YO/Prabhupada 0391 - The Purport to Manasa Deha Geha



Purport to Manasa Deha Geha

Mānasa, deho, geho, jo kichu mor. Orin Bhaktivinoda Ṭhākura leleyi. On ko wa basele ni ijowosile pipe. Mānasa, deho, geho, jo kichu mor. Ni alakoko, oti se ijowosile pelu okan re, nitoripe okan wa ni orisun gbogbo awon iranu okan wa, itumo ijowosile ati ise ifarafun Oluwa niwipe ani idari lori okan wa. Nitorina lose sowipe mānasa, okan nitumo re, lehina deha: "iye ara." Śarīra. Ara eda nitumo Deha; iye ara nitumo ara. Beena, ta wa ba ni ijowosile okan wa si ese Krsna, Lehin na gbogbo iye-ara wa ma jowosile. Lehin na, " Ile mi." Deha, geho. Ile nitumo Geho. Jo kichu mor. Gbogbo nkan ohun elo tani ni awon nka meta wanyi: okan, ara ati ile wa. Beena Bhaktivinoda Thakura sowipe ka se jowosile gbogbo awon nkan wanyi. Arpilū tuwā pade, nanda-kiśor. Kṛṣṇa ni Nanda-kiśor. Beena " Moti fun E ni okan mi, ara mi ati ile mi." NIsin, sampade, vipade, jīvane-maraṇe: " Boya inu mi dun tabi moni ibanuje, boya mowa laaye tabi mo ku." Dāy mama gelā, tuwā o-pada baraṇe: "Nisin moti ni ifokan bale. Moti ni ifokanbale nitoripe moti se ijowosile gbogbo nkan timo ni." Mārobi rākhobi-jo icchā tohārā: "Nisin owo yin lowa, teba fe toju mi tabi teba fe pa mi, owo yin lowa." Nitya-dāsa prati tuwā adhikārā: " E lese ounkoun toba wun yin pelu iranse yin. Iranse yin tayeraye ni mo je." Janmāobi moe icchā jadi tor: " Toba wun yin" - nitoripe awon elesin ma pada sile, si odo metalokan - Nitorina Bhaktivinoda Ṭhākura ti salaaye, " Teba si fe motun le pada wa s'aye yi, kosi nkan to baje." Bhakta-gṛhe jani janma hau mor: " Ibeere kan soso timoni niwipe tin ba ma pada wa s'aye yi, E dakun eje kin wa ninu ile awon olufokansi." Kīṭa-janma hau jathā tuwā dās: " Kosi nkan tobaje timo ba wa bi kokoro, sugbon mofe wa ninu ile awon olufokansi." Bahir mukha brahma-janme nāhi āś: Mio feran aye alainigbagbo. Tonba tie bimi timo je Brahma. Mofe wa pelu awon olufokansi. "Bhukti-mukti-spṛhā vihīna je bhakta: " Mofe awon olufokansi tio ni anfanni kankan fun idunnu ie aye yi tabi ominiran." Labhaite tāko saṅga anurakta: "Mofe ni asepo pelu awon olufokansi mimo bayi." Janaka jananī, dayita, tanay: "latiisin lo, E yin ni baba mi, E yin l'egbon mi okurin, E yin ni omode-obirin ati omode okurin ti moni, Eyin l'Olorun mi, E yin ni Oluko mimo mi, E yin l'oko mi, gbogbo nkan leje simi." Bhakativinoda kohe, śuno kāna: "Oluwa mi, Kāna - Kṛṣṇa, E wo ni ololufe Rādhārānī, sugbon E wo l'emi mi, E funmi ni'daabo."