YO/Prabhupada 0397 - The Purport to Radha-Krsna Bol



Purport to Radha-Krsna Bol

"Rādhā-kṛṣṇa" bolo bolo bolo re sobāi. orin ti Ṭhākura Bhaktivinoda ko leleyi. wan sowipe Oluwa Caitanya ati Nityānanda, wan rin ninu awon titi ni ilu Nadīyā, wan korin yi, ton ba gbogbo eyan wi. Wan sowipe, " Gbogbo yin, edakun ekorin Rādhā-Kṛṣṇa tabi Hare Kṛṣṇa." "Rādhā-kṛṣṇa" bolo bolo bolo re sobāi. " Gbogbo yin ekorin "Rādhā-kṛṣṇa tabi Hare Krsna." Ilana to wa niyen. Ei śikhā diyā. Oluwa Caitanya ati Nityānanda, jawon mejeji, bonsen rin ati nigbaton jo loju titi, Wan salaaye pe " Gbogbo yin ekorin Rādhā-Kṛṣṇa." Ei śikhā diyā, sab nadīyā, phirche nece' gaura-nitāi. Irin nitumo Phirche, phirche. Nigbogbo ilu nadiya ni wan salaaye eto yi. Ei śikhā diyā, sab nadīyā, phirche nece' gaura-nitāi. lehin na o sowipe, keno māyār bośe, jāccho bhese’, "Kilode teyin sen jeki omi odo māyā, aimokan ile aye yi, gbe yin lo?" Khāccho hābuḍubu, bhāi. "Lat'aro d'aale lee wa ninu isoro. Gege bi okurin to wa ninu omi, nigbami on ri sinu omi, nigbami on jade, sugbon leyin gbogbo e itiraka re si po. Beena, ninu omi okun māyā, kilode teyin sen tiraka bayi? nigbami t'eyin re sinu omi, nigbami t'eyin jade, nigbami inu yin ma dun, nigbami ibanuje. Niotooro, kosejo idunnu, teyin ba wa ninu omi yi, teyin ban re sinu omi t'eyin jade na, idunnu koni yen. pe e jade fun igba die, tetun re sinu omi na, idunnu ko niyen." Beena Caitanya Mahāprabhu ti salaaye wipe " kilode teyin sen tiraka pupo," māyār bośe, "labe agbara maya?" Kila le se? O sowipe jīv kṛṣṇa-dās, e viśvās, " E gbudo nigbago pe iranse Olorun leje, iranse Krsna." Jīv kṛṣṇa-dās, e viśvās, korle to' ār duḥkha nāi: ""lesekese teba wa sori ipo pe eyin di iranse Olorun tabi iranse Krsna, lesekese ni gbogbo isoro yi ma paari. Koni si isoro mo." Beena Oluwa Caitanya lo funwa ni ilana yi nigbaton rin loju titi. Jīv kṛṣṇa-dās, e viśvās, korle to' ār duḥkha nāi. Bhaktivinoda Ṭhākura si funwa ni ijerisi re. O sowipe, jay sakal vipod, " Moti bo lowo gbogbo alebu ," Gāi bhaktivinod. Bhaktivinoda Ṭhākura, ācārya loje, o ni iriri, oun losi sowipe "nigbakugba tin ba korin Rādhā-Kṛṣṇa tabi Hare Kṛṣṇa, mo man bo lowo gbogbo alebu." Jay sakal vipod. Jakhon ami o-nām gāi, " igbakugba tin ba korin orukom mimp, Hare Kṛṣṇa tabi Rādhā-Kṛṣṇa, lesekese ni gbogbo alebu mi ma tan." "Rādhā-kṛṣṇa" bolo, saṅge calo. Gege na Oluwa Caitanya sowipe, " Mo sin rin loju titi, mosin toro lowo re. Iru ẹbẹ wo leleyi? Pe ke korin. Ibeere timo ni niyen." "Rādhā-kṛṣṇa" bolo, saṅge calo. " E tele mi." "Rādhā-kṛṣṇa" bolo, saṅge calo, ei-mātra bhikṣā cāi, " Ibeere kan soso ti mon beere leleyi, pe ke korin Hare Kṛṣṇa kesi tele mi, ki itiraka yin ninu ile aye baa le paari."