YO/Prabhupada 0464 - Sastra is not For the Loafer Class
Lecture on SB 7.9.8 -- Mayapur, February 28, 1977
Beena mahājano yena gataḥ sa panthāḥ (CC Madhya 17.186). ale ko dada nipa imoye Krsna taba tele awon mahajana dada. Itumo Mahajana ni awon eyan pataki tonje olufokansi Oluwa. " Mahajana niwon. "Eyan" nitumo Jana. Gege bi orile-ede India awon olowo lonpe ni mahajana. Beena mahajana yi l'eni toba ni ise ifarasi Oluwa to wa ni pipe. Oun lon pe ni mahajana. Mahājano yena gataḥ sa panthāḥ. Beena awa ni Ambarīṣa Mahārāja; asi ni Prahlāda Mahārāja. Awon oba to po gan bi Yudhiṣṭhira Mahārāja, Parīkṣit Mahārāja,awon lonpe ni rājarṣi. Beena imoye Krsna yi wa fun awon eyan pataki.
- imaṁ vivasvate yogaṁ
- proktavān aham avyayam
- vivasvān manave prāhur
- manur ikṣvākave 'bravīt
- (BG 4.1)
Evaṁ paramparā-prāptam imaṁ rājarṣayo viduḥ (BG 4.2). Niotooro fun awon oniranu ko ni sastra yi wa fun. fun awon brahmana alakowe, ati awon ksatriya pataki. Ati awon vaisya ati sudra, awon eyan wany o keeko kankan ninu sastra, sugbon, nitoripe won ni itosona dada lati awon brahmana ati ksatriya, awon na wa ni pipe. Awon eyan ton wa lori ipo kini, munayo, bonse salaaye, sattvaikatāna gatayo munayo (SB 7.9.8), Awon alufaa pataki. Awon brahmana lonpe ni " alufaa pataki", Vaisnava. Won wa lori ipo sattva-guna pelu ise ifarasi Oluwa ton se. Rajas, tamo-guṇa ko le fowokan won. Naṣṭa-prāyeṣv abhadreṣu nityaṁ bhāgavata-sevayā (SB 1.2.18). Awon bhadra ati abhadra, rere ati buruku. Beena rajo-guṇa ati tamo-guṇa buru, sugbon sattva-guṇa si da. T'awa ba wa lori ipo, sattvaikatāna-gatayo... Teyin ba wa lori ipo sattv-guna, beena gbogbo nkan lodaju. prakāṣa nitumo Sattva-guṇa. Gbogbo nkan lo daju, pelu imoye to po. rajo-guna o daju. Apeere na wa: gege bi igi. Teba fisin'ina eefin ma jade. Teyin ba fi'gi sina eefin loma koko jade. Nialakoko igi, lehin na eefin lehin na ina ma jade. teyin ba si lo ina yi lati sebo, iyen lo gaju. lati orisun kanna ni gbogbo awon nkan ti wa. Lati ile, ni'gi ti jade, lati igi ni eefin tin jade, lat'eefin na n'ina tin jade, taba si lo ina yi fi s'aadura, svāhā - iloo ina to daju niyen. teyan ba duro sori ipo igi, igbagbe niyen je. teyan ba wa lori ipo eefin, ina die ma wa. Teyan basi wole si ipo ina, ina si po nibe. taba si lo ina yi ninu ise Krsna, iyen na lo daju.Ogbodo ye wa bayi.