YO/Prabhupada 0446 - Don't Try To Separate Laksmi From Narayana



Lecture -- Seattle, October 2, 1968

Beena sakṣat śrī. O wa pelu re nigbogbo gba. enikeni toba fe mu Sri lati Narayana, lehin won ma pa danu. Ravana ni apeere to wa. Ravana sife mu Laksmi lati Rama. Iru iwa si ni alebu to po to jepe, dipo ti inu Ravana ma dun... O si l'ola to po sugbon lesekese to gbiyanju lati mu Laksmi lat'owo Narayana, aye re si paare pelu gbogbo awon ore re. Beena ema danwo, lati mu Laksmi lati Narayana. Kosi besele mu kuro. Sugbon teyan ba gbiyanju lati danwo, aye re ma baje. Aye re ma baje. Ravana ni apeere to wa. Beena lasiko tawayi awon eyan si feran sri, owo. Śrī-aiśvaryā. Śrī-aiśvaryā. Śrī-aiśvaryā prajepsavaḥ. Gbogbo awon eyan, wan fe sri, owo, awon obirin to lewa. Śrī-aiśvaryā: money, ola. Śrī aiśvaryā prajepsavaḥ. Prajā. Ebi, awujo, owo nitumo Prajā. Nkan ton fe niyen. Beena wan sa tele Sri. sugbon ema gbiyanju lati toju Sri nikan. Lehin aye yin ma baje. Itosona to wa niyen. Ema toju Sri nikan. E toju re pelu Narayana nigbogbo'gba. Lehin na inu yin ma dun. E toju Narayana. Beena awon eyan to lowo, awon ton l'ola, oye kan s'aadura si Narayana pelu owo ton ni. E na owo na. Oye ke lo owo yi fun ise Narayana. Beena teba lowo, ema lo nilokulo bi Ravana, sugbon e lo ninu ise Krsna. Teba lowo, e lo fun ile adura, lati fi irisi Lakṣmī-Nārāyaṇa, Rādhā-Kṛṣṇa, Sītā-Rāma, sinu ile-adura bayi. Ea lo owo yin nilokulo. Lehin na owo teni ma wa fun igba to pe. Eyin o le di talaka mo. sugbon lesekese teba fe tan Narayana je, pe " moti gba Laksmi re," ebi ma pa yin danu. Ironu yi ko da. Beena ibikibi ti Sri ba wa, Narayana na wa nibe, ibikibi ti Narayana ba wa, Sri na wa nibe. Nitorina Narayana ati Sri. Nṛsiṁha-deva is Nārāyaṇa, ati Lakṣmī, gbogbo'gba lon wa... Nitorina awon deva, awon orisa, nigbat'on riwipe "Nārāyaṇa, Nṛsiṁha-deva, pe inu n'bi. Kode seni tole jeki inu re dun," Beena won rowipe "Laksmiji je alabasepo tii Narayana nigbogbo'gba, E sofun ko lo jeki okan re bae." Wan ti salaye nibe. Sākṣāt śrīḥ preṣitā devair. Awon deva, Brahma, Siva ati awon iyoku, wan si bere, " Mama. e gbiyanju lati jeki okan oko yin bale. Kosi basele se." Sugbon aya re na bere sini ja. Eru n'ba. Sākṣāt śrīḥ preṣita devair dṛṣṭvā taṁ mahad adbhutam. O mowipe " Oko mi ti gba irisi Nṛsiṁha-deva," sugbon nitoripe irisi Olorun yi sin deruba, Ko sife loba. Kilode? Nisin, adṛṣṭaśruta-pūrvatvāt: beena ko o wipe oko re le gba irisi ti Nrsimha-deva. Irisi Nrsimhadeva yi si wa fun Hiranyakasipu nikan. Alagbara loje. Hiraṇyakaśipu ti gba ibukun lowo Brahmā, pe kosi orisa kankan, tole fi ku pa; kos'eyan kankan tole fi kupa, kos'eranko kankan tole fiku pa; ati bayi bayi lo. Lona imi osi fe se keeni kankan ma le fiku pa. Nitoripe ni alakoko ofe wa laaye tayeraye, beena Brahma sowipe " Emi gan mio le wa laaye tayeraye. Bawo nimo se fe fun e nibukun lati wa laya tayeraye...? Kolese se." Beena awon rākṣasas, esu, wan si logbon gan, duskrtina, Ogbon - sugbon fun awon ise telese. Iwa awon raksasa niyen. beena osi sofun ara re pe " mole gba ona imi fi gba ibukun yi lowo Brahma, bayi mole wa laaye tayeraye." Beena lati jeki ibukun ti Brahma fun wa i pipe, Narayana si wa bi Nrsimha-deva, idaji kiniun ati idaji okurin. Nitorina adṛṣṭāśruta-pūrva. Laksmi gan ko ri iru irisi Olorun yi ri tele, idaji kiniun ati idaji Okurin. Narayana, tabi Krsna, alagbara loje. O le mu irisi toba fe. Adṛṣṭā aśruta-purva. koseni to riri. Botilejepe o wa nigbogbo'gba pelu Narayana koi ti ri iru irisi yi teletele. Nitorina wan sowipe, adṛṣṭā aśruta-pūrvatvāt sā na upeyāya śaṅkitā. Lakṣmījī si je iyawo to daju s'oko re. Beena śaṅkitā: eru ba, " Boya eleomi leleyi." Iyawo tosi daju gan loje, to daju ju. Bawo lose fe ni asepo pel'elomi? Nitorina śaṅkitā: Oro ton lo ni śaṅkitā. Botilejepe oye ko mo gbogbo nkan sugobn osi rowipe, " boya oko mi ko leleyi." Iyawo to daju leleyi, Laksmiji, nitoripe ko mo boya Visnu ni, ko ba soro, ko summon. śaṅkitā. Iwa imi ti Laksmiji. Eru ba, " Boya Narayana ko leleyi," nitoripe ko ri oko re ri pelu irisi bayi ri, idaji okurin idaji obirin. beena adṛṣṭāśruta-pūrvatvāt sa nopeyāya śaṅkitā.