YO/Prabhupada 0433 - We Say 'You Shall Not Have Illicit Sex'
Morning Walk -- May 13, 1975, Perth
Gaṇeśa: Śrīla Prabhupāda,ninu Śrī Īśopaniṣad wan sowipe agbodo ko nipa ona aimokan, pelu ilana imora-eni.
Prabhupāda: Hmm?
Gaṇeśa: Ninu Īśopaniṣad, pravṛtti pelu nivṛtti. Bawo lose je?
Prabhupada: Kini pravṛtti pelu nivṛtti?
Amogha: O sowipe ninu Isopanisad, won salaaye wipe agbodo ko nipa ilana imoraeni pelu ilan aimokan.
Prabhupada: Aimokan, beeni. Pravrtti ati nivrtti niyen. Igbadun ara eni nitumo Pravrtti. Itura lati awon igbadun wanyi nitumo nivrtti. Beena tawa ba sowipe " Ema ni asepo pelu eni tio kin se iyawo tabi oko yin," sugbon imo ako ati abo yi gan lon feran, beena nitorina lose je nkan iyipo. Awon eyan ton feran nkan aye yi. Wan fe ni imo ako ati abo yi bon sefe - imo ako ati ako, imo ako ati abo, ijo nihoho, pravrtti. Sugbon awa sowipe, " Ema se bayi mo," nivrtti. Wan o sife nitoripe asura niwon. Pravṛtti jagat. Won o mo koko oro na. Won o mo. Koko oro niyen. Tapasā brahmacaryena (SB 6.1.13). brahmacarya nitumo Tapasya. Awon swami eke wanyi, ton wa lati se awon itosona yoga sugbon awon gan feran imo ako ati abo yi. Nkan ton sele niyen. Niotooro, yanga lasan loje - wanti di swami won si ko awon eyan nipa ilana yoga - nitoripe won o mope eyan gbodo fi ipaari si gbogbo eleyi. Brahmacaryena. Beena itanje yi sin lo nigbogbo agbaye, awa sin soro nipa won. Murkhayopadeśo hi prakopāya na śāntaye. Teba fun awon didirin wanyi, inu ma bi won. Kole gba lati fi ni ilosiwaju. Ipo wa leleyi. Awon alakowe eke wanyi, awon elejo, gbogbo won lon wa lona pravrtti-marga. Nitorina lon se sofun awon eyan, "Bayi ni isotunmo wa se ri." Prabrtti-marga. Nitoripe ton ba le ri ijerisi kankan ninu awon sastra lati fi ti, won ma bere sini rowipe, " Ati wa dada." Nkan ton sele niyen. Pravṛttim ca nivṛttim janā na vidur āsurāḥ. Gbogbo aye yi kun asura, awon ebi Hiranyakasipu, nitori lose le gan. Sugbon taba fun won laaye lati korin Hare Krsna mantra, die die lo ma ye won. (Isinmi to po) Isoro tani niwipe: awon swami eke wanyi, awon aalufa, won wa lona pravṛtti-mārga. Gbogbo awon alufaa wanyi, sugbon wansi se imoako ati abo. Pravṛtti-mārga. Beena won sofun awon eyan, " Ele ni imo ako abo pel'okurin na." Wanti se igbeyawo laarin okurin at'okurin na. Se mo bee? Wanse igbeyawo laarin okurin meeji ninu ile Olorun na. Iru awon eyan wo leleyi? Wansi n'pe ara won ni aalufaa. seti ri bayi. Iru awon eyan bayi, ton moti... Wansi losi ile-awosan lati le ni iwosan lati aisan oti mimu yi. Alaisan egbeedogbon wa ninu awon ile iwosan ni orile-ede America, gbogbo won oloti, alufaa de ni won. se ti ri bayi. Nitoripe won wo aso gungun awon alufaa, kilon pe?
Srutakirti: Ewu awole.
Amogha: Asa?
Prabhupada: Ewu pelu esin kristi, nkan tonti da niyen. Ni India na, awon eyan ni okun, brahmana. okun toro-kobo. Otan.
Paramahaṁsa: Awon omo iranu gan ni ile ako gan ni.
Prabhupada: ati pelu igi danda kan, eyan le di sannyasi. Gbogbo agbaye leleyi tin sele. Awon Mussulman, pelu irugon to gun, oti di Musluman. Mussuleḥ iman. Musseleḥ, enito wa ni pipe ati iman enito je olooto. Itumo Mussulman niyen. Toje Olooto, ati to fokan si nkan ton se.