YO/Prabhupada 0468 - Simply Inquire and be Ready How to Serve Krishna
Lecture on SB 7.9.9 -- Mayapur, March 1, 1977
Pradyumna: Isotunmo: "Prahlāda Mahārāja Tesiwaju: Eyan le l'ola, pelu ebi to daa, ko lewa, ko keeko, ko ma dan, ko l'agbara, ko l'ogbon, ko l'agbar idan, sugbon gbogbo awon amuye wanyi kosi beyan sefe fun Oluwa nitelorun gan. Bakana, eyan le fun Oluwa nitelorun pelu ise ifarasi fun. Nkan ti Gajendra se niyen, inu Oluwa si dun si."
Prabhupāda:
- manye dhanābhijana-rūpa-tapaḥ-śrutaujas-
- tejaḥ-prabhāva-bala-pauruṣa-buddhi-yogāḥ
- nārādhanāya hi bhavanti parasya puṁso
- bhaktyā tutoṣa bhagavān gaja-yūtha-pāya
- (SB 7.9.9)
Beena ohun ini aye yi, (segbe) Ko sise? ( fowokan gbohungbohun) Hmm? Ola, dhana... Koseni to le mu okan Krsna pelu awon nkan aye wanyi. Awon ohun ini: owo, ati agbara eda, ewa, ikeeko, agbara idan, ati bayi bayi lo. Awon nan wanyi po gan. Kosi bonsele ranyin lowo lati summon Olorun. Krsna ti salaaye fun ara re, bhaktyā mām abhijānāti (BG 18.55). Ko sope awon ohun ini aye yi, pe " Olowo nikan lole funmi nitelorun." Rara. Talako b'emi ko ni Krsna je, toje pe teyan ba fun lowo die inu re ma dun. gbogbo nkan tofe loni , ātmārāma. Beena kon niwulo fun iranlowo kankan lat'enikeni. Oni itelorun, ātmārāma. bhakti nikan, ife, loye kani. lati sise fun Krsna nitumo bhakti. Laisi nkankan leyin. Ahaituky apratihata. bhakti, laisidi fun. Anyābhilāṣitā-śūnyaṁ jñāna-karmādy-anāvṛtam (CC Madhya 19.167, Brs. 1.1.11). Nibikibi ninuawon sastra, won ti salaaye pe bhakti ogbodo ni nkankan leyin.
- anyābhilāṣitā-śūnyaṁ
- jñāna karmādy-anāvṛtam
- ānukūlyena kṛṣṇānu-
- śīlanaṁ bhaktir uttamā
- (Brs. 1.1.11)
- sarvopādhi-vinirmuktaṁ
- tat paratvena nirmalam
- hṛṣīkeṇa hṛṣīkeśa
- sevanaṁ bhaktir ucyate
- (CC Madhya 19.170)
Isotunmo imi si wa. Taba ni bhakti, ife fun Krsna, lehin na kosidi fun owo tabi agbara tabi ikeeko tabi inira lati awe gbigba. Kosi iru awon nkan bayi. Krsna sowipe, patraṁ puṣpaṁ phalaṁ toyaṁ yo me bhaktyā prayacchati (BG 9.26). Kofe nkankan lowo wa, sugbon O fe ki gbogbowa pe nitoripe asi je nkankana pelu Krsna, Osi fe ki gbogbowa gboran si lenu, kasi nife fun. èròńgbà re niyen. Gege bi baba to lowo gan. Kosidi fun iranlowo kankan lat'omo re, sugbon osi fe ki omo-okurin re gboran si lenu kosi nife fun. Nkan to ma fun nitelorun niyen. Bi gbogbo e se je niyen. Krsna ti ... Eko bahu śyāma. vibhinnāṁśa niwa - mamaivāṁśo jīva-bhūtaḥ (BG 15.7) - nkankana pelu Krsna, nigbogbo wa je. Beena gbogbo wa lani'se lati se. Krsna ti da wa s'aye lati sise, fun itelorun Krsna. bhakti niyen. Beena, aye wa ni ara eda eyan tani yi. Awa ogbodo lo asiko wa nilokulo ninu awon ise tioye. E bere ke sewaadi besele sise fun Krsna. Ānukūlyena kṛṣṇānuśīla. Ānukūla. fun itelorun Krsna, ti tawa ko. Nkan ton pe ni ānukūla, to dara. Ānukūlyena kṛṣṇānuśīlanam (CC Madhya 19.167). ise nitumo anuśīlanam, konsepe " mon sasaro." Iyen na da ju pe kama se nkankan lo, sugbon ise ifarasi Oluwa ni ise gidi toye ka se. Eyan gbodo sise, ise tosi daju ni lati se waasu nipa ogo Oluwa. Ise to daju niyen. Na ca tasmān manuṣyeṣu kaścin me prīya-kṛttamaḥ (BG 18.69).