YO/Prabhupada 0414 - Approach the Original Supreme Personality of Godhead, Krishna



Lecture & Initiation -- Seattle, October 20, 1968

Prabhupada: Govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ bhajāmi.

apejọ eniyan: Govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ bhajāmi.

Prabhupada: Beena itumo egbe imoye Krsna yi ni lati sumon Olorun, Eledumare, Krsna. Imoye Krsna leleyi, taara. Ibukun pataki t'Oluwa Caitanya pe..... Ninu asiko tawayi, idamu towa po gan, awon alebu ninu aye eda, die die won ti fi imoye Krsna yi sile, tabi imoye Olorun. Konsepe die die wanti fi sile. beena Vedānta-sūtra sowipe, athāto brahma jijñāsā. konsepe ati da esin imi sile. Nkan pataki ni fun asiko tawayi. Nitoripe awa ti sowipe boya ke tele iwe mimo Bibeli, tabi ke tele Korani tabi ke tele awon Veda, Olorun ni'pinnu gbogbo e. Sugbon lasiko tawayi, nitori ipa Kali-yuga.... Itumo Kali-yuga ni asiko ija ati iyapa. Beena lasiko yi itiju awon eyan po gan. T'alakoko niwipe fun igba die lon gbe ninu aye yi. Marundinlogoji odun ni'gba aye ni orile - ede India, mio mo fun iwonba odun melo ni awon eyan man gbe nibi, sugbon ni Orile India awon eyan ti poju. Ko s'ogbon, tabi pe kon jade lati ni idari lori awon orile-ede imi. Gbogbo awon eyan wa sibe lati lo won nilokulo, sugbon won o losibi kankan lati se irun nkan bayi. Asa won niyen... won o le lo nkan elomi nilokulo. Sugbon, alebu to po gan lowa lori ipo India nisin nitoripe won ti fi asa won sile, won sife farawe asa awon aralu geesi, kode lese se fun won nitori awon ayidayida toni, Nitorina won ti bos'aarin iwo Scylla ati Charybdis. Se tiri bayi.

Beena bayi l'asiko yi se ri. Ninu orile ede India nikan ko, ninu awon orile ede imi, awon isoro t'awon na yato. Isoro won yato, sugbon isoro si wa, boya India tabi America tabi China. Nibikibi won gbiyanju lati s'eto fun alafia ile aye yi. Ninu orile-ede yin, ni America, kos'eto aabo fun awon eyan pataki gan bi Kennedy, se ri bayi. Won le fi ku pa enikeni leyikeyi asiko, kosi nkankan toma sele. Isoro imi niyen. Ni orile-ede awon kommunisti, won lo agidi fi ni idari lori awon olugbe. Opolopo ninu awon olugbe Russia, ati awon olugbe China lon kuro ni ilu won. Won o fe gbe mo ninu ilu bayi. Beena awon isoro wanyi wa nitori asiko tawayi. Nitori awon isoro asiko Kali, awon isoro wanyi wa. Kini awon isoro wanyi? Isoro towa niwipe ni asiko yi, fun igba die ni igba odun aye awon eyan, Awa o mo igba tama ku. A le ku leyikekyi asiko. Wan salaye pe ni asiko ijoba Oluwa Ramacandra, brahmana... (legbe:) Ko sise? brahmana kan wa ba oba, " Oba mi, omo mi ti ku. Salaaye funmi kilode ti omo mi se ku niseju babare." Seyin ri aduru ise t'oba ni nigbayen. Arugbo yi si wa ba oba, "kilode ti omo sele ku niwaju baba re? Salaaye funmi." Seyin ri aduru ise ti'joba ni nigbayen. Ijoba loma seduro ti omo ba ku ki babhato ku. L'aye yi oyeki baba ku ki omo to ku nitoripe ohun lo dagba ju. Iseduro yi wa fun awon onijoba. Nisin ninu ule aye yi, ele fiku pa enikeni.