YO/Prabhupada 0514 - Here, Pleasure Means a Little Absence of Pain



Lecture on BG 2.25 -- London, August 28, 1973

ise tani niwipe agbudp di brahma-bhūtaḥ. talole de ipo yi? Ati salaaye Krsna ti salaaye ninu ese-iwe na..kini ese-iwe na? Yaṁ hi na vyathayanty ete. Vyathayanti, kole fun wa ni inira. isoro aye yi po gan. Ara tani gan, isoro loje. gege na teyan ba koja gbogbo inira ati igbadun wanyi... kosejo igbadun, tabi inira. Ni ile-aye yi aisi inira nitumo igbadun. Gege bi eyan toba ni ewo. Kileyin pe> Ewo? Phoṛā? inira to po gan ni. sugbon taba fogun si, inira na matan, lehin na eyan lerowipe "igbadun leleyi." sugbon ewo na si wanbe. Iru igbadun wo niyen? gege na ninu ile-aye yi kosejo igbadun, sugbon awa rowipe ale ri nkan to le fun wa ni igbadun na. gege bi awon aisan. A le ri awon ogun fun ati da orisirisi ile-iwosan sile. Awon ologun repete sin jade latibe, M.D., FRCS. sugbon iyen owipe eyin o le ku mo. Rara, egbudo ku, sa. Bayi na ni ewo si wanbe. Sugbon teba fogun die si/.. Nitorina kosi'dunnu ninu aye yi. Nitorina ni Krsna se sowipe, "kilode ti inuyin sen dunsi? Egbudo ku, sugbon eyin ju bayi lo.Eda ayeraye leje, sugobn egudo ku. Janma-mṛtyu-jarā-vyādhi-duḥkha-doṣānudarśanam (BG 13.9). Isoro teyin ni niyen.

Sugbon awon asiwere wanyi o mo. Wanrope nkan lasan ni iku je - lehin teyan ba ku kosi nkankan mo. Sugbon asiko die timo walaye yi ejekin gbadun. Ṛṇaṁ kṛtvā ghṛtaṁ pibet. Igbadun ni itumo Ni ilu India itumo igbadun wan yato si ti awon ilu-geesi ton feran eran jije Igbadun fun wan niwipe kon je ghee konsi sonra si. Igbadun wan niyen. Cārvāka Muni si sowipe " Eje ghee ke gbadun aye" Kachori, samosā, awon ounje ton fi ghee fi se. mio lowo sa, nibo nimofe ri ghee? Ṛṇaṁ kṛtvā. Toro, ya die lo, tabi ko lo ji ghee" bibakan tabi keji, wa owo ko si ra gheee naa, otan Ṛṇaṁ kṛtvā ghṛtaṁ pibet. Eje iwonba ghee teba fe". Ṛṇaṁ kṛtvā ghṛtaṁ pibet yāvād jīvet sukham. Jīvet. Sukhaṁ jīvet. " ke gbe ile-aye dada, kinu yin si dunsi". Eto awon elejo lati ilu geesi niyen; kongbe ni idunnu ninu aye yi. sugbon ti alakowe na ba pasára , gbogbo igbadun re tin tan. tani alakowe yen to pasára? wansi si so gbogbo isokuso yi. awon alakowe lati ilu geesi nikan ko, osi ni Dokita Radhakrishnan, alakowe ninu Orile-ede India opolo e na ti pasára.

awon eyan yi o mowipe Olori gbogo nkan wa. ale roju basefe lati ni idunnu sugbon kosi bi inu yi sefe dun teba si ni ara eda yi. Oto oro towa niyen. Janma-mṛtyu-jarā-vyādhi-duḥkha-doṣānudarśanam (BG 13.9). nitorina awon eyan to logbon... Krsna ti fun gbogbo wa logbon. " Ode yi inu ara eda lowa. Awujo toni kosi ni iwulo".