YO/Prabhupada 0431 - God is Actually Perfect Friend of all Living Entities



Lecture on BG 2.11 -- Edinburgh, July 16, 1972

lati ni idunnu, nkan meta wa toye ka mo. Wanti salaaye ninu Bhagavad-gita.

bhoktāraṁ yajña-tapasāṁ
sarva-loka-maheśvaram
suhṛdaṁ sarva-bhūtānāṁ
jñātvā māṁ śāntim ṛcchati
(BG 5.29)

Egbodo mo nkan meta pere, lehin na ema ni alafia. Kini nkan na? T'alakoko niwipe " Olorun ni onigbadun, emi ko." Sugon nibi, asise wa niwipe, gbogbo rowipe, " Onigbadun nimi." Sugbon nitoripe onigbadun ko laje. Fun apeere, nitoripe moje nkankana pel'Olorun... Gege bi owo mi seje nkankana pel'ara mi. Kasowipe owo mi mu oun ti mole je dani. Owo mi o le je ounje na. Owo a mu asi fis'enu mi. Toba si los'enu mi a losinu ikun, ibi t'agbara ma jade nitori ounje na, agbar na asi wa si owo mi. Owo nikan ko - si oju, ese bayi bayi lo. Beena, aw ao le gbadun ounkoun fun ara wa. Sugbon tawa ba lo gbogbo nkan fun igbadun Olorun, tasi ni asepo ninu igbadun na, nkan to da niyen. Imoye wa leleyi. Awa o le mu nkankan. Bhagavat-prasādam. Bhagavat-prasādam. Imoye wa niwipe agbodo se ounje to da fun Krsna, lehin igba toba jeun ton a le jeun. Imoye wa leleyi. Awa o le gba nkankan lai fun Krsna. Beena nkan t'an so niwipe Olorun ni onigbadun to gaju. Awa o kin se onigbadun. Oniranse laje. Beena bhoktāraṁ yajña-tapasāṁ sarva-loka-maheśvaram (BG 5.29). Olorun ni olori gbogbo nkan. Otooro leleyi. fun apeere kasowipe eyin leni omi okin yi? Awa sin paariwpo pe awa lani ile yi tabi okun yi. Sugbon kon to bimi omi okun yi ti wa, ile yi na ti wa, lehin igba timo ba ku, omi okun na ma wa, ile na ma wa. Nigbawo nimo di onile? gege bi yara yi. Kato wole, yara yi ti wa, taba si kuro, yara yi asi wa. Tani onile tuntun ma je? tawa ba rowipe nitoripe awa nibi fun wakati kan si keji,pe ati di onile , ironu eke niyen je. beena eyan gbodo mo wipe aw ao kin se onile tabi onigbadun. Bhoktāraṁ yajña... Olorun ni onigbadun. Olorun ni onile. Sarva-loka-maheśvaram. Ati suhṛdaṁ sarva-bhūtānām (BG 5.29), Oun l'ore gbogbo wa. Ore awon eda eyan nikan ko loje. Ore awon eranko na loje. Nitoripe gbogbo eda dabi omo s'Olorun. Bawo lose jewipe ale huwa kan si awon eda eyan sugbon asin huwa imi si awon erankp? Rara. Ore to daju gbogob awon eda l'Olorun je. T'awa ba ni oye awon nkan meta wanyi, lesekese ni alafia ma wa.

bhoktāraṁ yajña-tapasāṁ
sarva-loka-maheśvaram
suhṛdaṁ sarva-bhūtānāṁ
jñātvā māṁ śāntim ṛcchati
(BG 5.29)

Ilana fun santi leleyi. teyin ba rowipe " Emi nikan l'omo Olorun, awon erank o l'emi , eje ka pa won," imoye to daju ko niyen. Kilode? Kini awonh aami eda to l'emi? Awon aami na je nkankanna: ji jeun, si sun, imo ako ati abo ati igbeja ara eni. Awon eranko na sin se gbogbo nkan merin wanyi. Kini iyato laarin awon eranko at'emi? Beena gbogbo nkan lo daju ninu imoye awon iwe mimo Veda, nipataki wanti funwa ni isonisoki ninu Bhagavad-gita gege bose je. Ibeere wa kan soso niwipe ya s'Olorun. Aaye to wa niyen. Ara eda eyan yi l'aaye kan soso tani lati mo nipa Olorun, Eni ti mo je, ibasepo mi pel'Olorun. Awon eranko - awa o le pe awon ologbo at'aja si apejo wa yi. Kolese se. Ati pe awon eda eyan, nitoripe o le ye won. Beena awon eda l'ogbon lati ni oye na. Durlabhaṁ mānuṣaṁ janma. Nitorina lonsen pe ni durlabha, o sooro gan lati ni ara eda eyan. T'awa o ba gbiyanju lati ni oye nipa "Ta l'Olorun je, eni timo je, kini ibasepo mi pelu re," lehin o dabi ipaara eni. Nitoripe lehin aye yi, lesekese tin ba f'ara y sile, moni lati gba ara imi. awa o de mo iru ara wo lama ni. Owo wa ko lo wa. Eyin o le sowipe " Ni aye to kan mo fe d'oba." Kolese se. Toba yeke d'oba, awon agbara iseda a fun yin l'ara oba ninu ile oba. Eyin o le se bayi. Ntorina agbodo sise lati ni ara imi to da. Wanti salaaye ninu Bhagavad-gita na:

yānti deva-vratā devān
pitṟn yānti pitṛ-vratāḥ
bhūtāni yānti bhūtejyā
yānti mad-yājino 'pi mām
(BG 9.25)

Beena toba jepe agbodo seto aye to kan ninu aye yi, kilode teyin o le s'eto lati pada si odo metalokan. Egbe imoye Krsna niyen. Awa fe ko gbogbo awon eda eyan bonsele s'eto na beena tonba fi ara yi sile wanle pada s'Olorun. Si ile, odo metalokan. Wanti salaaye ninu Bhagavad-gita. Tyaktvā dehaṁ punar janma naiti mām eti kaunteya (BG 4.9). Tyaktvā deham, after giving up this... (Isinmi) ....agbodo fi sile. Awa o fe f'ara wa le, sugbon o ye ka se. Ofin iseda niyen. " O daju bi iku." Kato ku oye ka seto fun ara wa to kan. T'awa o ba se bayi, a kon paa'ra wa, ipara-eni. Beena egbe imoye Krsna yi fe fun agbaye yi nigbala lati ma se ara won lese pelu ironu pe nkanna lonje pel'ara won. itosona to wa niwipe e gbodo korin oro meridinlogun wanyi, boba tiejepe oni sayensi leyin je, teyin ba femo nipa awon nkan pelu ironu sayensi ani awon iwe nla nla bayi. Ele ka awon iwe wanyi, tabi ke paarapo pelu ka korin Hare Krsna mantra yi. Ese pupo.