YO/Prabhupada 0507 - By Your Direct Experience, you Cannot Calculate
Lecture on BG 2.18 -- London, August 24, 1973
seyin le siro odun Brahma bayi. Yuga merin lowa, Satya, Tretā, Dvāpara, Kali - awon merin isiro yi koja Oke-meji lo ni odun. Apaapo awon odun meerin na niyen. mejidinlogun, mejila, mejo, merin. bawo losewa? mejidinlogun ati mejila? Ogbon, ati mejo iyen bosi mejidinlogoji ati merin gbogbo bosi mejilelogoji. Sahasra-yuga-paryantam. aimoye odun, sahasra-yuga-paryantam ahaḥ. Ojo kan nitumo Ahaḥ . Sahasra-yuga-paryantam ahar yad brahmaṇo viduḥ (BG 8.17). Ojo kan Brahma niyen. Ara titi d'ale ni Ojo kan bosi Okoja oke-meji odun lo. Nitorina agbudo ko nipa awon nkan bayi latinu sastra. Bibeko eyin o nji oye, bawo lesefemo. Kosi besele lo sodo Brahma tabi Osupa kama wa sonipa Brahmaloka ibi to gaju ninu agbaye wa. seyin riwipe kosi besele mo teba fe fori ro, kode si besele debe. awon oni sayensi le gbiyanju lati se isiro na, sugbon kole bosi wan sowipe lati de planeti to gaju ato odun oke-meji ton ba lo pelu iyara ina. awa sini isiro iyara ina awa si le fun yin ni isiro nibi, iwonba odun tonma lo kato bere sini soro nipa ijoba orun Panthās tu koṭi-śata-vatsara-sampragamyo vāyor athāpi manaso muni-puṅgavānām (Bs. 5.34). akiyesi ori nitumo muni-puṅga . Kosi besele fori ro. teba tie fori wo fun amoye odun kosi besele waadi re. egbudo gba bi sastra se sofun yin, bibeko kolesese. Nitorina Krsna sowipe nityasyoktāḥ śarīr-ukta. wanti so ni tumo Ukta kon sepe mo kan sosokuso Olorun loje. Ilana to wa niyen Afi ti awon Olori ba p'ase, ukta, awon olori, acarya kosi basele so nkankan. Parampara niyen. Egbianju lati mo sugbon ema fikun Kolese se. Nitorina wansen pe ni nityasyoktāḥ. kosi besele jiyan. Ase loje Nityasyoktāḥ śarīriṇaḥ anāśino 'prameyasya (BG 2.18), aimoye.