YO/Prabhupada 0466 - Black Snake is Less Harmful than the Man Snake
Lecture on SB 7.9.8 -- Mayapur, February 28, 1977
Awon okorin pelu iwa ejo won buru gan. Canakya Pandita ki sowipe,
- sarpaḥ krūraḥ khalaḥ krūraḥ
- sarpāt krūrataraḥ khalaḥ
- mantrauṣadhi-vaśaḥ sarpaḥ
- khalaḥ kena nivāryate
"Awon eda meji lon niitara. Nkan l'ejo, ejo dudu, ikeji ni okurin toni iwa ejo dudu." Kole ri nkan to daa. Sarpaḥ krūraḥ. Itara ejo po gan. Laisidi kankan a kon geyan je. Tejo ba wa loju titi teba koja segbe re lesekese loma geyin je. Beena iwa ejo niyen. Beena awon eyan wa ton ni iwa ejo. Laisidi kankan won ma bere sini bu yin, ejo ni awon eyan bayi na. sugbon Canakya Pandita ti sowipe " Awon ejo dudu wanyi ko nitara to eyan pelu iwa ejo." Kilode? Nisin, ejo dudu yi, pelu awon mantra tab'ogun ele ni idari lori re sugbon okurin pelu iwa ejo, kosi besele se."
Prahlada Maharaja ti juwe Hiranyakasipu bi ejo. Nigbati Nrsimha-deva binu gidi gan, O si so wipe, modeta sādhur api vṛścika-sarpa-hatyā (SB 7.9.14): " Oluwa mi, Eyin binu gidi gan si baba mi. Nisin oti tan, kosidi fun ibinu mo. E fokan bale. Koseni kankan ton binu nitoripe e pa baba mi, o daju. Beena kosidi fun ibinu. Gbogbo awon orisa wanyi, Brahma ati awon iyoku, iranse lonje siyin. Iranse nimo je siyin na. Beena teyan ba p'ejo toni itara, inu gbogbo eyan ma dun." Beena osi fun l'apeere nipa modeta sādhur api vṛścika-sarpa-hatyā: eni toje sadhu, okurin mimo, ko feran lati pa enikankan. Inu re o ni dun teba pa kokoro kekere gan, inu re o ni dun. " Kilode teyin se pa kokoro na?" kama wa so ti awon eyan, Para-duḥkha-duḥkhī. toba tie je kokoro kekere, sugbon lasiko iku kokoro na jiya, inu eni toje Vaisnava ko le dun: " Kilode teyin se pa kokoro na?" Para-duḥkha-duḥkhī leleyi. Sugbon inu Vaisnava yi ma dun teba p'ejo tabi akẽkẽ. Modeta sādhur api vṛścika-sarpa-hatya. Beena inu gbogbo eyan ma dun teba p'ejo tabi akeke, nitoripe awon nkan alebu lonje. Laisidi kankan won le geyan je wansi da isoro sile. Beena awon eyan pelu iwa ejo bayi wa, wansi ni itara nipa egbe wa, wansi ba wa ja. Iwa toni leleyi. Baba Prahlada Maharaja na si fun ni idamu to po, kaama wa soro nipa awon iyoku. Awon nkan bayi masele, sugbon koye ko fun ni idamu, nitoripe Prahlada Maharaja o ni ibanuje kankan nigbati gbogbo awon isoro yi sele Wansi fun l'oro lati mu, won ju sinu konga pel'ejo won ju lat'ori oke, won fi abe ese erin.. Nitorina ni Caitanya Mahaprabhu se sofun wa pe " Ema jeki ibanuje mu yin. E faramo." Tṛṇād api sunīcena taror api sahiṣṇunā (CC Adi 17.31): E faramo ju awon igi lo. Eyan gbodo ressile ju awon ewe. Awon nkan wanyi ma sele. Ninu aye kan t'aba se ise imoye Krsna dada, ti isoro die ba wa, ema foju si. E tesiwaju pelu imoye Krsna. Ema jeki ibanuje mu yi lokan, ti awon isoro ba wa. Nkan ti Krsna salaaye niyen ninu Bhagavada-gita, āgamāpāyino 'nityās tāṁs titikṣasva bhārata (BG 2.14): " Arjuna mi, toba ni ilera, bi ara eda se ri niyen, toba ya oma tan. Kosi nkankan to wa titi lo, beena ma jeki awon nkan wanyi fun e ni isoro. Tesiwaju pelu ise re." Itosona ti Krsna niyen. Prahlada Maharaja ni apeere to daju, agbodo tele iwa awon eyan bi Prahlada Maharaja.