YO/Prabhupada 0533 - Radharani is Hari-priya, Very Dear to Krishna
Radhastami, Srimati Radharani's Appearance Day -- London, August 29, 1971
hari-priya ni Radharani je, Krsna si feran re gan. taba summon Krsna lati Radharani, asi rorun gan fun wa. ti Radharani basowipe " Elesin yi da gan", lesekese ni Krsna ma gba, lai wo boya ode loje. Nitoripe Radharani lo ransi Krsna, Krsna gbudo gba enina. Nitorina ni ilu Vrndavana, gbogbo awon elesin man korin oruko Radharani ju ti Krsna lo Ibikibi teba lo ema riwipe awon elesin korin " Jaya Radhe". Teba si losi Vrindavan ema riwipe awon eyan man yin Radharani logo. Wani ifarasi lati sadura fun Radharani. Nitoripe, tin bale seki inu Radharani du, binba tie je elese togaju lesekese loma rorun funmi lati ni oe Krsna. Bibeko,
- manuṣyāṇāṁ sahasreṣu
- kaścid yatati siddhaye
- yatatām api siddhānāṁ
- kaścid vetti māṁ tattvataḥ
- (BG 7.3)
teba fe monipa Krsna pelu ogbon lasan, aimoye aye temalo ketomo. sugbon teba gbiyanju lati le sise fun Radharani, ele ri Krsna mu. Nitoripe Radharani ma funiyn ni Krsna. Nitorina elesin to gaju loje, aami awon maha-bhagavata. O le fun Krsna gan lati ni oye nipa amuye Radharani Krsna gan sowipe vedāhaṁ samatītāni (BG 7.26) " mo monipa gbogo nkan", sugbon osi le fun alti monipa Radharani. Radharani lagbara gan. osi sowipe .. Krsna mo nipa gbogb nkan. Nitorina lati le monipa Radharani, Krsna si gba aye Radharani. Krsna si femo nipa agbara Radharani. Osi ronu pe " Odindin nimi". Mosi pe sinu ara mi, sugbn mosifemo nipa Radharani. Kilode? Iwa yi loje ki Krsna bere sini gba awon amuye Radharani, lati lemo nipa ara re, Krsna. Sayensi to ga gan leleyi. Awon eyan to ni ilosiwaju gan ninu imoye Krsna tosi monipa sastra, awon lole ye. sugbon awa na le soro nipa sastra. Nigbati Krsna femo nipa ara re, Osi gba amuye Srimati Radharani. Caitanya Mahaprabhu ni onitoun. Rādhā-bhāva-dyuti-suvalitam. Krsna ni Caitanya Mahaprabhu je, sugbon oti gba amuye Radharani. Nitoripe gbogbo igba ni Radharani fewa pelu Krsna. gege na ninu ipo Radharani, gbogbo igba ni Oluwa Caitanya na fewa pelu Krsna. Akeko Caitanya leleyi, awon akeko nipa iyasoto, konse ti ipade. ilana ise ifarafun Oluwa ti Caitanya Mahaprabhu kowa fun ara re, pelu awon alabasepo re, ni basele ni imolara pe Krsna osi pelu wa. Ipo Radharani niyen, gbogbo igba lon ronu bosele wa pelu Krsna Awon Gosvami na ton wa ni ilu Vrndavan, kosigba ton sowipe " moti ri Krsna". eyan to dajuwan lo kosi, sugbon kosijo kankan ton sowipe moti ri Krsna." adura ton gba nigbogbo igba niwipe: he rādhe vraja-devike ca lalite he nanda-suno kutaḥ. He rādhe, Rādhārāṇī, he rādhe vraja-devike ca... Radharani ko le danikan wa. Gbogbo igba lowa pelu awon ore re. vraja-devī, Lalitā tabi Viśākha ati awon obirin imi ni ilu Vṛndāvana awon Gosvami sin gbadura nigbaton gbe ni ilu Vrndavan, he rādhe vraja-devike ca lalite he nanda-suno kutaḥ. Ibo lowa Radharani? Nibo niawon alabasepo re wa? Nibo lowa wa Nanda-sunp, Omo-okurin Nanda Mahārāja, Kṛṣṇa? nibo ni gbogbo yin wa? wansi wa gbogbo wan kaakiri. Kosi gba tonsowipe " moti ri Krsna ton ba awon gopi jo. Ni ale ana mosi ri" (Erin) sahajiya nigbogbo eleyi. Awon elesin tioti ni idagbasoke. sahajiya ni awon eyan bayi. Wan rope gbogbo nkan si rorun - Krsna ati Radharani si rorun lati ri ni gbogbo ale. Rara Nkan ti awon Gosvami kowa koniyen. Gbogbo igba lon wa wan He rādhe vraja-devike ca lalite he nanda-suno kutaḥ, śrī-govardhana-pādapa-tale kālindī-vanye kutaḥ: " sewa labe oke Govardhana, tabi leti odo Yamuna? Kālindī-vanye kutaḥ. Ghoṣantāv iti sarvato vraja-pure khedair mahā-vihvalau. ati sukun nigbogbo gba niise wan, wansi kigbe " Nibo lewa? Radharani nibo lowa? Lalita nibo lowa? Visakha ati awon alabasepo Radharani nibo lewa? Krsna nibo lowa? Sowa legbe oke Govardhana tabi leti odo Yamuna? Ghoṣantāv iti sarvato vraja-pure. ninu gbogbo ilu Vrndavan lon sukun ton wa wan, khedair mahā-vihvalau, bi were. Khedair mahā-vihvalau. Vande rūpa-sanātanau raghu-yugau śrī-jīva-gopālakau.