YO/Prabhupada 0496 - Sruti Means we Hear from the Highest Authority



Lecture on BG 2.14 -- Germany, June 21, 1974

Beena egbe imoye Krsna yo wa lati mo nipa gbogbo nkan dada, lati olori to gaju Krsna. Ilana to wa niyen. Tad vijñānārthaṁ sa gurum eva abhigacchet (MU 1.2.12). lati le ni oye nipa eto oro yi to koja ogbon ori wa, ani lati summon awon olori tole salaaye funwa. Gege bi tinba femo nipa eni ti baba mi je to koja ohun ogbon mi, tokoja nkan timole fori ro, sugbon tinba gba oro iya mi to daju, ogbon pipe niyen je. Beena ona meta lowa lati ni oye na, tabi lati ni ilosiwaju ninu eto imoye. pratyaksa je ona kan, tale gba. ikej je awon olori, iketa je sruti. Igboran lati eda to gaju nitumo Sruti. Beena sruti ni ilana yi je. Pe awa ti gbo lati olori to gaju nitumo Sruti. Ilana wa niyen osi rorun gan. Olori to gaju, awon eyan lasan ni asise tonti se, sugbon olori yi o daabe. Won ni abàwonàbùkù laye won. abàwonàbùkù t'alakoko ninu eda lasan niwipe, ole s'asise. Awon eyan pataki ninu aye yi, gbogbo won lonti s'asise. won si wa ninu aimokan yi. Won ti gba awon nkan tio kin gidi bi nkan gidi. gege b'awa sen gba ara eda eyan yi bi nkan gidi. Itanraeni leleyi je. Sugbon konse nkan gidi. " Emi nimi." Otooro leleyi. Beena itanraeni leleyi. lehin na, pelu imoye itanraeni yi, imoye tio daju, ati d'oluko. Iyanje imi leleyi. wansowipe, gbogbo awon onisayensi ati alakowe wanyi, "Boya," " O le dabee." Beena nibo ni imoye yi wa?" O le dabee ati " boya." Kilode teyin sen gba ipo oluko? " L'ojowaju ale ni oye na." Kini ojowaju yi? seyin fe gba sọ̀wédowó ton fi s'ojowaju? " L'ojowaju masi riwipe, nitorina onisayensi nimi." Kini oni sayensi? lori gbogbo e, awon iye ara wa tio daju. Gege bi awa sen ri ina kan nitoripe ina imi wa. ti ina o ba si, lehin na bawo ni mose fe ri nkankan? sugbon asiwere wanyi won o miwipe ironu won o daju, sugbin won sin ko awon iwe nipa imoye. Imoye wo leyin ni? Agbodo gba imoye na lateni toje pipe. Nitorina la wa sen gba imolye na lati Krsna, eda to gaju, eda pipe. osi n'funwa ni'tosona wipe teyinbafe fi ipaari si inira ati igbadun, Lehin na egbodo s'eto, kema tun ara imi gba ninu aye yi. Itosona ti Krsna ti funwa niyen, basele fi ara eda yi segbe. Wanti salaaye nipe eto yi ni apa keji iwe mimo. Ninu apa kerin Krsna sowipe: janma karma me divyaṁ yo jānāti tattvataḥ, tyaktvā dehaṁ punar janma naiti mām eti (BG 4.9). E gbiyanju lati ni oye nipa awon ise Krsna. Awon ise yi nipa Krsna wa ninu awon itan akoole, ninu Mahabharata. India to lagbara nitumo Mahābhārata, tabi Bharata to lagbara , Mahābhārata, itan akoole re. Ninu atan akoole yi Bhagavada-gita wa ninu re na. Beena Oun soro ni pa ara e, E gbiyanju lati ni oye nipa Krsna. Egbe imoye Krsna wa leleyi. Beena egbiyanju lati ni oye nipa Krsna, ise re. Aiseyan ko loje. Janma karma me divyam. Ise nitumo Karma. Oni ise re. Kilode ton se awon ise aye yi na? Kilode to sen wa?

yadā yadā hi dharmasya
glānir bhavati bhārata
abhyutthānam adharmasya
tadātmānaṁ sṛjāmy aham
(BG 4.7)

Osi ni'di; Osi ni awon ise apinfunni re. Beena e gbiyanju lati ni oye nipa Krsna ati awon ise re. Wanti salaaye ni ona itan akoole. Beena nibo ni isoro na wa? Ati ka awon nkan to po, itan tabi awon ise t'olori kan, awon oniselu. Nkankanna loje, agbara kanna, lehin ma lo lati ni oye nipa Krsna. NIbo ni isoro na wa? Krsna, nitorina, Oti f'arare hon ninu awon ise re to po.