Purport to Narada Muni Bajay Vina
Purport to Narada Muni Bajay Vina -- Los Angeles, September 22, 1972
- Nāma amani, udita haya
- bhakata-gītā-sāme
Orin Bhaktivinoda Ṭhākura leleyi. Koko orin yi niwipe eda pataki ni Nārada Muni je, O sin sere pelu irinse orin re ton pe ni vina. Irinse t'olorin ti Narada Muni ngbe lon pe ni Vina. Beena bo sen sere pelu irinse re na lon p'oruko rādhikā-ramaṇa. Rādhika-Ramaṇa ni oruko imi fun Kṛṣṇa. beena lesekese to bere sini sere pelu irinse t'olorin na, gbogbo awon olufokansi na ma bere sini daun. asi d'ohun to dara lati gbo. Amiya dhārā variṣe ghana. Nigbat'on korin na pelu irinse t'olorin yi, o dabi wipe ojo oro-ofe n'ro, gbogbo awon olufokan si sin tokan tokan pelu idunnu to po. Nigbaton jo o dabi wipe wa pa na nidi oti ton pe ni mādhurī pūra. bi awon eyan na man ya were lat'oti mimu, beena ni awon olufokansi na si ya were. imi ninu won bere sini sukun immi ninu won bere sini jo. awon ti won a le jo niwaju awon eyan, wan bere sini jo ninu okan won. Bayi, Siva si fa Narada Muni mo ra, Osi berre sini soro pel'ohun to kun fun idunnu. Nigbati Brahma riwipe Siva ati Narada Muni jo n'jo, oun na bere sin i jo pelu won, o si bere sini sowipe, " Gbogbo yin E korin, haribol, haribol!"
Beena, Oba Orun, Indra si bere sini jo pelu won,inu re si dun gan. osi bere sini jo ton korin, " hari hari bol." Bayi pelu ohun mimo oruko Olorun yi, Idunnu si kun gbogbo agbaye, Bhaktivinoda Ṭhākura sowipe, " Nigbati gbogbo aye yi ba kun fun idunnu nigbana ni ife okan mmi ma tan, nitorina ni mosen gbadura si ese Rupa Gosvami, pe ejeki orin kiko hari-nama ko lo titi bayi, lai paari."