YO/Prabhupada 0474 - Aryans Means Those who are Advanced



Lecture -- Seattle, October 7, 1968

Vedanta ti funwa nitosona wipe, " Nisin egbodo sewaadi nipa Brahman." Athāto brahma jijñāsā. Eleyi se pataki fun gbogbo awon eda eyan ton laju. Mio soro nipa awon olugbe America, ni Europu, ni Asia. Nibikibi. Awon ton ni ilosiwaju nitumo Aryan. Awon tio kin se Aryan i awon eyan tio ... Itumo Sanskrit, arya. Ati sudra... Awon Aryan yi pin sona meta. Apa to logbon ju lon pe ni brahmana, ati awon ton kere ju awon brahmana ni awon oniselu, won pewon ni ksatriya. eyi to tole won ni awon onisowo, awon, onisowo, elero, won kere ju awon ooniselu lo. kere ju bayi lo ni awon sudra. Oniranse nitumo Sudra. Beena ilana yi tipe. Ibikibi lowa. Ibikibi ti awujo eda yi ba wa, awon eyan merin wanyi wa nibe. Nigbami awon eyan man sebere lori eto isasoto eyan ni India. Niotooro isasoto yi nkan adayeba lo je. Bhagavad-gītā sowipe, cātur-varṇyaṁ mayā sṛṣṭaṁ guṇa-karma-vibhāgaśaḥ: (BG 4.13) " Awon ipo merin okurn wanyi wa nibe, ofin mi leleyi." Bawo lonse je merin? Guṇa-karma-vibhāgaśaḥ. Amuya nitumo Guna, ise nitumo karma. teyin ba ni iwa toda, iwa brahmana... Itumo iwa Brahmana niwipe eyin man s'ooto, eyin mo esi mo lati nidari lori ara iwa yi, okan yin bale, e mo bonse faramo nkan.. Eni gbagbo ninu Oluwa, emo awon iwe mimo dada. Awon iwa wanyi wa fun awon ipo to gaju, brahmana. Amuye t'alakoko to awon brahmana niwipe ooloto loje. A so gbogbo nkan fun awon ota re gan. Kole fi nkankan paamo. Satyam. Śaucam, o mo lati toju ara re ni mimo. Awon brahmana gbodo we lee meta lojojumo, kesi korin Hare Krsna. Bahyābhyantara, o mo nita, ati ninu. Awon amuye wanyi. nigbati awon amuye wanyi ba wa n'be, lehin na Vedanta-sutra, Vedanta ti salaaye wipe, " Nisin e sewaadi nipa Brahman." Athāto brahma jijñāsā. Athāto brahma jijñāsā.

Nigbat'eyan ba de ipo aye pipe, lehin nkan to tele niwipe ogbodo sewaadi. T'awa o ba gbiyanju lati sewaadi, lati ni oye nipa Brahman, ibanuje ma gba okan wa. Nitoripe idamu yi wa nibe, ilosiwaju imoye wa. Ofin ilosiwaju imoye niwipe, koseni tole ni itelorun pelu nkan to mo teletele. O gbodo sewaadi si. Beena ninu ilu yin, taba fi we awon orile-ede imi, etii ni ilosiwaju to po. Nisin emu brahma-jijnasa yi dada ke sewaadi nipa eda to gaju. Tal'eda to gaju yi? Tani mi? Brahman na nimi. Nitoripe mo je nkankan pelu Brahman, nitorina Brahman nimi. Gege bi iwonba kekere wura, Nkan imi ko loje. Beena, iwonba kekere laje si Brahman tabi eda to gaju. Gege bi ina orun, won tana lori orun sugbon won si kere na. Beena awon eda, nkankana laje pel'Olorun. Sugobn bi orun se tobi beena lose tobi, sugbon ina kekere orun lawa je. Ifi we laarin Oluwa at'awa leleyi.